• No se han encontrado resultados

Irohin Imọlẹ

N/A
N/A
Protected

Academic year: 2023

Share "Irohin Imọlẹ"

Copied!
8
0
0

Texto completo

(1)

Baby West Afri­

can Signwritcr Companny for your sign wri­

ting and Robber Stamp making — 4, Isalp agbpdp St, Lagos Nigeria [opposite Isaipgan gao Square.)

W a n t e d

TO BOY VACANT LAND ANYWHERE IN LAGOS 200 X 200 Call Personally:-

CROWNSON 16, Bamgbope- Street.

Lagos.

VOL. V No. 318 MONDAY FEBRUARY 26 — MARCH 4 1962 K.QBQ MEJI (2d)

IJOBA DA JO AWON KAN.

SILO TIKO SAN OWO ORl

M il e Ibiobio ni agbegbe O pobo

* * ni ijoba tl ko ogunlogo awon Igblmo I b i I e ti ko san ow o ori won, A j e I e agbegbe na, Ogbeni Ekanem, nigbatl ori wipe enia pu- po ni ko san ow o ori lodun ni lo si Ipade awon Igbimo.

A tun ilu pe, a ni awpn Apoju Ijpba ilu. Ni- gbati o bero bi nwpn ba ti san o w o ori wpn, pnu ya a wipe pupp n i n u wpn ko ti san owo ori wpu rara. Loju kan na o pc ftp pplu wpn o si fa wpn le Ijpba lpwp.

Ijpba da pjp p w p n opu kpkan fun wpn, ti nwpn ko ba lc san o w o bi pgbpn §ile si apo Ijpba, lehin ti nwpn ba saD owo ori tan.

Qgbpni Ekanem, Ajplp agbegbe na ni o ya on Ipnu pc awpn Opelu ni lati ma sa lati san owo ori ni iwpn igbati o je wipe awpn ni nwpn nbu fun plomiran. O ni on mura tan lati fi opin si iru a?a jatijati bp.

Faranse fe mo bi araiye ba le gbe ilu Orun

Pari*:-- A ti gbo irobin bi awon Rosia ti te ran aja ati pbp Ip si Qrun ti wpn si pnda bp, bp na ni a gbp pe awpn ar<i i I p Amprika ran odidi enia lp si Qrun ti nwpn si pada bo ba kan na.

§ugbpn a ti ri ka niou iv gbp finrin, bpni eti koiti gb coke Ip si Qrun ri laye tab lp wa silc aiye ri. Kyi ni ol awpn Faranse lati fp po ads ekutc ransp si ilu kan ninu bi ibp yio ba pe gbo A w ckute nwpn ransc Ip si Q r March 1962.

JE OKIGWEs- ko kp i$p, ti ko ppp kuro ni prun gbogbo ipan prun ni arun na tpri gba a Onipegun na ba y i n bamu-bamu.

TAIAWA SO WlPfc-

PELU AMUMORA. ATI SURU OHUN GBOGBO YIO SE SE

Ni pse ti o kpja ni Gbpgan Trenchard ni ilo pkp giga University ti Ibadan ni Alhaji Tafawa Balewa, Olori Ijpba Naijiria ti ba awpn pmp ile pkp sprp atata. Ninu prp rp, o sp nipa lala ti awpn ti pe ki Naijiria to di Ominira o ni ipp nla ti o wa niwaju gbogbo wa nisiyi ni bi a o pe lo Ominira na fun ogo ilp .va ali itura awpn enia wa.

Oni §ugbpn o da on loju p e b ia b a le ma pe sura nigbati prp ba diju, ti a si noi amumpra, ohun gbogbo yio pe pc.

O Di ki awpn akpkp na spra ki awpn Opelu ti ko bikita fun irp- pp ma, tp wpn si pna ti ko yp.

TAFAWA BALEWA LO $E ALAGA NIBI IPADE AWQN OLOTU IP1NLE MET 1ST A NAIJIRIA NI ILU IBADAN.

Gbogbo awpn Olori Opelu ti o mbp ni ilp Naijiria. awpn bi Olo- ye S. L. Akintpla, Dokila M. 1. Qpara, Sardauna Sokoto ali Tafa­

wa Balewa pplu awpn ispngbo wpn ninu awpn Alapp pe ipade nla kan nigboro ilu Ibadan, Alhaji Tafawa ni o pe Alaga Igbimp, Alai- yeluwa Comma Ipinlp lwp Orun lo si ipade na. Tafawa Balewa lo duro ti nsprp ninu aworan oke yi, Gonuna Ibadan si a vy o li pnu, Akintpla lojoko lpgbp Balewa.

(2)

O R O O L O T U

M0W6AV FEBRUARY 26 1962

E fi A p e r e rere Jele

N

I OJU K I N I IWE WA NI IROHIN AVVQN OSELU TI KO DA OWO ORI WA. O YE Kl EYI J f ITIJU NLA- NLA FUN GBOGBO WA.

Hi awpn li a gbe ilu si Ipwp ba j? arufin bawo ni nwpn yio $e lo fan iiu ni Ofin ti o tp? Bawo ni nwpn yio se le tun ilu se?

Ni iwpn igbati awpn Osdu ti o nbu owo ori to ba san tiwpn, b a w o ni 9 $e ro pe mvkunu ti o mp p e e ko san yio $c san.

Qrp yl ki §0 ti ilu ibiobio nikan. Ibi gbo- gbo lo wa. Rupp ninu awpn O&elu wa ni ki isan iye owo ti o y? ki nwpn ma san. Rupp ni kl isp iye owo li o nwple, b?oi pnyin ni e o$ofin, beni ko si obun ti a le $c lalsi owo ori.

E fi ap?rp nsre lelp, ? jeki a ri nyin, E yp iti oju ara nyin ki 9 ba le yp ti mpkunu.

IftdHtS iMOLK O-M; SVVfe KEJl fi!

Nwon dite lati da oko Omoba Mragaret

Olopa mu Ke hinde wa lati Ilu Oyinbo

duio lenu ise

Inunibini ko kan-km olaimp iwa wu, $iwa ju ki Antony to fp iyaw<> re, Omoba Mar­

garet, i'pto lo nya kakiri fun iwc irohin kan tra npe ni Sunday Times. I?e yi na lo n$c ki 0 to ba Murgaret pmpba ile Gesi sprp if? pa pq, ti nwon si ba ara wpn gbeyawo A r e de.

Gpgebi a$a Gpsi pnikeni ti o ba fe ompba Oba (jpsi ni lati da Oluwa 19 ni phi, ko da bioluwa re jp ukujp, Oba yio sp di pni nla form ilu. Eyi ni idi 19 ti nwpn 50 fun Antony pkp Qmpba Margaret ni oye L o r d Snow­

don nwpn si fun ni 1.59 lati m i pajc jori alin Nlania kan. Inunibini ko kan aimp iwa hu rara. Eyi ni Okunrin Olowo arakuyanu ara ilp Kanada kan ri tobp tip li nleri bayi pe On ni lati ri wipe on da pkuorio ti nwpn npo ni Lord Snowdon ypn duro Ipnu i$olnisi ibere kan wipe kilojo. Kosi eniti o le ypmi lpwp rp wo, jugbpn bi o ba jp pe dida duro ti mo da pkunrin na duro lo ko wabala ati inira ba Idile Qba, ngo mu pwp kuro ninu ohun ti mo fp 50 na, nitoripc nko fe inira kan Idile Oba Gpsi.

Ni 9* ti o kpja ni Kpbinde Collins ti p I9 si lo Oba ni c$i fun pkp dc pelu Q:ppa oyinbo kan Iphm rp Nigbnti a- rabirin yi de iiu Qba awpa Olppa yp rru ro wo, nwou si ba Igbo ti nwpn ma man bi siga ara binrin yi ni 0 ni obiario kan ti oiukp rp ojp Angelina Juhnson oijp'fi ran on si Omp 19 oi Ilu pbu Nwpn mu de ilrEjpEugbpr, wpn da siip,

Lphin. eyi ni Ijpba Naijeria mu eniti o ft Igbo ran kpbinde ply pa Oyii bo si mu u wa m- siyi lati jpri pe nitotp ni Joimson fi Igbo ran- 59 si 11a Oba,

Ijpba ko gba ki K?- h!nde ba awpn enia rp gbe titi yio fi se plpri ti 0 fj ijp ki o to' pada bi Ilu pb» lati Ip kp 9kprp

tSSf^XS&MMSMMS5(SS(!S(S(SS(MS(Sl^

Aworan Asikiwe ni ile - iwe giga ti M eth­

odist Boys High School nilu Eko

Ni agogo mpkanla abp ni owurp pjp Tues­

day ti o kpia ni n w p n $e 979 fisi aworan Oipla Asikiwe, Gomina agba lun ilp Naijiria si. He-iwe g i g a ti Methodist Boys High School ni Eko, ninu ile pkp yi ni Qlpla Asi­

kiwe ti ka iwe, pniti o s if i aworan na $c pyp lun ile iwc na ni Qgbpni Adeniyi Coker pkau uimi oinp ile iw eyina ni Ogbpni Coker n$e.

Oipla H. O. Davies li o sprp nibi pyp na.

Oloyc Davies papa ip pkan ninu awpn ti wpn ti jijp nkawc ni ile two yi pglu Gomina agba.

Oloyc Davies ni aworan na y i o j? igberaga lun awpn agba li nwpn ti fi ile iwe na site, yto si ;p iwuri fun awpD pmpde ti o wa ni- bp nistsiyi wipe, enia Dudu ti o kpkp joye Gomina Agba nile yi, ninu ile pkp wa yi ni Methodist Boys High School lo gbe ka iwc rp jade.

OKUNRIN ONBJBITl KAN SE WaY0 ‘ O Si VVEVVQN ODUN MLJI IBADAN:- Okunrin kan ti n w p b npe ni Alhaji Muliamadu ko n?e wipe, o de Mpka ri, ornkp r? ri Alhaji, i?p

^ y o ati jibiti lo nse pkunrin mirnn ti o njo Salu Yaro til alarn- na fun Alhaji Mul'ama- du yi, o wa Ip rbliin iru 159 ti Alhaji na 115a fun pkunrin lbo kan ti wpn npe ni Jo b fgbo;opnu, wipe, Alajupajda ni ‘ Al- liaji na bi euia fun ni Cgbftun ponun, yio sp dt p g b a a pt nun fuu oiuwa 19. A1.. J o b bu mp aijp lo ba lo tu owo ti o wa ninu ile. jp, o ri ppnun m?rila di ni adp- rin ko jp; 0 si selcri fun Job pe on yio jp owo na /,2»6 di ^2900.

Odabi empe n*u ni Qkunrin Sclu Y: ro ati Alhuji yi wa fi obo bo

o dloju, ko p? (i Job ko own fun ooijibiti yi tan, Iowa dabi pnipc ukanna ka kuro loju Job sp pc nigbati okon na ko kuro loju on ti on si lo berc owo on pads, ija ci Alhaii gbe ko on ti o si yp pbclati pa on, Ailajp ri pc pjp Alnajr ti jpbi, 0 si puHj pe ki o da owo to gba pads ki 0 si Ip si liwpu Qdun meji.

(3)

MONDAY FEBRUARY 2b 1V/.' lRoHtN IMQLg OJU EWE BETA (M

*EGBE IMOLE AIYE*

Enia lo nleni debi Ola Eni

LATI QWQ:— FATA! A. OYEROGBA NO. 18, OMQ EGBE 1MQLE AIYE

0 pe ni ilu kan, Qba kan wa, o ni Ola pupp, o pi Iyi pplu, o si bi pmp binria ti o dara kan ti o j? pc ninu gbogbo ilu vi, ko si pniti o dara lo pm? Qba yi. Nigbati o to akoko lati lo si ilo Okp, awpn Jjove ti o wa ni ilu wa lati wa tprp pmpdeyi, bi Ijoye ti nwa, bpni Qlpla nwa lati fp pmpdeyi, $ugbpn p m p yi kp ja Ip pc on ko fp pni kankan. Agbe kan wa jade lati Ip tprp pmp yi, pmpde binrin yi gba lati fe Agbp aroko yi- Sugbpo Qba binu gidigidi pc, laduru gbogbo awpn Olowo, Qlpla ti nwpn nwa yi, Baba Aroko io wa fefe?

Qmpde yi kp jalp, o ni on ni on yio fp, Qb? pinnu pe ki o ku- ro ni ilu fun on. Baba Alugbaro yi ni, nitori pe on mafe lyawo ki on wa fi is? tabi ilu ti on ti njp, ti on ti nnui sile, k'i on ku- ku ma f? pmp yi mp. Qmp binrin na gba pe ibiti cma ma de ni aiye, koni sayi debp.

Ni owurp pjp keji, wpn bprp irin ajo wpn, w p n riu titi, Baba Alagbaro yi daku si oju pna, Qmpba yi joko li Okp rp, o bprp si spkun, Qdp kan wa ni to si ibe, o ngbp ekun enia, o wa jade sita

t

;baugba, o ri niti o nkigbe, o bi lere pe kini o de si iwp arabiurtn yi?

o ba ko prp o ro fun, Q d p yi ba dahun pe, on yio ji Qkp r?

Alagbaro yi, Qdp yi mu ilcri re sc, o ji Alagbaro yi, nigbati o ripe o ti nsprp, o wa sp fun Jyawo Alagbaro yi pe, mo fun yin ni pmp mi obinrin yi lati li $e ikeji rp lati tpju Okp yin. Ode yi tun .spfun Alagbaro yi pe, ilu ti o nip yi, nwpn ki wpbp ni owurp ayafi asalp ti o ba d? I? Ip, oru pganjp ni ki p ti mura lati Ip, ti ilo ba mp ba yin nibp, wpn yio pa Qkp yin, £ o di lyawo Qba, wpn mura si irin ajo wpn, wpn nip, wpn de ilu na ni ulf, ile Qba ilu na ni wpn de si, wpn ?e wpn ni alejo, ninu awpn pmp Qba ti o ngbo onj? fun wpn nsp wpn.

Aja W asuku lo be ilu Oyinbo wo

Nigbati Qgbpni Aja Nwasuku_ lp so a,b?wo ilu aege bi awpn pmp ile £kp ti nsisg wpn si uinu if npo ni EUlian Green mlu Oyiubo, o si ba awou pmp ti orukp wpn njp Amelia Gilliet ati Gillian Parson pm tala ti nkp bi a ti se nya aworau.

wo

N igbati'a'siko'ati'sun'to. wpn.t e n i fun wpn, pmp Q b a binrin yi wa’ Ip j ba Baba Alagbaro yi, o ni o wu mi ki nfi p se Qkp, ati pe nwpn yio bere ibere. mpta Ipwp re, ti iwp ba yoge, wpn yio li p je Qba dipo Ba­

ba mi, ti i w p ko ba mp, nwpn yio pa p.

Wpn yio bere pe k i n i ohun li o wa ni ile pwp ptun, pwp osi ati i l e pkankan? Bio ba ti mp, o yege ni ypn.

O bere Ipwp pmp na bayi pe, bawo nr emi yio ti ?e mp ki ile p!a to mp, pmobihrin yi wi fun pe, ile ptun ypn, pru Qba Iowa nibp, lie osi ypn, £ru awpn Ijoye ni lie arin yen ko si ikan kan nibp, pd? yi dupe pupp Ipwp re o ba pe adehun pe on yio fp p. 1 1 p pjp keji mp, wpn pe a I e j o yi wa si Afin ggge bi ohun ti wpn m a n$e ati ibere (i wpnma nbere Ipwp alejo ti o ba wp ilu. A won Ijoye ti peju, Olowo, ati Qlprp ilu pejp saiin Qba.

KO ITI PARI

Kini ohun ti o mo nipa awon JUase ile Naijiria?

(1) Ilu wo ni a ti bi plpla Amadu Bello Sa- dauna of Shokoto?

(2) Qdun wo ni a bi plpla Jaja Nwaneliuku.

(3) Ninu pdun wo ni a yan gegeb; alasp eto pkp fun Ijpba apapp ilp Naijeria

(4) Qdun wo ni wpn da pgbp Olomi North­

ern People Congress silg.

(5) Tani o da pgbp na silp, (6) Tani oludasile pgbp pmp Odudmva, (7) Tani a bi ni pdun 1912 ninu awpn oselu Naijeria

(8) Qdun wo ni a bi pba Ademji Adelc (9) lie £kp giga wo ni Qba A dele lp, (10) Qdun wo ni wpn pi igu tdueguran titun ti ijpba apapp kp fun Qba cko.

WO IDAHUN AWQN IBERE VVQN YI NI OJU EWE KEJE

Y oruba Challenge

March - April 1962

TI JADE FUN T1TA.

O kun fun pkp Ajinde. itan ati irohin.

Awpn aworart inu r? fanimpra.

Oju Iwc rp pe 24. Tete tans? lirg.

4d pere fun lwe kan.

(4)

Monday Febru a ry 26 1^2 m o m s TMpto O.TU EWE KERIN (-ij

O ya ti NCNC yio kuro ninu Ijoba

Lati Qwp:— Afplabi Qlabimtan

Lakoko ti tiwon ba wo enikan san um. »wc-n Oofeegwr> W .*1. Ala- koso won, yio fl as? fun «qu pc. aru wpn il da. ki won nu< >? S|R "on, Sugbon'M'un ni a gbp wipe awpn li won da slip otnu a«on A iw w o n y t pp tobe go, tofi j« wipe enia dip lo tun ku m i b u d o Adpt? m Ab,.kal ki.

Awon Oyinbo Qnisowo U.

A . C. fi m o t o alarun tore fun I j o b a Sabarumo U. A. C.:— Trohin ta si wa leti pe awon Oyinbo Oni$owo U. A. C. fi mpto ti o ngbc awpn ti o ba fi a r a gbpgb? alaisan, tabi awpn A l a r u n (Ambulance) lo s i t e iwosan ta Ijoba Sabarumo ( M a l i ) I p r ? , Oyinbo U. A. C. to gbc mpto na Ip fun wpn ni Qgb?ui Wallaston, o si fi le awpn ijimi enia nwpnyi Ipwp: Jean Marie Kone, Minister, Alasane Iiaidara, So- niine Dolo, Mousa Keinta.

PALM LINE:— Qga pkp W. G. D.

Keill ti o ti nsis? Qgakp lab? awpn Ovinbo Qlpkp Palm Line f u n pdun merindilpgbpn ni a gbp pe, o ti fi 150 silp, on lo $i*e ninu pkp M. V. Lo- bito Palm gb?hin.

Awpn pmpde nwpnyi ni a gbp wipe awpn Oyinbo U. A. C. f u n ni pbun pkp plpfe orukp w p n ni wpovi:—

Emmanuel prap pdun metala y i"o Ip kpwe ni M. B. H. S- E k o, Fasasi j?

pmp Agbowoka kan ni Oshogbo, yio Ip kp ekp r? ni Grammar S c h o o l Abpokuta. Jubrila pmp pdun merinla yio lp kp p k p Ur? ni Ibo U n i o n Grammar School ni Kano, Raphael pmp pdun mprinla yio lo kp pkp tir?

ni National Grammar School Enugu, Felix pmp p d u n mprinla yio lp kp pkp tire ni St. Patrick College Asaba.

A w on adete ko lati padasi arin awon Ebi won

Awpn marun ti nwpn we geie ninu avyoran yi ni) awpn Obinrin ilc Naijiria ti awpn Qlpkp ofurufu gba lati raa se Anti Palp fun awpn ero ti 0 mba pkp ofurufu lp si ilu Oyinbo, ilu Mpka, Amprika tabi awpn ilu miran lpna Okc okun. Orukp wpn niwonyi:—

Awpn ti nwpn duro ni Victoria Doyle Ipwp osi, Rita Lester, pmo ilc Gpsi ni sugbpn Jiko lo ngbe nisisiyi, on lo wa larin meji wpn, Christie Qkoro pmp ilu Oweri.

Awpn to joko lati pwp osi, $myclu Agu pmp ilu Obosi, Rose -Mary pmp ilu Eke ni Enugu pnikpta wpn ni Dorothy Agina pmp ilu Onitsha.

Gbogbo wpn si mb? lpnu ikp$? Ipwp.

Awon Asoju ninu Ipade gbogbo Agbaiye

Enu nut n y a mi pe, Qlpla Opara, Olori pgb? Alakukp kp nmp iwpn ara re. Bi 0 ba mp iwpn ara 19 ni a rap pe ui il? Naijiria lode oni, Hausa n|

alagbara, ohun ti n)w pjn )ba si f? ni egb? r? ni lati fp.

Nigbati Opara gbp pe AG f? da- rapp se Ijpba, o ni on ko ni ni pwp si 1, bi ? n i p e o ni agbara lati take iru cro bayi, O gbagbe wipe on papa ati pgb? on, Ipwp anu Alhaji Tafawa lawpn wa, ti o ba si ti tp Alhaji Iprun bi Opara f? bi ko f? ?i?e »L

Boya Opara ko mp pe nisisiyi NPC ti ni pmp pgbp to ni lie ijofin nla la- ti.?e fjpba l a i pe ?gb? on- Bi o ba gbpn, ki o ya pa ?nu r? mp ki o ma

$e s? Alhaji Tafawa Balcwa ki o ma ba le wpn jade.

Awon Anti-Palor ti o nsise ninu Oko Ofurufu

ABAKALIKI:- A gbp irohin wipe, awpn Ad?t? pp gidigidi ni ilu Abak?- liki, Ijpba si kp ilu kan fun w p n ni biti awpn enia na yio ma gbe ti arun et? ko fi ni ran mp pnikeji, nwpn npc agp awpn a d ? t ? na ni Segregation Leper Camp.

" • ’ ltlM;

Awpn U a nwo ninu aworati.yi ni awpn A*oiu ninu i p a d e aboisbo Agbaiye eyi m aworan ti wpn ya nigbati wpn nse ipade na Ipwo ni ilu Lpndpnu, wpn duro wpn si fi pro jornitoro larin ara wpn. orukp wpn 51 atl, c,wt? °cs,'' R. A. Njoku, A l a s ? eto oko fun ilc Nayina Qlpla L. H, Sbatrtz, «m psyp Earl De Uw arf, ati ‘Ogbeni L.

H. E. Bury, Olon A?oju il? Australia.

(5)

MONDAY FEBRUARY 26 1985

Aseju ni Baba ese, Kse si ni Baba Adanu

Lati Qwg:- WOL1 KOGBEREGBE

ha tan bi, ko mg pc agcju lo npauia, A^cju to fi'fc gbo' IR O R tR LMQLR QJU EWB

Iblnu ko y? grog enia, oitoripe ninu ibinti ni egg ti njadc wa, Ibinu abiju gag lo omu wa ninu ibinu ni ipin- ya ti nwa. E jgwg giyka §ora fun ibiDU, ibinu ttjeju lo- opania, Epikgni to'ba it, finale Ododo tabi 1 g b a g b 9 Ododo ki.jbinu bcni^ki sijse aseju.

Nitorina mo fc'.ki 9 mg wi­

pe enikeni to ba nja B a b a tabi Iya rc li ole ti o st wipe ki ko gsg on na ni cgbg apa- Birun, ICniti o tje agberaga li aiya, a ru ija soke sogbgn

?niti o gbgke re le O l u w a li a 0 mu sinra eniti <1 glyke- Ic aya are rg asiwere m.

Sugbgn emkeni ti o ba nfi ggbgi rin on li ao gbala OWE 28 ESIi 24, E jg ka sgra ni m> iwa agtyu. Bi iwg ba jare grg r? aseju yie si mu 9 jgbi grg na, oju yio si ti 9 nitori aseju re.

Enikeni ii,o ba pa Ofi mg on-najm yio ri.lye ainiptkun lati gdg, Olgrun, gugbou eni- kgni ti o ba ru Ofan yio jg gbese, ki yio si ri ran lailai, WOL1 KOGBEREGBE nitonna yjg ku sa fun 99?.

E jfka fi 999 silg, Oluwa tirg ni Ododo, «ugbgn ti wa ni ltiju, DaNiELI 9,! f S f 7. Eugogu mo fg ki e mg wipe ere ajgju koyc gmg Olgruo, oitori org gigcan enia ti pg si Orilg-Ede E jgwg aseju ko dara, bi enia ngc aseju yio pofo Ha! awgo gmg araiye yio si ma wi loju rppe jgwg rnusuru ma?e binu si aya r? tabi gmg r?. _

•Sugbgn bo ba di ghio rg tan, nwgn 0 si ma wipe, ko

Iyawo rg lo na ni ygo o, Ero ibi ai ni ero wgn, 1J mage jg ki gnikan k: o ro ibi ni gkin rg si gnikeji rg gma- gc bura eke oitori wipe cbogbo iwgnyi ni mo ko rira ni Oluwa wi. SEKARIAH 8, £SE 17 Chun

Olola Njoku lo se abewo i\papa

a nwo ninu aworan yi ni igbati 01gla E- A.

Ig ge aygwo nwgn grg ci yio ma lg awgn iyg- 1 fi nge burgdi ti uwgn si kg lie grg na si cti ni Apapa. Ogbeni G. P. Coummantator ni yio ma ge alamojuto ile ig? ibili a gbe ti nig yjfon na.

rere kan ki dun nitori ti o ti fi ageju bg inu re Aseju lonsg ohun didun di kikan, nitorina g masc fi’ohun Mi mg fun aya 9 ma si gc sg perli yio siwaju gljdg nwgn asi yi pada gwg nwgn a si bu yin san MATTEU 7, £SE 6. Aseju ko dara rara, aseju pi awgn ole oge ti wgn fi ko si gwg Qlgpa, gugbon mo fg ki g mg pe obunkohun ti aseju ba ti do, yio baje ni, ko si ni, ni atun se mg. Aseju a raa ohun rere jina si enia, aseju ni Baba agctg.

Iyan Omi lo mu Omo ilewe kan ku si Odo Oya

AWKA:- A gbo irohin wipe, omi wgn ni agbcgbe ilg Onitsha tobg ti nwgn fi nta G a r a w a omi kan oi

$itc mcjl, awgn glomiran t ’ ko Ic fi ara d i lati san fjlle meji fun Garawa omi kan ran awgD Grog rg lg si okan bi busy meji lati lg pgn omi ninu odo igbo.

Ni akoko na ni Qrag ilewe ti nwgn npe ni Felix Okafor wa omi lg sinu odo Oya lati lg pgn omi wa si ile, gugbgn r.igbat: o de ghun, o b?rg lati pgn omi ni ?sg re ba yo iori Apata, o si ba omi lp.

Qmgde na je gmg Akgkg Ile gkg giga ti nwgn ope ni Totre Dame High School ni iln Abatete ni agbe- gbe Onitsha.

Are you also Suffer!]

Silently from:- PUFFY, SWOLLIH

m w p i

ikAMtmu

FOOT ACiOl

IIKED OUT WITH CONSTANT PAIN LIMBS LIKE P I E C E S OF LEAD BACK-ACHING SWOLLEN JOINTS SHARP SHOOTING PAINS LUMBAGO.

RHEUMA7SM - GOUT - ARTHRITIS Millions cf people are suffering under these terrible afflic­

tion which constanlv impair with the meeling of health [HE CAUSE?- EXCESS OF URIC ACID IN THE BLOOD. THE CURE?- UROXAL. The kidneys must be prompted to cleanse from the system the pain-giving luart affecting poisons and this 00 the evidence of thousands of Piie-tim*-sufferers restored to normal health condtions by the use of “UROXAL” the World reknow, nod remedy for all Kidney and Bladder affections.

P rice. S /6 d (MADE IN FRANCE)

2 i h l .

Stockists:

Waterloo Medicine 8, Palmchurch Street Lagoa, Phone: 22878 Nigeria, (Oja ita Faji)

ADEDUN CHEMIST

WAKEMAN STREET, YABA PH oN E: 22878 WATERLOO MEDICINE STORES 11A, FAGBEWESA STREET, OSHOGBO.

(6)

lYAflX A1ABE OWffife

Oko file m i ko gbogbo asc mi lo.

IBERE:- Mo j? pfcunrih li pjp °ri r; to Qduntnpkan- dibipgbpB, mo si yan ale obinrin kan pmp pduum?la- dWt«sb?n oibi kanna ni a tj gbe jijp nw?» ni'u wa* 8S1 ma ri ara wa iojojump, Ni igbBiwran ewe enw a ma sin l(i si iletaja lati Ip ra nkan nl ?pbu. Mo fp ran Obinrin y iju Igbesi aiye mi ati awgn Obi mi Ip, Nkan ti o wa sofo nl b? oi wipe mo tigbeyawo, on na si ti ni qkp, o so fun mi wipe on f? ran mi jo pkp on lp, gegobi o ti ni fi; mi to, o ma wa ba mi fp awpn aijp mi ti o ba doti o se ui pjp kan oigbati o wa bn mi fp§9, pko re wo si o p .o ri nibiii o gbe nfp »$p mi oin u, ni aiudoju- bpie o si ko googboa?? mi ti o mba mt fp lp si ile re.

Nisisiyi emi ko mp ohun ti emi ko ba ?e boyu ki uko aya tni silg ni tabi kini ki ai$e? tabi ki Ip ba pkpai?

mi na ja ija ola.

IliARO ADIS A KASUNMU

IDAHUNi- 0 titp lo nap nkan wpnyi, Sagbpn ki o ip ba tkp lo koji rp ja tabi ki o le aya ro lp, ko ye nkan tun p Ni pna akpkp o y? ki o ba ara re wi pupp oitori aya aiaya ti o Ip ba, ti o si fe ji ife onifp gbc.Tru nkan bu~

ruku bayi ni o ma gbeliin poiti o hu irufp iwa yi. Nkan ti o dara ju pe ki o pe ni pe ko gbtgbe gbogbo rp, ki o si wa iyawo tire Ip, eleyi yio si ypri si rcre fun pjupe ki o ma Ip ba aya plomirao Ip.

IBERE:-M o Of? pmpbinrin kan, pmp na si nf? mi, sjugbpn g?g?bi asa ilpwu mo mu pmp no lp han lya mi mo tun Ip fi ara mi han si i y a pmp no sugbpn iya ie taku wipe rara on ko ni fun mi ni pmp on,

Gbogbo owo ti mo ti na‘ fun pmp na Ijspkps? ni wpn ti da pada fun mi, ni pmp na na Baber? si spkun pe dandan emi ni on yio fp, emi oa *i taku pe on ni emi na yio f? ki a ma fa pro oa gun w p n da if? wa ru, Ki Qlpruo mase da if? wa ru. Qmp wa na fans? si mi wipe ki nfi pkan bal? emi sa ni on yio f? dandao, Awon Obi temi si ti. sppe ki wa yawo miran Ip lyafin Alakp cwo m ki use o, Qmp Taku pe on yio f? mi Awpn ile wpn kp I y a mi na ui ki nwa miran lp propde sppe aS pri afi pxuo, Ewo ni ki n?e o.

ORO TOWN S. ONIGEGEWURA,

I D A H U N M i si ibere pgbpni S. Onigegcwura niyi Awpn Yoruba mpai nipni lo npa owe bayi wipe, lya- wo buruku ko ?oro ni-fifo, ana buniku ni ko sunwpn lati ni. Nigbati pmpbinrin na taku wipe, a U ori a fi prun, ayafi bi on ba fe Onigegewura, ti on paapa si wipe, bj igi nlugi mp tgi pmpdebinrin na ni on yio f?

sugbpn Iya pmp na kp lati fi_pmp r? fun p, b?ni awpn Obi tir;p a a p a ko ipwp 'si pc ki o fe pm? ns.

Irnpran mi si p ni wipe, ki o fi piuo na silp ki o si wa orniran ip. Ki Olprun mase jpki ohun ti yio pu wa wu wa, Bi enia ba ti n?e ohun kan lo, ti gbogbo re D gun

MONDAY FEBRUARY 26 1962 IROHIS

Owo eni lafi tun iwa eni se

Bi ailowolpwo ba nda p lamu, biairpmpbi mba p Ipkan je, tabi airipppe lo nypp l?nu, tabi o til? n?i?e na owo i;o oa ko duro Ipwp r?, Tabi awpn Qmpraiye ko j?

ki o gbadun igbesi aiye r? ni gbogbo pna kona.

Qko rere tabi aya tcro lonjo'p niya. Tabi amubp pkp tabi ti ajra, tabi pja ti d nta ko lp dede, tabi ohun miran lo mba p Ipkan je ni gbogbo pip.

Mp daju wipe difdi? io kpkp bere. Ki osi tun pna r?

?c. Kpwe p?iu (Jile M?wa abp (10/6) pflu Siiampu oni tprg (3d Stamp) fun ohun to fa ati atunsc adanwo na Ipdp:-

P. O. BOX 166

AWORAWQ 16, MQLEYE STREET YABA - NIGEKA

IMQLg OJD feVVE KEFA 16)

regcrege, li o si tun wa ri ohun ikps? sakiyesi pc pkan na ko ni ?e on ianfani lo j?ki q fibf.

Fl obinrin na s i 1 ? ki o wa onnran Ip, nitoripe enia ko lc ri iku nil? ki o lp tp prun bp.

Emi ni:- lyafin Alake

Iya, Omo ati Baba ku lehin onje

Ni Oroga, Iieto kan ni Ondo ni ariwo ta ni ps? ti o kpja oigbati arakunrin kan Ajijpla Onipede, iyawo r?

Alice ati pmp wpn ku Iphin onjo ti nwpn j?.

Gtgpbi irohin ti a gbp, Olu ti Ajijpla mu bp oko ni nwpn se ni al?, cyi ni iiMpn si je tan ti Inu bpr?

si run gbogbo wpn. Awpo ero jlcto na gbiyaniu lari ran w p n ipwp pplu pro inn sugbpn ?pa ko ba oro mp.

Ki il? ojp fccji to mp gbogbo wpn ti ku.

Akiyesi Pataki

MASE SURE LQ YO “EHIN” ENU - R15 MQ NITORI 1RORA "AKOKOIiO" LAI DON EGBOGI

T1TUN TI NVQN Nl’E NI:—

LINIMENT

BA KE ABAMO O

Gbogbo awpn pniti AKOKORO nyp Ipnu mp bi oro tabi Irora r? ti pp to, pupp ninu awpn enia wpnyi a si ma lp yp awpn EHIN ti o fa Akokoro yi wa bawon kuro ki wpn ieri alalia. Nipa yiyp omiran niiiu awpn EHIN wpnyi, a ko ba Oju ati erekp elomiran a si papp wpn a si wa di arugbo cku, pelu.

O secoia ni anu lati ri wipe Pupp oinu awyn egbogi ti a nta kakiri lgboro fuo Akokoro ko ti ? Ie sc iwossu r? rara, do bi ti yio Ie pa kokoro buruku ti a nju EHIN ni idr, tabi erigi nitoripe wpn ko lagbara to rara lati le de ibiti kokoro yi gbe sapamp si.

Aworon ti oke lwe yi fi han p duju gbnngba bi EHIN r? ti ri de isalp atipe awpn egbogi lasan tabi olowo ppka ko ie «e iwosan r? daradara. Nitorina a gba p ni impran wipe ki o rpju mgbakugba ti Akokoro ba. nyp p ipou lati ra tabi ran?; Ip' ojulowe. giriki ati rttlogi r?

ti a as?s? wa idirc kpn li u ni>e ni TOOT H LINIMENT ki o dpn wo Iariu i??ju ruaroo pore iwp yio ri gbaogbn daju pe “Meji” re kosi fun akokoro m gbogbo iiu Na- ijiria iy?D dajti.

Ki o to Ipyp EHIN r?, masalai dpn Egbogi yi wo bi bo kp iwp yio kc ABAMO. r? daju. A si I? onyin onibara via gbogbo ni Arjwa ati Gusu lati ma roilin Egbogi yi fun awpn elomiran niwpn igbati ? ba ti lo wo ti p si ba bi ati robin r? pelu.

SILE MEJI PERE Postage-l/3d DQZJNI 20/- POSTAGE & PACKING 3/- A si tun ni awpn Egbogi fun oju didun tnti pns pfun li owo wpn roju fun tita pplu ni ori?lri?i.

Bere ni §vbu awpn:- Waterloo Medicine Stores 8, Palmehurch Street, P. O. Box 333 LAGOS NIGERIA W. G. A. Phone 22079.

Akiyesi:- $?ra ki awpn ylomiran ma fi oru ta adampdi fun p o.

(7)

Nmu ipade kan tl awpn asiwaju awQn otjclu ipinlc Iwq O run, Ila Orun, Ariwa ati ijpba Alapappjo $e nigboro ilu Ibadan lati jump oi ajumpsp nipa gogebi nwpo o ti

$c raa oa owo. Eniti o $e Alaga Igbimp na ni Q'pla Alhaji Tal'awa Abubakar Balewa. E rin o si s i pade na ni Qlpla Adesoji Adciemi. Eniti a nwo ninn aworan yi Ipwp ptnn ni Dr. M, I. Okpara, nitori oojppkan ninu Igbimp na.

M Q N b A V F EB R U A R Y 26 1962

wa si Ipade ti 3e ni Ibadan

IROUlfo iMQfc% OjU EWH KeJe (1)

O m o Am erika kan lo Sorun o bo Joht,' U °K--9ja f t I i ? b a Amprika ran John Clenn lp si Qrun. Nmu inn ajo r? ni ofurufu o yi tVynB n V n ' J ^ A ° dC. Ken° "i i3?ju kokanlelogun Ichin waN^ \ , Jt nb9GilIT “ ki . aji,"Dl‘aW0 nilOTi «

EYI N I 1DAHUN AWQN IBERE TI O WA NI OJU EWE KETa

(1) Nilu Rabah, Ilu kckere kan ni Ipinle Sokoto.

(2) Lpdun 1018, (3) 1959, (4) Ninu 0?u- Septembcr 1957, (5) Qlpla Amadu Bello, Sadauna of Sokoto, (6) Gloye Qbafpmi Awolpwp, (7) Oloye- Festus Okctie Kboh. (8) November 13, 1893, (0) lie gkp giga C M S Gramar School (19) Oei 1st I960

EGBGGI

‘CHLORODONT’

tabi “F H iUM'fc§x?Tgr' t amani li ° do fun pou e v i ' n i J 1 N ’ N -U d 0 h j t a b > f a n n U A - VrrPf PM U R Q EH1N. Kokoro ugbp tabi jp id, Erie, Ebin na, a si tna j? ki pno

Pa kokoro buburu >•' r,,D Pata- DROPS* ^ eEb°S‘ “ W9” Dpe 'CH |i-ORODONl

Igo ala:- Silemejc-abp perc 7/6 Igo kckere:- Silemerin pere 4/

OWO QKG Silekan-abp (Postage I/6d)

MOGBAYI BABY MIXTURE

OLURANLQWO FUN *\VQN ABIYAMO

BERE FUN

KGBOGI EKUTl!:

M O G B A Y I BABY M IX T U R E j c o^un p a ta- id ti a sc ni asc pc fun awpn Q mydc a ti nlo ogun yi fun Opotyp? pdUii s^liin p$!u iduniloju fun A w on uf^ rib i rib i ti o ti n$e.

M O G B A Y I BABY M I X T U R E je egbogi to da rn fun igbona, ikp, o tu tu A i p c r i, Qtd Qm pde, jedij$di, kokoro ori Qmpde. O d a ra fun O roide ti ko tele rin a ti fun aw pn aistan m iran 1q. O ntnu om pde ko m a nsun fonipii O mu Id ehin h ih u j $ irp run-fun uw gn on»vd<: o sinjflri aw w i om ode to b i, osi n m u w $n d a n nia wc».

flnyin Abiyamp, c-ku afojuba cciw gi v i A ran yin letipe M O G B A Y I BABY M IX T U R E > rgbo fc i H ' ko bc mani fun qwqii om odc I j n l . i r a Icwu p u p o , tetc lo ra tire hi !c itaja F.gbogi o w a ni A dugbo r$.

u t okckere re j e 2/68 Igo n la j c 4/6d R E : - S ib i k e k c r e le m e ta lo ju m o Wholesale V ietrib u lo rf A. K. KARIMU ANJO LA & BROS 6 , Balogun S tre et, W ert, 34, D occino Streat

Eagos N igeria, Lagos

Phone 22515 PU one 24247

i Gjulowo Egoogi ti npa EKUTE bt mpnampoa lain!

ewu rara fun enia tabi run ohun pai.t miran oi ile.

Silemcji pcrc ni (2/-) Dpsini (£1) OWO QKQ:- Silekan-abp (Postage l/6d)

Bere Egbogi wpnyi ni ppbu awpn:- Waterloo Medicine Stores 8, Palmchurch Street Lagoa, Phone: 22878 Nigeria, (Oja ita Fajp AK1YESI:- Ri dam gbangba (ripe sobu ti wpn nta lo gbe raopp lpra, bi bevp awpo plomiran yio fi ERU lp ta adampdl tabi orlpi omiran funp o, maw gba f8ra.

(8)

MONDAY FEBRUARY 36 - MARCH 4 19o2 IRoHtW tM Q U O f t EWfc RE-IQ («)

FEDERATION OF NIGERIA THIRD DEVELOPMENT

LOAN

The Central Bank o f Nigeria has been autho­

rised by the Federal Minister o f Finance to raise funds within Nigeria by the issue of £7 million registered Stock in February/March, 1962. The Stocks to bo issued will be:*

1. £2,'million 5% Federation of Nigeria Third Development Stock 1966 - to be repaid in hill on 7th June, 1966.

2. £ 5 million 6% Federation of Nigeria Third Development Stock 1986 - to be^repaid in full on 7th June, 1986 Both Stocks will be issued in multiples o f £10 at par, and applications will be accepted at banks throughout Nigeria or at the C e n t r a 1 Bank during the period 26th February to „6th March 1962.

Prospectuses, which contain full information, and application forms may be obtained from : banks or at the Central Bank on or after 26th February, 1962.

W. A . TIBBLES.

General Manager.

CENTRAL BANK OF NIGERIA, FEBRUARY, 1962.

Ebi npa mi olose nkiri, nigba- ti we Inu ngo se we ode

KADUNA:- Niwpn agogo Mpkanla-abp owurp a gbp wipe pkunrin Hausa Alagbe kan wp inu koto nibiti Ali- kali gbe use idajp, awpn Qlppa gbidanwo loti da duro sugbpn Alagbe na ko gba rata, O kato, o sj ni sgbara awpn Olppa si mu ti.

Nigbati ritiriti rp nip da ijoko kotu ru, Adajc dide o so fnn awpn aw90 OIppa wipe ki nw<?n mu ekuoriD olo- jti kan na wa siwaju on o hiwifuo wipe, iwQ ni ngo fi se apt re fun awpn pni bi iru r? ti o ku, nigbati iwp nip wipe, ihinyi ko use pja ti a le fun p ni owo ninu ohun ti a nta, so fun mi kioi iwp wa pe mh:n yi?

Okunrio Alagbe na dahun wipe, eru re ati ofin rp lo ba mi ni mo mbp Ipdp r? lati 6 pro fduo mi han e ki awpn Qlopa to bprp si di mi Ipna. Qba ko sa sp pe ki enia mt.se witi enu r? Adajp se pe odara kioi prp ?dun r? na?

Alpgbs na dahuo pe, O di ijpta ti mo ti ri onjp je, Ians ni mba lp jalo sugben eru re band, nitorina ni mo pinu lati wa fi pro na han q ki o b» mi wa owo lati fi

ji.<un nisisiyi, ni adajp ba gbe nisi fuo o gba, o kpri si isp

Jolooj?.

DURO KO OGBO

Eniti o ba gbekple prp re yio jjubu tjugbpr. olododo yio ma gba bi ?ka Igi.

Knikyni ti o ba fe eke, o l'e imp eugbpn eniti o korira bawi pranio ni.

RICHALET

BERE OJULOWO EGBOGI AWON FaRANSE TI WON PE NT:~

FUN ARUN EJE ARA ENIA GBOGBO Elcyi yatp patapata si awpn Rpbi-rpbi Is? re lara enia si daju fun Iwosan gbogbo K o l t o i o buruku ti o ba wa ninu “ EJE ARA” bi Mpnpmpnp.

Meji re kosi oinu gbogbo awpn Egbogi ti wpn npe ni TONIKI Eje ti wpn si nta kakiri ni owo pppku, adirapwp tabi ki o lp nil?

ko di owo, lypn ?e ewp awa ki ta awpn egbogi bawpn yen rata tabi ti owpn opota ni ile yi.

Gpgpbi awpn Onibara wa ti mp irulp awpn egbogi bawpnyen a m i ba ojulowo egbogi atata ti a ran?? fun tita lati awpn ilu .Jamsi, F a r a u s e ati ti awon Tatanbulu si Iti.liJe. Mp daju pc bi E it ara ko na mp daradara awpn ampdi tabi ailera wonyi le

?ep Lakuregbe, orieiria: Ioarun Ojueipu tabi didun JpdiJpdi Afcp Iba arun edpki Aya didun lan- para ekuru laya.

Ara riro, Eapalapa Egbo ese Amodi Apo ile itp phin didun tabi Ibarjdi riro pplu egbogi Ri.

saleti a nia pa gbogbo Kokoro buruku ti o wa ninu E j e ara patapata yio si fp $jp re mp tonitoni pplu. Sa dan Igo rp kao wo lara re dajudaju iwo yio ma rohin ry fun 9 I o m i r a n pplu nigbakugba.

Berc Egbogi yi ni $Qbu awpn:—

Waterloo Medicine Stores 8, Palmchurch Street Lagos, Phone: 22878Nigeria, (Oja ita Faji)

ADEDUN CHEMIST

WA REMAN STRfcET, YABA PH oN E: 22878 WATERLOO MEDICINE STORES UA, FAGBEWESA STREET, OSHOGBO.

ATI NI AWQN 9QBU IBADAN:- ISE OLODUMARE DISPENSARY OKE-BOLA

AKIYESi FUN ENITI O FE RA TABI TA ILE TABI ILE NI IBI GBOGBO Eminent ti o ba fe ra tabi tita tabi lift ile ya, tabi lati haya ile to dara ti o si laye tabi ile i$p tabi ile c y i t i ko ppju adptu esp ni fifp ati pgprun eso ni gigun. nihin tabi lphun ati nibi gbogbo, bi Eko, Ebme metta, Apapa Yaba Suru Lore, New Lagos, ati ni Idi Oro, M u . n i o Isplp Raod ati Ikeja tabi nibikibi, Wa ri Ogbpni:-

j. B. Crowuson Cdujobi & Sons 1st fioor 16, BAMGBOSE STREET LAGOS

mmsssmm m m xm

Pruned mid Published by MODUPIJ PRINTING PRESS 16. 2Banigbose .Street lottos Phone 21985 Olotu E. A. Adeniji

4, Oliyide Street, Odu Abgry MUSH1N,

Referencias

Documento similar

A lign sprp isiri Ipppyppp o si gba awpn obi niyanju lalii rna wn si rrn ipade bp Ki wpn le ma mp awpn olukp pmp wpn ati lari me wadi ilpsiwaju owph pmp wpn, Awpn obi dupe Ipwp awpn