• No se han encontrado resultados

Irohin Imọlẹ

N/A
N/A
Protected

Academic year: 2023

Share "Irohin Imọlẹ"

Copied!
6
0
0

Texto completo

(1)

IROHIN

IMOLE

I MOLE ORE A / i E , TLN1 GBOGBO LAM A

NO 872 TUESDAY DECEMBER 15, 1964 (2D)

Awyn Serafu Ngbadura Fun Aiafia

E K J Ni dccdc agogo munin irply ana pjp A j c ti «§e 9 j o kyrinlu 0 s u yi ni gbogbo a won Serafu ijy aladura ti nw^n wa ni Eko ati agbegbe n?-parojv si gban- gba ode L’Eko ti gbogbo «Qn si gba akan$e adura patak/ fun aw9n a$iwaju o$elu wa gbogbo.

On/rohin wa Ejongboro ti o Ip sibi pylu /taw? ni awyn yio gbadura na fun isin adura no ni ir<?ly ana fi yc wa wip<? qjq meje laiko fi ynu kan omi tab! ata o W 9k9 mcji (40, 000) enia ti gbogt o ki gbogbo rogbodiyan ti o wa larin ilu

"On wu nir u a$o fun ywu funfun, fila wynyi ki o le sily.

fu/ifun, bata funiun ti gbogo wpn si Nvvyn si tun kcsl gbogbo awpn aladu- funfun balau. Qkan ninu awvn "W0/1” ra ti ko ti gbp p6 ki wpn ina$e & laiko ti o wa mb? ni alp ana $e alaye fun wa si 'pade adura na m gbangba pdnu Ejongboro wipe, pjp mcji ni awsn yio L ’eko. Ki OJuwa ki o gbp adura gbogbo fi/ §e adura pataki na. tun aLye pe wao.

D okita O kitara Sp l»« : .... . . ...

a k t n t o l a k o f e k i i l e

IGBOMINA GBA OMINIRA

OGOJ Gbogbo enia lo ya enu sily ti nwpn fpr? le nia pade nip nigbati I) o k i t a Mickeal Okpara Alakoso Ijpba Jpin ? l a Orun aijiria, ati olori pgb? Alakukp, nsp fun gbogbo awpn enia ti nwon wa gbp prQ r? pe, Oloye S. L. Akintpla, Alakoso Ijpba ipinlp Iwp Oruu ati olori egb? Dpuip ni ko fe ki awpn cnia^llorin ati Kabba Igbomina kuro ni abp Ipinlp Ariwa, ti o si nwa o ia bi nwon o ti §e ma §e pru awon enia lailai

Dokita M.

Olori Egb?

Dpkita Okpara tun sp s:- w:ju ninu prp re w;pe Adelmn ikpkp kan wa larin Oloye Akiotpl »ti Alhaji Ahmadu Bello, wipe ki Awpn e >ia Iiprin ati agbe- gbe Kabba ki nwon o ma le kur > lab? Ipmle Ariwa.

Dokita Okpara tun fi han gbogba enia wipe if?

inu awpn enia Iiprin ati agbegbe Kabba ni Iati wa derappm p awpn Yoruba pmQ Iya wpn ni Ipiulp Iwp Orun Naijiria.

B1 awpn enia Iiprin ti ise lie Igbomina ati ti agbegbe Kabba ti nle lpsanati loru to wipe awpn f? papp mp awpn omp Iya awpn Olaye AkinOla kpeti ikun si igbe aw pn enia na.

O tile tun sp gbangba p?

lu igboiya loju gbogbo awpn enia na pe, “Adehun ikokp to wa larin Sardauna il?

Sokoto ati Oloye Akintpla ko jpki Akintpla ofeki awpn enia na o p id i si pdp Yoru ba pmp iya wpn’’

Dokita Okpara tun fi kun prg re pe, “Gegebi iwa are- kere»e Oloye Akintpla o ti gba iati sika adehun na ni tori ileriasan ati ala ti ko le s? ti Ahm.da Bel o n$e fun uo"

O tun fi han awpn enia na p?!u idaniloju w i p e

“ Lasiko to je wipe, awpn enia awpn enuwa r? kuro iori aga akoso Ijpoa "i asiko ibo, aiafia, ati ifpkanbal?

ati Ipsiwaju ko ni le pada si ipinle Iwp Orun

!!\$ IR I IKQKQ!!

Nipari prp r? Dpkita Okpara wa kesi Oloye Akin

tpla, pe IIMajeki a gbp irp nine. Bi o ba je wipe, irp ni gbogbo orp ti mo nsp yi, Ki Oloye Akintpla yara sp, fun gbogbo ..iye gbp. Mo setan Iati tu asiri ikpkp na fun gbogbo enia!!

Ninu prp ti awpn enia ilu Bansarra ni agbegbe Ogoja

I. Okpara

Alakukp

sp, uwpn fi nye Dpkita Okpra w pe, gbpnin-gbpnin ni awpn duro lehin re ati Oloye Qbafemi Awolpvvp

Nwpn wa fi ye Dpkita Okpara ki o to ip kuro ni pdp wpn pe, ,.wpn ni ojulo- wo igbekele ninu Ijpba rp, rwpn s; rso rlctitp I D.ki-

ta Okpara ti ti ise Alakoso Ijpba laiko $e iyemeji.J ^ j

N w p n w a fun D< kita Okpara ni pkan bal?, pe ki o ma a woran. ki o si

?e akiyesi ohun ti yio sele ninu ibo ti mb? yi.

Dokita Okpara se afikun ninu prp r ? wipe k o si otitp ni u prp ti awpn pmp egb? Olomi (N. P. C.) nsp kukiri w pe, awpn nf. isp- kan on irepp awpn ema orile ede Naijiria.

Onirohin wa kun r a n wa leti pe, o ti le ni pdun meji nisisiyi ti awpD pmp He Igbomina ti n j a Iati gba ominira, ki awpn enia na o si le daduro gedegbe Iati m a a da Ijpba a r a wpn se.

A gbo wipe awpn enia na ti ran a$oju wpn losiKadu- na lasiko ni iye igba lat> lp bu wpn se daduro latima a se ijpba ara wpn.

Sugbpn Iati igbiti nwpn ti n$e wahala ra ko si eyiti o ti yori si rereoniwe irohio lo siklie plan ninu awpn pmp Ile Igbomina lie Q'bhi Qlanrewaju ti ise Minista Alamojuto eto ise awpn Qlppa fun Apapp Ijpba lara Iati gbp bi prp lie Igoomira na ti nlo sugbpn nwpn so wi pc Qlanrewaju ko si ufle o ti Ip si Ipinlp Ariwa.

Igba meji ni a tun fi erp gbohungbo sprp si ile M. A.

Olarewaju ni alp ana iati fun wa ni irohin ominira ile Igbomina, sugbpn a ko le ri ba sprp iori prp yi.

Bi a ba si ti tun gbp prp nipa ominira ile Igbomina a si, e o tun ma a g b p ninu Iwe Irohin Implp.

(2)

1064 1ROH1N . IMQUji QJU EWE K FJ1 (2)

TTTRSDAY PBCBMBER 15.

Awolpwo Dorisa Apa 9

Lati Qwo Adio Mosanya

£o je iyalyna pe eniti o ti ja ija akitiyan bayi yio ni yta pupp larin oyelu: I yna si ni awpo deean yk> pp Babawa. ninu igbokegbodo yi, mo ri ri ppplppp ohun ayp ati ibaun- j- yugbyo mo ^ba gbogbo ry pylu pkan kan Peteru kan (ki ye apostol Peter a ti inu Bibeli nnmo) ninu Twe kan ti "alpoieko ti anpe ni “ Fortitude” s> bayi pe:- ‘Igbesi aiye fno ara ry ko j? nkankan bikose ok.in Akin ti a ba fi io aiye na.

Oloye Qbafemi A

wo

I

qwo

ati Iyaafin Re

Lyhin igbati nkan babu- ru ti ba Peteru, o gbp ohun kan ti o so fun pe:- Ibukuo ni fuo g b o g b o ibanujy ry, ki o si mu vkao

!e loriiyoro. Ibukuo ni fun gbogbo nkan ti i sp enia di pkumin”

Oluwa mi, gygebi prp Peteru. eroi na wi fun o pe!

Ibnkun ni fun idajp re;

Ibukun si ni funastko y»p- n ti o fy da fun mi.

Nisisiyl ki iye ti ara mi lo nja mi laiya biko$e pe ywym ti o fy ju mi si yi le ba nkan pupy jy fun ile Naijlria. Idi rayta pataki lo mu mi sp eyi;

Hkinii Bi o ba ju mi si ywpn, ilu yi ko ni ri mi lo mp fun i$y ribirib ti mo ti ye mo si tun le ye fun ogo ily na.

Ereji: Gbogbo rudurudu ti o ti wo lati nkan bi Osu mydogun syhm le p j s i; o si le ko ba awpn ile miran ninu apapo ily ti a npe ni

‘ Commonwealth.”

Ekyta: Fun igba di? si, iran eto ijpba alayaro ti a fan ynikpkao *a ni anfani lati ye bi o ti fe, ti o si gba pro efin gbp, le yipada ki a si peda sinu o k u n k u n biribiri.

§ugbpn lyhin okunkun

biribiri imply yio de, Nitori na, pelu a'foya, idaniloju ati ireti ni mo fe kuro lati

!p sinu okunkun. Mo si ni igbekele ninu Oiu -va pe ayp mbp 1’owurp.

Awpn pta mi le ma sp pe kini Awolpwp nfi ara re pe? Bi mo ba ku nko

$ugbpn iku ko ti pa mi;

mo si wa 1‘ aiye, mo wa 1 a i y e, B e n i ng ko ni ku si pgba ywpn.

Nitorina, o da mi loju pe anfani ki a r n ki a yan bi o ti wu wa eyiti a n i ki iwp Oluwa adajp rid a - bobo yio si ma wa 'iti ko- ja ywQn ati ide.

Mo fe sp fun p loni pe mou ile ejo ti a wa yi, ni­

nu opoti yj yi, mi i I e Naijtria tuun ti b.'rj si wa s ’ aiye. Iru emi y ; ni mo ti fi gb gbo pjp aiye mi ja fun lati ri pe ko pamn.

Ki ng to pari prp, mi, mo fe sp pe pylu gbogbo idaduro f„n pse di? to kp- ja t.i ko ieki o tete se ida- jo yi, m.. ki p fun suru t.

o Di nigbati a nse yi. P a­

taki julp, mo dnpy lpwo ry fun iy?si ti o fun mi ati awpn ylegbe mi. Mo dupy o nisiyi mu ye tan lati gbp id-.jp ry”

Kyi ni prp iwuri ti Oloye

Qbafy.ni Awolpwp, sp, Bi o si ti pari prp r? ni ada­

jp $uwemimp bere prp tiry.

O sp bay; pe:-

“Ohun ti o wu ki ylomi- ran le so, ero t’ emi ni e'e- yi o, Ki se bi adijp ni m i fe soro bayi bikoye gegebi pmp Naijiria. Bi o ba ye pe iwp nikan ni a mu wa siwaju mi fun ?sun yi, ng ki ba ti ju p s,ywpn.

$ugbpn ko si ohun ti mo le se bayi nitoripe mo ti ju awpn pmykekere wpn yi s’ewpn. Nitorina, mo ni lati fi wp na s’ewpn p?lu.

Iwp ti o ti jy pkan n i n u awpn Olotu Ijpba ipinly lo wa di er > apoti N ; ba sp pe ki o ma Ip bi o ba ye pa iwp nikan ni a mu wi siwiju m . Ng ba ro pe jjeyi yyi ti Ju re ti ri tc tun In ra ei; y nito- ripe itiju nla m o j*.

§ugbon patiki prp ? j o yi ti mo ti ri ti m > si gba, ibi di o p / pp 'baje sily ati pe iba gbi pdun pupp lati tun se.

G gebi mo se ri oro na ui pe okan ni' u awpn ti o parapo lati ko he wi ngbe- ro lati wo ile na. Ohon ti mo mu jade ninu prp ni pe eni na fy yi oja awpri yoku syhin.

Okan niru ohun ti o dun mi ni pc pk; u ir u ; wpn ti o ja fun omimirn iie yi eniti 0 ti se olotu ijpba Ipinle oh ri Altitaka Ijpba ni i!e Igbimo Asofin ni Eko agbe joro tun wa ni idi nkan ba­

yi evi P o mu ki < ro na ta koko.

L'hi igbati m ti pi mu ati ju ■ >vp ■ p.iip kek< ke s’

ewpi a»-pn ti mo pe mo iriuise ni nwpn j? ni u oro esu ' i b11 a se pe bayi h oro r\a •? ise rnr n; lati ri pe a ’ i P I a" p <j o ba job, vsun ay o j. ryiti a -a g el m r >. o ■ p m se ju Sd u

• i . ba se i wo mk >ii n| a mu wa siwaju mi bu da o sdy Abu- u nl - ni pe ■ tiara r s ran yi yugt s n ejo prp iselu ni pm lpp nkan mir­

an wa i a Ko ni ri di wpn 1 iiai hun i m>. i t ejp ti o r ni aji m. e . i ni o mu m so pe tain, na j me porp ki se u adajp ad da si prp seO s > ipa idaduro ri o w lori ejp yi ki se be r-ra

1 c b w.' ni ip 1 mi ni ti o si k die i mu aw n nkan wo yi eri ti i gba eg eta oiu iwe (800p nes) oro awpn ag ej r a tun ba epbeta rj we (600pages) ati r si- risi ai * i j y n n u mi 'ba dun lati su pe eip na ti pari mo si ti da gbogbo a -• q ti fi esun kensileo ya ini lara lati se asise lat da eniti a ti esun kan sile ju pe ki gba eniti ju s’ yvpn laisi idantoju esun ti a ii kan.

Ohun tl o sele ni ibo mi ran k > kan mi yughpn r.igb- aniran en a ni lati ro prp ti o je mo wen.

Ng kn ri nkan rereywpn le s? fuun o yu; bpn mo gba gbopoiw o lo da gbogbo n t an wpnyi sile mo wipe ki sy -i ara ry lo nja.

E DIBO Fun

Akuko

(3)

TUESDAY DECEMBER 15, 1964 iROHIN IMQLE OJU EWE KglA (8)

s w a H i m : m n k a n

Lati Owe LATIFU BA8ALQLA Akpwe A g b a Egb? I M9 L ( ! AIYE

Qmp ti ko ni iwa rere ko poro me nibikibi ti o ba wa lwa aibikita ati tani yio mu mi, ti o ba nhu ni yio fi han gbangba iru Qmp ti o jp pfin ni iwa ko se ft pamp rara Bi pmp ti ko ni iwa ba ti ndasi ni i*akiwa yto tun bp ma wp ipwu yio se bi ohun daradara ni on npe yio tube jingirl sinu iwakuwa apa pnikun ko ni le ka mp awpn Yoruba lo ma npa owe kan bayi pe: kekere ci a ti p?

kau iroko bi c dagba tan apa ko ni le mp.

Idi ni eyi ti a ft nti ppp lQPPpmp ti o ba dagba tan ti wpn ndi Qmuti, 0le Uju kokoro ati elewpn paraku ohun pataki ti o y? ki_ a kiyesi ni pe iru iwa ti a ba ii kp ara wa nigba ewe ni yio sp ' i igbesi aiye oluku- luku wa yio ti ri nigbati a ba dagba o w e Yoruba kan ni o Ip bayi pe Yiyp Orun ni sp bi oju pjp yin ti n.

Qmp ti ko ba nl iwa re re jp itiiu fun awpn Obi rp lb ouje ti o to iiu rp fun Obi ko wppp sib;sibp bi a ti i pe itpju iwa pmp rairan to ko r.l gbp ko sa pe ti inu rp sa .

Tani fe ki pmp bibl iou on ma pe wulo fun pjp

aiye rp afi ki o ma a sunta l i o si ma wp pwpn bi obp awpn oniiu ni o saba ma nsp bayi pe, Oba lowo Ivwp to spkpre Iwa rere ni nkan.

Mo b? gbogbo enyin pmpde, papa gbogbo pnyin pmp egbp implp Aiye p j?

ki a ma nu iwa rere oitori iwa rere lo data, i e lati nko pspre ede od1 pwp wa Lpse to mbp, lagbara Oduduvva end yio bigbo gbo enyin Odp sprp nipa pgbe jdp titun ti a rpe r.i (Nigerian Youth Piecceis, ati itump pataki ti a le fun pgbe na pplu ero egbe na fun awa Qdp ilp Naljiria nitorioa ki p tpju kpbp mejt yin sile.

K k U E O !

Kurani Ogbpn Epu ti a ?e Larubawa ati itump rp lede Yotuba 25/- Postage l/6d, Iwe Adura pitaki fun Aris ki ati ippgun lori - hun gbogbo lati ilg Mi- stra 1/6 Iwe Atump Ala ati Adura Ala ib.ijp ti a ti nta ni 4/- o t| din si 2/6d Afpmp isin Moham­

med II—

Tete ra tir? lpdp:—

ESAN K.OGBOGUN SERVICE 8, Idumagbo Avenue, Lagos Nigeria

( Leti Oja Jankara I’Eko

K in i E \d n r o Fun ?

Bi o ba ni asp fun fifp ati iilp bi ( wollen ) asp oke, Xappta Sapeti ati orisiripi asp ti n ba ni fun fifp ati lilp ni i-rpju kan

TETE GBE WA SI <?D0

JOYCE L AUNDRETTE SE R V ICE

34, Ojo — Oniyun Street, Apapa Road Ebute Mgtta

Kia ni ao ba p fp ti o si ri gba ni psp kanua.

A .e wa gba ni ile rp, ki a si ko pada fun ,> ti a ba fp tan kp nomba ile rp raDp? si wa.

Dan wa wo ipkansoso ki o si ri bl ipe wa ti dara to owo pppku ni a si ngba

Y E IK A WO HU ' V O

AQUARIUS (Jan 20 Feb l8)Qjp ooi ko buru tobf sugbpn pro ola kan yio p?l? loni lori ohun kan Mape gbp ktle alejo rara Mast pe ba enikpni jowu papp.

PISCES (Feb 19 - Mar 20) Ere obp fun p loni pu- gbpn agbara re ko b? pe suru, ki o ma si pe apeju ki o le dara fun p.

aRIES (Mar 21 - April 79) Fi oju ati pkan r? si awpn nkan ti o npe pataki nikpn, ki o si ma feti si gbp- ran ki o tofesl si prp, pugbpn jjki pgbpn ori pe daradara

TAURUS (April 20 - May 20) Ire obp fun p loni gyp , t adun ni igbthin re Iwp yio ri otitp prp gbp lati pdp awpn enia pataki feti si itnpran wpn.

GEMINI (May 21- June 20) Arp yio mu p loni pu­

gbpn odara fun ki o ba enia sprp pupp ppra rp ki ori rp ma pa Ese di owp r?

CANCER (June 2 1 -July 20) Awpn prp r? a p ati awpn titun yio ni lp tprun si p awpn obinrin yio si f?

ppplpnp prp atijo yio sp nkan iyanu si p.

LEO (July 23 -Aug 22 Gbogbo arisiki r? dabi eyiti o tilp sibe bo til? j? pe igba ko lo bi orere fun p o ko pai si o ;uta idigbolu ppa rp mipe gbpkple enikan tr bi atejo.

V.RGO (Aug 23 - Sept 23) O dara ki o tete wa wprp kp fi se ad i masi pe ko ohun ti o ma da be ni ki o mape atako si orp pmkan ki wpn ma mu o ni pta.

LIBRA (Sept 24 - Oct 23) Okan rp ko ui baly loni ki o ilia si pe jeki itiou bori pgan ko pe alaisi iporo dip pgbpn ' ri rp ko si to pugbpu Iwp yio gbp Irohin ayp.

SCORPIO Oct 22 - t'Ov 22) Ire nbp fun p Ipjp oni kole pe ki o mape si isubu ati idi e fun nipa owu jijp gbo gbo re yio ma pipe pp fun rare.

SAGIITARIUS) Nov 23 - Dec 21) Ipprp kan pplu igbo ara kan yio sple larin iwp pplu enikan mnn awpn ebi re mura lati ?e atnnpe.

CAPRICORN (Dec 22 - Jan 19) Awpn pre rp atijp ad a vp i titan yio jpri pjp oni punwpn fun p ki o si gba mpran nipa bi ase ntpja owo nipa ipp

GBoOBO ARA 1LU NKQ ORIN I YIN AYQ

n ip a

“DYNAMIREN"

TQNIK

ALfc~BI-ALE Egbogi lpniki Jamanu titun ti gbogbo ara ilu Eko ati ja- kejado Naijiria mp daju fun Akp agbara ati Aj?

bidan ipp rp lara Agbala- gba Qkunrin gbogbo.

Bi ar? ara ba nmu p, nigbakugba fun wahala la- la pipe ti o ko le jpun daradara, tabi ki o male sun dadi pkun Ipsao tabi awpn rpa n ara rp gbogbo ko ba p pp daradara ti Eemi 3reatb) inu r? koba gunlp daradara fun ip? tabi wa­

hala pipe tabi fun awpn ailera gbogbo’ tabi ti pjp ori rp (age) ba ti koja pgbpn pdun o si de adprin tabi jub? lp. Mp daju pe “DY- NAMIRBN ni egbogi ti o nfp U'i sp'ara rp di ptun pa tap ita ara rp a si jplp, prao -ra re tto ti hunjp vio yi po padapatapata alafia ati gbadun yio de si q lyen

be

Bere egbogi na ni §pbu:

NIGERIAN MEDICENE STORES 4. Tinubu Square Lagos Waterloo Medicine dtores,

8, Balm Church Street, (Qja Ita Faj*

Lagos, Nigeria, ADEDUN CHEMIST 14 Wakeman Street Yaba

(4)

_ TUESDAY prefcM ir.'K l .s ___<Q( 0 IROH1N IMQLIg: OJU EWE KERIN 141 ' EGBXJi A WON aRA ILU FARANSK

T E S S Y I M t i i Fun Qui:-— Qwq At! Oroide Gbogbo

t

• essydre je ojulowo egbogihaunhain ti nv i. i',-ufere kcsi kakiri it boro , u Nigeria iu■ iioju fmp g- A0 tab"' pmpde lati le je ki won ma hu EHIN . nu w 0;) peiu irprua laisi «abal« rara tabi t-ikole sun yal* ' lcis ,n t jbi sun awfn iya wpn gbogbo Og r or sirisi eab bayj ni wgtfnpoiowo si-u er- uf hunt .ijr-.n .ati sinu jwe klira 1-houn y .-• lost yr 1 !e * we.£g b( gi TesSyd re ram o. Qlgtbon d, on . n" > ;* u 91, on ara ilu S.-O at! awpr, a n dr A - - FUP . e„b( gj yr dajndaiu . n no ni .. wa CrlA. 1 fe fc b a s e i e h i n u t d i • ,o n si L f u n

wahala tabi h>' „k0ii 11 erne ouuu « ako. Kosi fekun fglr- n, inu rirun 0 0 ri inu wc a.perr osnnu

r "

, gBuru tab. ikol 0 ma nvo

,ro at- fete an orb.nsr awgn any d * Jessy awpn <?m? <?wo lenu m ba Ehi H ;d : ti dre a ma mu ki ehin enu re omo re g

Jsar. ara \\?n p?!u. - ,, . . b , ,e r a j Aw<?n QfflQ ti WQU : lo eg o ; V1 e

raran i ' ... “>u ko

Si ie ri aye i.. i du 0 ' ara

dara ti nwpn si nsun gb .du: pylu Berc Egbi-ai Ni Sobu . y :

' W A T E R L O O ST O ! S 8, Pa'ra Church Street. Lag s a d e d l n c h e m is t

4, WakemaB Street, Ytt a

t(iu.«w«) rija li t -<ui

I ’i

V«-j£e

Niioripe

O KO TI POLO >\ () O J \ IU:

SINU

i R O H I N I Wi O h E

T ’OUl N R N GBOGBO YQ UBA

KOWE 1 POLO WO OJb R f M AL)V RTISM ENT MANAGER

l R O ! i l \ SM-oLE

I 6, P: n.gl cse Street Phone ’ 9 5

Iseyin Ko Egbe Demo

<9iotu, Inu mi yip du bi y ba iegba mi ni aye die ninu i-ve nyin oloyinmpmp lati fi hs»n gbogbo awon ymp jl§ Yoruba pc awo t : 1119 i/u ls$yi« ko se $gbo nira ati pe lojpkpjO egb? A Ion if re ,;yi ti Oloyc Awrlpv p n?c olori re ni ti awon pmp Mu Iseyin Mo fe fi ye enyin enia to ngbg pe aw, n ggby Dymy ma nwa si l$$yin ioti

§e eto ipolo-H'P ibo

Sugbpn-mo fi-fi ye nyinpeko si o m o ilu Iscybi to legbagbe i§? ti Oloye Auolpwp se si i l u Iseyin . -i : beg be re lasiko ti o wa !> ri aga gegebi C:I tu lioba Ipinle hvp Orim Naj-ria. L a t i igbaii gbogbo nkan ti kuro ipwp Olove A ’.vq!^ a o ni a ko ti n ok an

OLOYE S.L ARiNTOLA Olori Egbe D,my>

to jv re-re l-an ni ilu Iseyin a fi pe egbc D?mp ma fi i\a ma je awcu enia ti ko ba se ti w y n N tori eyi a ko thi>. sj c g b e D?my patapatE, Olotu mo dupe pup^ fun aye ti y gba mi,

bnii ni, Jimph Adcspla

ISEYIN.

g e g e N f e I t o j u I j o b a Olotu i n i!! j»i yio vFin b e ba lel- ba mi ■ i avc die i inu i-.‘. ie ny in Ohiyi m omo Lit: k, . !;< ba ip i lwy Or N ai: id: 1: 11 eio to j<? p A ege k u < j i

1 iiu k ere

ninu i 'N n ilu to wa ni CkliU 1

:

Mi pe a ko 0 UVil) -i i. ltd • ia .ara.

Inu a 9-i ia Auegc y>o du b l! b,. i p n l V <w9 Oi i i) r, ba 1 (eie so m ijot;y -lu11 lati ri Kege- bi a ii ri ati • wy>n nk. n i llebu to w-i n i ilu na ■ i' «j ba Ip nle Iwy r-in k-isi wve' *i ily-

si«aju sio se wa ni ilu no.

Eleyi yio si dura bi Olotu Ijtyba ipinle hvp Orun Nai- jiria ba le Jo po re rere la ti ba wa sc etc bi idagbaso ke yic se a a - i ilu Agege lati fe jc ki a :e anfani otvo

<1 ri ti a ns.m si apo Ijpba wa na. Olotu nr dupe pupp pko Oba ko ni si ny|i. lese. Amin.

Emi ni Alice Adeb'si AGEGE

A Nfe Irohin Imole Ni Ifu Offa

Olotu jpwp gb - mi 1,1 aye d c 1 inu i\\ e nym oloyin mi, my) lati fj ,.Ja;e mi yi \e nyin ni ckun rere lori iv/e t'Vin Irohin-itn^Ie cyi to je pt- a ko nri ka ni ilu Qffa a li ti aw on e- ia wa to ba wa ni ilu fcko tabi ibadan h .' i si i!e i a ma nri j" e r a k ey. to je pe irohin h dun ai itvton nan ' :i 9 1 911 ■■1 o si lun in-, iwe na.

! ■ J1 > ! si dun m 9 awon (in} i|i, Off 1 tie ba le lo ipo nyi rere ki e se irai 1 ,w fun w geaebi o se le mu , - i ■ e Irohin Imp! ilu < d a g-.eebi ilu m r i, ni ilc karg o'j'ire bi? Rig ii mo ti ivvt tia 0 je ol un in ya mi lenu lati ii pe iwe irohin k a n wa lede Yc-ruba cyi to je pe oj« jump lo njade.

Inu wa y e dim bi a ba je ri i * e n i ma ka n i ilu OH a i ojojumy .;t i pe 1 i e (etc > e eh bi e bi As ju k. n n i l u Offa.

Olotu a nreti nyin.

Emi ni, Ade i ve Baloj un

Ol’F A.

E Ma a Ka Iwe

•irohin Imoie Lo-

jojumo Ki c Si

Ma a Polowo Oja

Nyin Sinu Re Pelu

(5)

TUESDAY DECEMBER______ IS, 1964 ihO ilTH IMQLg OJU EWE K.XRUN j g j

Yoruba Ko Gbpdo Gbagbe Ore Ti A wo I owq Se Sile

Eyin eo a mi ti y jy ymy 1I9 Ijybu jakejado ily Naijiria paapa julyj'ni ily Yoruba n o r0 pe ' o si nikali to gbodo gb .g'e ore nla ti Oloye Qbafymi Awolywy je si Ipinle Iwv Orun Naijiru 01 akctan lasiko ti o wa gyaebi Olotu Ijyba Ipm e Iwy Orun ivajjiiia an paapa ni asiko ti 0 jy pe ygbe re ti o je ygbe Afy ifere lo nje akoso Ijn- ba lpinly pa

E DiboJ’ Fun

? IMS

Lati Owo Olujoye Tiamiyu

n^y no b. rara u o t u i i.vpn si fi ibo ghe tori ify o* k, a g .e i,e Ba

bn vva u ki y jyk 1 a kyywv t vvy 0 yd sit? ki u ro igi,e si aiye awyn ymy *a a si dibo fun ygby alakuky an yghy Afyiifcre kt tlysi aju . ati alalia pylu Ijoba rere yio ele t; wa lywy tabi pe ki ae I si !e ri y wy n« gygybi d ti wa {' tele sugbyn (ihun to te fa le 1 j eyi wa ni pe ki o dibo wa fu C

tgbe ol ne tlu eyi 11 ise UPGA 1 Awolowy le jade lati wa fun wa ni yna eto ti yio mu ygbvn ati ilysiwaju ba wa o i i gba die.

Oloye Awolywy pe -1 jade.

Nkan ti mo fc so le ti wyn Iiybu loni yi ni py awyn Ijybu a l p s npa Iowe pe ‘ 1 ybu ki j: yj9

§ u g b o n me si my pe ti omy an b 1 • a ti o je ymy oky iiybu ti ka ba d i b o fun e g b e Aienifere eleyl yi fi han pe (j, w, re ko my re pitapata

Nitori m i pe ypo'ypo ilystwaiu ti gbogbo agbe-.

gbe ljebu ni I siko tiegbe Afenifere fi nse akos„ Ijyba ipinle iv y 61111 ki i$e ke- kere papa tu ilu w y n y i Aheokuta, E li ati agftgbe Osboo ti awyn ilu ti mo dauik y re yi ko ni fi iwa al aimt; ore ra n$e to ye ki o ir-0 ygby ti yaty si y g b y UPGA p .danu owo ibo ry nigbatinwyn ba nka abayy ori.

Eyin ymy ily ljebu nile ati lok i mo to pe ilu miran ti k o ju oju mydoguu lo si Ti a ba nsy iru ore ti olo- .

ye Awolywy $e si ipinle Iwy Je Pe nwyn ng'ja ry ajory- Orun a bo le sy tan ii oju “!»gbesi ti nwyn da yda si tnefa «ti pe awyn agbe ile W<* 0?a wyn ti awyti ilu Yoroba ko gbydy gba ry ati !'^a m inn ni omi yry pelu awyn agby jakejado ily Nai- ‘"a fiyntriki. Nitori eyi eyi

... n eo a mi ile ejy to ku p'a- jiria tori owo koko ti o jy ki

o ga soke ni ipinle Iwy Orun eyi to je pe 0 ran awyn ngby to wa ni ily Naijiria lywy.

l i a ba tun mu you ku- ro nipa ti awyn agby awyn ymy to ie pe iranlQwy olo- ye Awolywy lo gbe uwyn de ipo giga loni lori eto eky ati pe awyn obi ymy miran k o n iaeb ara lati ran ymy re ni ile yky si je pe o rl anfam eto yky pfy jy ti aw- yn ymy wyn si wa ni i p o giga ni ojn om nitori eyi enyin enia mi si fy ki e ly o iru ore ti e le je lati fi san ore fun 01 >ye Awo- lywy.

Otity ni a ngby a r i w o k ikiri ti nwyn o k g b e Awo ! Awo !! Awoii! su- gbyn ki ntk le my pe oti­

ty si awyn enia wynyi fe- ran Oloye Awolywy o di yjy idibo ki nio le my pe awpn enia wynyi f e r n ti Oloye Aaolywy de !nu ati

yi lati je pe a le da Oloye Awolywy lare bayi ni eto yi ki y si je ki a fi tykan- tykan dibo wa fun ki a si !e fi ibo wa da a lare.

Nitori eyi ohun to jy pe o le se anfani fun wa lyhin yia ni ki a ro tr awyn t. mo wa to wa lyhin ati awyn t

Alhai D S Adegbenro

Gbanjo ! Gbaojo

F . N QDUN K ER t SIM LSI A ni lati fi kede fuD awyn ouibara wa pe Qja gba­

njo wa byry lati oni ly titi dl 30/11/64. Tete ra tiry ki o to kase nily

APEJUWB ILE ITA IWE WA Wy Byysi Mushic, syka'y ni Ate\.ylara Bus Stop 1 Bere ladipo Street, ti o ba rin titi Ladipy, bere ILE IWE ODU * ABORp. Ti o ba de ibe tan, wa be re Nombs 5, Alaba Stree Mushin, ile ijy wa dojukyti

ODUS SURF”

AWQN OJA WA

Olubori Egbogl Ajybidan 40s di 30s Iwe Egbogi Ajy- bidan 25s di 22s Iwe Egbogi Awogba Aruu 20s di 17s Iwe liana Ifa purin tity ait etu jije 20s di 17s Iwe Afoj?

Isedaly Yoruba ati Psalmu Ajybidan 3/6 di 2s 6d Turari Isygun Ajy 10s 6d di 8s Turari Itaja 10s di 6d 8s Turari Ala rere 10s 6d di 8s lye owo Turari pangolo niti oke yi Turari ti 0 wa ninu pakyti jy 2s 6d pere Iwe Ilumy Ala Joseph Alala 5s Iwe Aniyan eto Irun o ti di 2s 6d Akynni lysin pataki Islam 2s 6d Tailor’s Measurement

book di Is 6d

Tenants Agreemeot Forms 10/6d di 5/ Gold Smith Form.3 Cerlficate of Apprenticeship (myta] 17/6 di 10/6d

OJA IlT U N TI A $E$E R l GBA jA ttla tuimy fuc. adura tete Idaloju (orijiriji awy j' u Turari.

Abyla mimy fuu itaja (Kowo wyle pylu Turari 20/-

„ „ „ Isegun Aje pylu Turari 20/- Lyfinda tabi Ororo ipara fun itaja, Ijegun Ajy ati arisikl 30/- Igo kan

Fi owo Tansy tabi ki o wa ra ni ydy;—

J. O. Shoyinka Alaba Street 5. MUSHIN.

(6)

IROHIN

IMOLE

• • I S i OLE ORE AIYE. TEN! CBOGBO LAW A Mo >72 TUESDAY DECEMBER 15, 1964 [2D)

Awon Qmo O gun He N<*ijlria Lo Si lj?bu-ode

IJEBU-ODE Ni kutukutu owurg gig Aiku ti ije kftnla OJU vi ni awgn 9 m 9 oguo ilg Naijiria eyi ti a npc ni "Fourth Battalion o f Nainrta Army" ni irohin ft yc wa pe nwgn wa ni ilu Ijfbu-Odc bayi lori irin ajo wgn lati lo fi yc awgn enia ilu Ijcbu-ode lori gegebi nwgn le 5c gbinyanju lati 1c I9 kg i$g ogun eyi ti nwgn yio ft odindi gjg met a je ere eyi ti yio wu enia lori lati le Ig kg i$v ogui.

ilg Naijiria ni Ijebu-Ode ni awgn g m g ogun na si ft ibudo Ni ana ni irohin fi ye wa pe awgn glgpa na ?e ori$iri$i ere Idaraya ni papa ti ltoro ni ilu Ijgbu-Ode lati fi han nwgn e n i a lori awon anfanl to wa ninu i$g o g u n ni ile Naijiria ati gegebi olukuluku le se gbinyanju lati Ig fun 5g ogun.

Awgn gmg ogun 1 1 ? Naijiria na ni oniwe irohin wa ti i I u Ijebu-Ode fi ye wa pc g g a acha ti "Fourth Battalion Naijiria Army ' gga o g u n S. A Wall ni o $e olori awgn g m g ogun na Ig si Ilu IJebu-ode.

Irohin fi ye wa pe Igba ile awgn glgpa

1YAAFIN AKERELE JARE

EKO:- Ni ojo Abamgta ti i$e ojo kejila osu yi ni adajo Agba lie gjo kekerc Eko, Ogbe~

oi A| boola Qlaloye paje pe, ki lyaafin Boye Akercle oka n ninu awon A$iwaju ogbe Demo i'Eko ati anon enia mokandin ogun pyln r, ki o nia a I9 layo ati a'afia nitoripe esun t a fi sun won ko fgsgmulg to

Qigpa ti o ba lyaafin Akereleati awgp yoku re se ejg se alaye fun ile gjg pe, ni gjg kgwa o$u kgkan la Qdun yi, oi rogbodiyan ti o fgrg di ija igboro be silg ni opopo $h?tgolu Eko Lgsgkgsg ni awgn Qigpa sure de ti nwgn si dekun ija na ti nwgn si mu awgn ti nwgn da ija na s'lg igsi

Tesan awgn Qigpa lati gbg ti gnu wgn.

ALAYE Ninu idaje rg eyiti, o se fun iseju mgdoguo, Adajg na se aLye pe fgbg oselu kan ko le ma a t>u ara rg ja laiko si ggbg oselu keji gggg bi alaye ati gsun ti awgn

1DIJK ! IIMJ*:.

A fi eyi kede fun awgn Onkawe Irohin Imgig ati awgn Qmg karg-o-jire pe a nfe

ITAN L’EDE YORUBA

Eyiti gnikgni ko ti tg jade ninu iwe ri tabi ti nwgn ko ti sg lori grg Red o ri Eoikgoi ti o ba si bori yio gba

5 )

PQNUN MARUN Akiyesi;- Kg itan tire ki o han rekete, ti gniti ko ba han a o fa ya oi, ki o si mg dajudaju pe ko ni ipa ninu Id'je na, ITAN gniti o ba si daraju ni a o te jade ninu Iwe Irohin Imgig yi a o si fi lg(£5) Postal

(Order) ransg si

Fi Stamp Tgrg (3d) tans? fun gbigbe Pgnun marun f£5) ti o ba je pada si g. Ki o ge ibiti Idije yi wa. ki o si fi ransg p?lu Stamp tgrg rg si wa.

Enikgni ti ko ba ge Idije tirg ransg siwa ti o ba jg owo na a ko nl fi ransg si.

Ibugbe... ... ...g... ....

Fi itan rg ransg si:-

Olotu Irohin Imple

16, BAMGBOSE STREET, LAGOS.

Qigpa mu awgn enia na wa si Ile ejg fun.

Adajg ia tun sg siwaju ninu grg rg pe’ 00 gbagbo wipe otitg oi lyaafin Akerele mu egba, ti o si fi na nwgn gmg Ile iwe ti nwgn nkg- rin owe ati gtg niwaju ile rg ni gjg 1 a.

O ni awgn gigp 1 ti kuna ninu i§5 wgn, nigbati nwgn ko ti le mu awgn gmg ile Iwe na wa si ile ejg ti o wa je wipe lyaafin Akere'e nikan ni awg glgpa mu wa gggebi arufin Adajg na wa here pe, a gbg wipe enia meji ja enikan tari, enikeji dn?

Adajg na tun sg pglu i aou

EJO

*

pe, “gna ti t.wgn glgp gba ti o fi jg wipe, nigbati Iya- afin Akerele Igke si wgn nl

“ Lion Building" ti r.wg > ko tete daa lohun ko jg eyiti o dara to rara!!

Osi ba a»gn gkpa wi wi­

pe, nwgn ko se isg wgn ge- ge bi isg.

Adajg na gb 1 wipe, abani rojg Ijgba na kuna ninu gjg (i o to, laivo mu awgn ema ggbg Keji wa si ile gig Ighinna o gba wipe lyaafin Boye Akerele gmg rg gkun- rin Akingla, Iyaaf n Olu- funtg Thompson ati awgn enia mejidmiogun minran ti awgn glgpa mu, ko jgbi eyin na 1 itori idi eyi, Mo da nyin s>lg, g ma a ig ni ayg ati aiafia.

C o n g re v e s F e m a le Ifieniedy

(FUN OBINR1N

Ojulowo egbogi titun fun gbogbo awgn Obinrin t 0 Pa oi iygnu abi amo di inu rirun nigbakugbata i n gkg gkan ghin didun ibadi wiwo tabi sisan ejgduu ati tabi bikoto eje ara Inu gbigbemn nigbakugb°Igba- -aiye riro gmu riro diduu arg atiou wa ni o ma nfa oyi-oju Ilaogun a a gsg ara sisan gfgri tabi pglu iba ati olutu Egbogi yi dara pupg julg fun itoju gbogbo Obinrio gg­

gebi Ajo fun ilera ati orisirisi amodi miran ti o ma ayg wgn lgnu ni inu nigbakugba pglu

NIGERIAN MEDICINE STORS 4 Unubu Square! Lagos WATER-LOO MEDICINE STORES

8, P Imchurch Street, Lagos Phone 22L/8 Nigeria, (Qja Ita foji

ATI NI SQBU OLODUMARE DISPENSARY OKE

IBADAN. BQLA

Printed And Published by Modupg Printing Press. 16 B.mgboje Street Lagos Phone 21985 Editor: TUNJI ADuQSUN 45, Campbell Street Lagos (15/12/64)

Referencias

Documento similar

wolewole o si mu, Nigbati o mu ti wpn kp akple ti o sp bi awpn igi bp wa ni N igeria.' Mo ki gbogbo agbagba O| 0 yui, ba ft mulp si kotu wpn tab wpoyi se wulo to ni ode oih'Tim Lphiona