• No se han encontrado resultados

Irohin Imọlẹ

N/A
N/A
Protected

Academic year: 2023

Share "Irohin Imọlẹ"

Copied!
6
0
0

Texto completo

(1)

t D A U tN IM O t P OJU EW E KeTA (3)

No

^ni To P e Aiiubakar Mi Ole Pi l*onn M arini J u r a

EBUTE — M&7TA;— HI R u ti i$e civ kgkandiologun o$u yi dj He ^jo nt ki Qkunri« k»n ti o keg be pe AJwkoso Ijoba apaps> ile N aijiria UKU Alhsjl Abubakar ni Ole «i i/e cjp kekere ti Ebute M ?tla 1$ fi pvun nut run tabi ki o 1<? si fwpn o$u kan ppiu f$£ ala$ekara.

Adajo ile ej<? na tun sp ninu idajpa r$

pe pkuurio na ko gbcd p b» enikanl-j.n fa rcgbodiyan fun odincii osu mejila ta- bi pe ti o bu lu ofin i.» yio san pgun pQ- nun tati fi tanra ki nwpn to j<?oi iya sii Okunrin na ni Qgbeni Festus Ara- ba eni ogun pdnn eytti awpn plppa fi

?sun kan pe o lu ofin to le da rogbodi- yan sil? ni arin ilu Araba si gba pe on jpbi ?$un na.

Ni pjo Aiku fi ise pjp Aejidinfogun o$u yi Digbali Alakoso Ijpba apapp ilp Naijiria Qlpla Alhaji Abubakar f< ip ni Jkpja lati Ip si .Kaduna'fun ipade kan ti awpn egbe olomi N P C ati egba D^jnp N N D P fe Ip «e m Ok unfin na fa igbe ta li o ni ok! ole!! ok!!? eyiti awpn plp/ja yarn tire mu rdarau na ni adugbo 'Denton Street, Ebute M etis'

IDIBO APAPO YIO WAIVE L’OSU KQKANLA

ODUN YI

Ninu awpn a d c h un ti awpn Olori egbe Olomi N P C ba awon olori egbe Demo N N D P, M. D. F\

N D C (Niger Delta Con­

gress) sc lori eto adehun na n i b i ipade w p n na ni Kaduna t yiti awpn Olori awpn egbe na jijo lero pe nwpn se ni;

Ninu awpn orp awpn pmp pgbe jinroro lori le ni pe to ba di asiko ti iie igbimp asofin ti apa- po ljpba > yio se ipade eyi to tnbo yi pe awon onto pgbe na yio so r p lori idasilc ipinle kan ti anwpn yio ma pc ni “ C alabar S tate” ati River State ” eyiti yio je pe nwon yip ya kuro lara ipinle Hit Orun Naijiria, iwo Orim Naijiria a t i Agbedemeji pitnle Iwp-Orun Naijiria

Awpn egbe na tun so ninu ipade won na pe awpn omo "egbe yio pari ija kan to \va larin awpn pmp egbe M. D F. larin Ogbem John Edokpolor ati Qgbeni James Otobo Irohin na, fi ye wa labele pe awpn egbe na yio fun Qgbeni John Edokpolor ni ipo Oludasile egbe M.

D. K ati Ogbem James K A D U N A :- Ninu ipade ti awpn pmp egl ; Olomi

N P C ati awpn alabasepo won egbe Demp N N D P

“gbe M D F ati awon iyoku won ni irohin ti do owp wa label? nibi ipade na ni a t i ' gbp pc eto idibo si ile igbimp asofin ti apapo ljpba N aijiria yio waiye ninu osu kokanla odun yi ati pe awpn egbe Olomi N P C ati awpn alabasepo won ti jin ro ro lori eto idibo na nibi ipade ti awpn Olori egbe na nse lowo.

Olpla Alhaji A bubakar Tafawa Balewa Alakoso Hpapp 1 j <_>be /vaijiria

Iforaiko A u < hi

Oino$£e Y i« L’u sv T i :mn>

EKO:- Ni pjp Ru ti ise ojo kpkandinlogun osu yi ni irohin de pwo wa laii ile ise Ala oso .to eko fun apapo ljpba ile Naijiria pe eto fifi oruko awpn omp- de ti yio here ile eko ninu odun to nbp yio bere ni pjp kerindinlclogun, si pjp kerindinlpgbpn osu yi lati agogo mejo owurp si agogo mewa ati lati agogo me- rin irole si agogo mefa irole fun odindi pjp meta, Iro­

hin na tun fi ye ni pe obi ti o ba kuna lati fi oruko pmp sile fun pjp meta nwpnyi ko le ni anfani ekp ni ilu Eko ati agbegbe re l’pdun ti nbp.

Irohin na run fi ye ni pe pmp ti nwon ni lati fi oru­

ko sile fun ile eko lodun ti nbp ni lari mu awpn pmp na lpwo ati pe ki is pe fun obi ti yio so pe on ti ngbe ni ilu Eko ni kan sugbpn awon obi omo ni lati ri i pe pmp ti yio bere ile eko lpdun ti nbp na ni lati ko npmba nitori arun ajakale.

Aw'pn Obi awpn pmp ta­

bi Alagbatp ni lati ri i pe awpn omo ti nwon fc fi oruko re sile m ti mu iwe eri pjo ib: re lpwo lp si awpn ile ekp ti nwpn yio li fi oruko awpn pmp sile fun ile ekp ni pdu ri nbp.

Irohin na tun fi ye ni pe

agbegbe re ko letp lati fi oruko omo re sile.

Irohin na tun n ye ni pe lai je pe o han gedegbe pe awon Obi tabi Alagbato si wa ngbe ni Eko laseko ti ifi oruko awon omp sile bore ati pe lai je pe awpn obi pmp na ti ngbe ni Eko lati ibere pdun 1964.

Awpn pmp ile ekp to ti w'a ni ile ekp tele ko ni anfani lati tun lp orukp sile gegebi eni pc o arse fe bere ile eko Irohin lati ile Alakoso eto ekp ti apapp ljpba ilc Naijiria na tun se ikilp pe eniri ba gba pna evo li orukb pmp sile fun ile ekp lodun ti nbp na ni lati jiya lori eto to ba ofin Alhaji A HAM DU BELLO

Irohin na tun n ye wa siw'a ju si pe awpn pmp egbe Olomi N P C ati awpn alabasowppp won ti here ipade na ni pjp Aiku ti

OLOYE AWOLOWO ise pjp kejidinlogun osu yi ati pe awpn ptup egbe na si nba eto pro won lp lori im ura sile ati a d e h u n ti awpn egbe na yio si j i j p fl pwo si lati nip e r o ajumpsepo won lasiko idi­

bo si ile igbimp asofin ti apapp ljpba i I e Naijiria na eyiti yio waiye ninu osu kpkanla pdun yi ge­

gebi irohin ti a r i g b p labele na.

(2)

FRIDAY AUGUST, 2* 1964 1

R

0

HIN OJU EWE KEJI ill

OTELEMUYE

I^I h 1 O^ewe Yorulia ?

Ni pjo I?egun ti isc pjo kewa osu kejp pdun yi ni CKelen.uye Eko wple to gberij lit cmti fgbs ndun. Mo ki i. o si ki emi na. \io wa bere Igwp ry pe a raa ri yni loai " May?

Qkunrin’’ osi dami lohun pe byeni prp kan ni on wa bere Igwp mi, Ni mo ba sp fun pe ki o m$o nile. Nwpn yi ni awpn ibere ry ati esi ti mo fun.

AwOn Ibere

V M ? I e n i u y < P

Eko

Qtplemuye E ku deede iwonyi o Olotu, §e ara le d ad a ?

Olotu :• lyiwo ni o le sc bi ara mi ti le to , ko si nkankan lara mi o.

Qtplemuye Lori grp nipa dida egbe osewe Yoru- ba sily ti Qgbeni J. O, Shoyinka nkede re lojo- jutnp ninu iwe irohin Yoruba ati Imple ni mo se wa ba nyin O l o t u I n n mi dun lati

gbp be e nitoripe eni mi ni Qgbeni ti o daru- kp yen.

Qtylemtye Ore mi gidi ni Ogbeni Shoyinka na ise, biko ba ri mi ni i$?ju kan yio kan mi lara bi ogan. Bi o ti kalariri mi to, bi o tily wa legby iyavvo lpganjp cru bi mo ba kan ile- kun kokooko. piri ni yio si fun mi tabi kilo tun ku ?

Olotu Inu mi dun lati gbp be e ki i wpn Ipd?

emi na. Kini o fe sp si orp dida egbe Osewe Yoruba na site ? Qtylemuye Ohun li mo fe

so si ni pe lati igb .ti Ogbeni

Shoyinka ti nieuump ida- sily egbe awpn osewe Yo­

ruba ko kp ibi ara si to Olotu:- B.iwo ni o se mp pe wpn ko kp ibi ara si ?

> telemuyy: Ohun ti mo fi mp pe nwpn ko kp ibi ara si to ni pe, a ko gbp pe nwpn ti da egbe na sily bi pgbyii Shoyinka ti nt.-nu 111 ,) to.

O |otu:-O dodo pro ni o sp Otylemuye ye. Emi p pa ti kin prp Shoyinka Ichin titi S’jgbpn a ko ri ki awpn ose­

we wa lede Yoruba |i giri.

O tc ly m u y ,A se k o ti emi yio tese by prp yi ni nwpn

yio to ji giri Olotu- Ngo wipe o wi bee

Odumsre ko fuu p se Qiy!eniuye:-Amin ati amin uloiut-Nigbawo ni o ti ri Ogbeni Shoyinka m gfehin?

Oielemuye-:.Mo ri oi ana a si j ‘.jp fi prp jnm itoro prp tori jdisily ygbe oselu na

Qlutu: Kini o tun wi Otelemuye:- Orp pp ninu

iwe kpbp, ohun ti ow.

ati eyitt mo bere Ipwp ry nt yi o O lotu Q T E i - E M U Y E P A D E

S H O Y I N K A Otelemuye: Eku oginnitin

yi o Sht y inks, se kn de pdp nyin o?

Shoyinka: Nko tile mp chu ti o nje Pginnitin ni­

toripe mo ti fi ekp irp- mi gbe pbe ti oyir.bo

PORAL

Bi amodi “ IKO” ti Qjo re ti pe tabi ti nyo e lenuto k an bi (.dun kan tabi ju e lo awpn egbogi iip i ni ese iwosan re rara, ma 6 owo re se owo • f mp

Bere fun egbogi awpn ara, lu Faranse ti wpn up ti PORAL ojulowo hanunhanuti, a amaiase egbogi fun In otutu, Ikp pna cfun, Ikp Igbaava, i o ill , Ikp ti o mu mu ema tu ke ybe nigbakugba lati inu "[fun wa (Lungs) tabi ti o ba nmu enii ru pelu.

Bi o ba an lgo kan PORA L yi wa I« p na yio ri a i tp "inu era re ui kiakia lgbjaya tabi Qua pfun r ; ti o ma nho yio duro “ !K O ” re yio si sm ni p atip ata i vp yio ma ji-ut-dar dura iwp y c si un fonfpn pylu a la fia de

Bere egbogi yi ni a»pn orisiri 1 L§b gi Ikp miran ni pbu awprr. —

WATERLOO MEDICINE STORES g, Palmchurch Street, Lagos Phone:- 2287 Nigeria, (Oja Ita F.-ii) ...

_ Adedun Chemist

OGBENI ERUKOBOLiO Osewe Yoruba i pe ni "Pepper Soup”

dasi ki nto by sita.

ni o i'u rp yi iwp ni mo le bere lowp re pe $e o ko ri otutu yi.

Otelemuye- oginmtin fe, n ig b atio jy wipe egbe pasero mi ni mo ti di- de lowuro yi, nko tile mp o h u u ti o njp o g i n nit i n mo tp yara de ibikan pa a §u gbpn kini e ti gbp mpa prp ida sily egbe ojowe Yoruba si ? S h o y i k a -Emi ati cle-

gbe mi osewe Yoruba kan ti falpwp a o si ri pc a da egby na silc ninu o s u yi lagbara oluwa

Otelymuyy -Ti y ba tele da egbe na si!e anfani nlanla ni yio je fuo r>mo Y"ruba.

Shoyi ku -B eni ppplppp anfani ni o wa nibe Ekini Awpn on o yoruba yio t i anfani ati ma a kp etie ij n e yoruba.

Otylemuye -mo kin , rp ti o wi yi lehin §e bi aw pn Ghana ati Ii dia ti i eta mu .i-d e .won

kikp ni yen ju e d e eledc Ip.

Shoyinka -Woyika lode on pppk pp pmp Yoruba jiidi haun ni o mp edc Yoruba ka ti a ti kp si di ise pehi

Otelemuy? O Ko purp Sho- , yin ka Yoruba turn ; cysi kan r,i n*Qn fi nbp ara

wpn larin sprp : Shoyinka -Eyi ni Yoruba

r.pe ni a m u l u m a la Yoruba tabi adampdi

» Yoruba.

Otylemuye i yi ko se gbp lati r i pe pmp Yoruba ko m p p so tabi pe ko nip ka Shoyinka Shoyinka- Kini anfar.i pmp

yoruba ti ko ino ede baba re fp!

Otylomuy?.- A ni ppplQpp ntiju lati m a asp Yoru ba td e abunibi wpn Shoyinka E ko purp ptely-

niuyt’ ppp sp Ovinbo jp "Opere” lu si pfisi kakiri, iwp yio ba wpn nibe repelp. , Anfani keji ti o tun wa ninu

idasily egbe yi ni pe, Opplppp awpn pm p yoruba

ni nwpn ni t pplp lati se orlsirisi iwe, §ugbpn ii nwpn ko ni owo Ip­

wp lati ft te jade fun ida egbe bayi stle nwpn yio e maa se iranlpwp lati ba iiu eaia bee tp jade fun lita

Otplcmuyy: A ni ppplp to . pe ju ti Alajp Sornolu Ip koko orp gan ni o sp.

Shoyinka: ' Ntpa ;se bayi awpn os re * a bi pgbp n, Ogunde, yio m a a ni ppu'ppp awpn iwe ti awpn omwe wa ba n$e lo .un i re rp.

Qtvli muyv: Bern, p ip re ko se, uigbati o ba va ti awa nu ii$ere sinu Si- tiirna. Ti a ba si bersjsi lo iwe ti awpn a$ewe wa se. ko ni legb? ni gbo- gbo agbaiye Shoyinka.- Wo iru iwe bi

Ogboju oJp ninu Igbo Iruumale,.

igjc ki nwen fiiru yyn sere | ninu Sioima” bawo ni o rope yio ti dun to? | OtyltmujC. Ere oloyii.mp- i.

mp ni yio j ■ O lotu -S aji.mps pp emi ati Sh- oyinP . i iy,n, a o ma J reti idasile egbe na. | O lotu:- Gbp bi Ogb-ni Sh­

oyinka ti wi yen, t. r pe a leri lejc ni. K a fi rere p..do o < u " *

(3)

THURSDAY AUGUST 21. 1964

Mo Kin Benson I.oliin

O lotu, J«,w<? g ta mi ni aye lati kin Oloyc T O S Benson /?hin

<?rv rq ti o so ninu iwe Irohin Im o/? ti pjp kejidlnlogun o$u yi, nipa f.e ki w<?n j?ki a bpw^ fun Ar? Orilc—ode yi Qm<j- we Nnamdi Azikiwe.

Oloye T. 0< S. Benson M inista Alam ojuto Eto Irohin Fun Apapp ijpba ll<? N aijiria Ati Igbakeji Olori Eg be AlaAru-

ko (N. C. N. C, Mo K i O k ve Benson l<hin Qrp re pelu impran mi yi fun gbogbo awpn ara ilu paapa awon Ooiwe irohin p j?ki a bpwp fun’ Olori \P3. ko dara latt ma fi pniti a pfc ni Baba fun gbogbo araiye, ti gbogbo awpn ile Ok ere si nbpwp ati Ola nla- nla fun fci o wa j? pe awa ni ao ma fi baba na wple, ira ey\ ko dara rara.

5 bpwp fun Qlpla Noamdi Azikuwe O di Qwp wa o.

O kare Oloye Benson, Emi ni, Falilatu Arpago

A N f? lie V k V Giga N i v*svsa

O lotu Inu mi yio dun pupp bi e ha le gba ni eye ninu iwe iro­

hin yio/ati kesi Ijpba Ipinlp lw p-O run pe ki nwpn jpwp ki wpn ko ile pkp giga fun awpn pmp ilu wa Qspsa ni ?kun lj?/m Abe Ijpba rere Ipinlp na lati /ete k j ile pkp giga si ilu Qsp- sa aiko ji ile ekp giga ni ilu wa o nj? wa ni ya N iton Qpplppp awpn pmp ilu w a tio ba jade iwe mefa ti awpn ?bi r? ko sini owo pupp 1 ati ran ip si ilu mi- ran kio lp kawe ni tori owo bpda ni oma le alarin kiri sugbpn ti aba ni ile ?kp gi^a ni ilu wa owo dip ni ao ma sao ti awpn pmp w« yio si ma Ip si ile p/cp loojump ko pe ao tun ma san owo ni ptp ejpwp pnyin Ijpba p tete ba wa fi eyi si ero A o ma retio.

Emi ni Jimph Adeyemi O/iwo Ospsaljpbu

Kyi Ya Mi

L ^ n u P i i p ^

Olotu, jpwQ gba mi n i aye ranpp ninu iwe Irohin Iroolp «atl sp p rp &ekere yi fun awpn o n la we we Irohin lm plp

O ya mi lpnu pupo nigbati mo ri prp Alapara Ibadan ka ninu Iw e lmplp Owuro t i nwon ntp ni Ibadan ti o si tun nsrbpnu $e fun pgbp Dpmo (N N D) ni ojo kpdognn <$u kejo odun yi

Mo wa bi ara mi )erc bayi pe tabj ogbpni w a Alapara Ibadan ti wo pgbp Dpmo ni? nse ni oro na fa ariyanj/yan larin emi pplu prp mi

Ti Alapara Ibadan ba wp gb? Demp nitori o»o, njp Yoru- ha ha le ronn bayt? Njp nwpn yio tete jpki Oloye Awolpwp jade ni pgba pwpntia fi si k akia.

Ogunde sp wipe ki Yoruba ro- nu, sugbpn kaka ki eweagbpn dp, nja lo nie koko, Njp ti oba ri ba yi, awa le da pri fun awpn /i ojp ri ek $i Awolowp nitori owo bi Nitoripe prp Qlprun sp pe ki a ma $<* da ni lpjo ki nwpn ma ba da wa lejp ati pe csuwpn ti a ba fi wpn fun plomiran ni nwpn ofi Wpn fun wa.

Yoruba ko ronu rara yio si j?

ohun ti yio fa abnmo wa ba wa l?hin p!a nigbati nwon ba to ipm Ip wa fuu ipinlp wa fuo ipinlp rnlran ti awa na si nwo nitori owo pmp Yornba* odi pwp yio o. bi owe bi owe ni alu ilu ogidigbo $ni t! aba gbpn ni yic jo Abp prp ni anso fun pmpluwabi.

ki iyoku ye nyin

Mo b? alapara Ibadan wa ha lati tete so ero re fun araiye gbp o Olotu, mo dupp fun aye t i p gbu mi, ajinde ara yio ma j p o

Emi ni, Kudira/u Sanyaolu,

1 BA DAW.

lganinu.se Pp ui Idiarafca

Olotu jpwQ gbami la ti kesi Ijpba lbilp Mush/n fun amojuto Idi- araba nipa iwa arufin ti o wa ni ibe lasiko yi

Abp an»pn Qlppa 1 a/i mojuto agbegbe yi nitoripe awpn igan- muse ati awpn orisirisi iwa ti ko dura ni nwpn r,hu nibp ppplppp si nro wipe awa Hausa ti awa ni b? ni a nhu iru iwa buburu yi Nitor na afc ki ij ba ibi/e Mu- sh*n tete mura si orp yi, ki nwpn si gbogun ti nwpn oDiwa buburu ti owa nlbp ki awa h ngbe idi- araba le ni ifpkanbalp

Olotu mo dube popp fun aye ti pgbami ko ni rp yin

I mi ni Maltam Kulode ldi-A raba

IROHIN 1MQLE OJU EWE KgTA (3) MAF1 OWO R g “ O FO ” MQ NIPA R tR A AWQN KOBIRQBI TQ N IK I N ITO RIPE uW O V/QN RQJ ARA R E LO NSE IY£N D A JU O B ER E OJULO A O H U N H A U N AYONRAN TQ N IK I TI WON N PLNI

“MINOPIIOS-TONIK! ’

Aworan ?gb? yi fi han q gbangba bi ^da eni ti ri laisi "E R A N A R A ” atlpe ojulowo tpniki to le ?e 19? ribiribi ni ara, i?Qri ara ninu eguogua gfgfbi awo­

ran yi to fi han (J, M IN O - PHOS Tpniki a m& ?jvs fa ti turfsi ara, papa ti e ia ba nru siogurodo tabi f in wa- h ila ije ?ise aiko nri oruo sun daradara to, beni o si darajulij pelu bi ara enia ba n be 11a nigba’.ugba ta­

bi lehiu aisan t»bi amodi bi igbona, iba pp ijupgnju abi a a wiwo enia nigbaku gba,

Ati fun i$<?o a lokun ati egungun ara ti o ba dabi ?nit pe omurp tabi ti ko la gbara to. $a dan igo kan egbogi tpniki yi wo iwp yio Bi ma robin r? fun gbogbo enia ppiu. Bere ni §pbu aw on:-

WATERLOO (S H u P ) M ED IC IN E STORES 8, PALM CHUCH STREET LAGOS

P, O, BOX 333

A w ^ n C>ja A j ^ b i d a i i

Iwe ilana Ifa lyanrin tit?. Etutu $iee Iwosan ati egbogi aj"bidan ti o ba ni iwe yi Ipwp, abiku koni ypp lpnu mp oso ati hj: ko ni lagbara lori rp, owo paapa ko ni wpn ui ohunkohun toba si dawp rele ni yio ja si rere awpn baba awon ti o gbowo gba asp lpwp enia ko ni ri gba mp

lye owo rp 20/-

Iwe egbogi ajpbidan Agbabietu awpn Ogun Ajpbidan ti 0 wa ninu iwe yi ko $e sp a fi ti o ba raa, ti o ba ni iwe yi Ipwo §apa arun ni o ko ni le wo ko si ni ijaiya pe arun tabi Amodi kan le pa p lye owo 25/—

Turari Fyb u A j?- 0 ba nfin turari yi ba a ti $e sore re Ajp ati abatpnijp ko ni foju si 0 lara ohun kohun ti o ba si diw ple rere ni yio maa ja si, iwp kp ni mp aita pja agbaoa ko si ni wp igba rp idabobo s i w a fun iwp ati awpn pbi rp.

Pangolo kan I0/6d

Kekere 2/6d

I-ve Gbedegbpyp Hausa 3/

1 tump Jospfu Alala 5/-

ltum p Ami Ara 3/-

Eewo ilp Yoruba ati Etutu 4/6d

Afpfjp Ispdalp Yoruba ati Psalm Ajpbidan 3/6 ati aybara Psalm egun l o r i awpn Ajp pplu

Ara 30/-

Tailos Measurement w^rks 2/- 6d

Iwe L ri iyege Ikp?e (Certificate of Appreuticeship)5/-

eyp kan 12/- 6d mpta

Iwe Adehun larin Onile ati mehaya Tenants (Agr.ment

Form ) 10/- 6d meji

Iwe Asofofo Aleio (Visitors,not Book) 2/-6d

Iwe Alagbafp (Laundry Book) 5/-6d

Kadi ifisprp sinu redio Ipfe 2d

Iwe Egbogi Ajebidan fun itaja ati Isegun Aje 16/-

iPEJU W B ILE l$E WA

Wp Bpsi ti o nip si Lawanson ni Yaba 3d perc bi, ti o ba spkalp ni Lawanson. bers Ito Hirp. Ti o ba de Ilu Itirp bere ibiti nwpn ti npa rnalu, tin ibp ti ite itawe wa wa Ti o ba fp li owo fans? fun pia rira adirpsi mi myi:—

J,

0

. Shoyinka c/o Postal Aaent,' 1, Isiba Street

Itirp Via,

(4)

THURSDAY AUGUST 21. 1964 TftOHIN IMQLE OJU EWE KgSfN (4)

\ ii h ii Balognu Pgbeyawo

CKEVA:—

Ojo nla ni pjp igbeyawo Ogbpni Muhatnmed Nubu Balogun je n n u igbesi aiye re ngbati o bp fila Appn Slip ti o di eniti o di oniyawo ni pjp Abamgta ti i»e pjp bini o$u yi ni Okeyi ipiolp Ariwa ile Naijiria, k0 si to afojuba ni pjp nla na nigbati gbogbo ilu Oke- ya fi fun ebi ati prp fun awpn alabaspyp igbeyawo na nigbati o gbe otnidan M uniratu Alabi arpwa Obm- rio ni iyawo ti gbogbo wpn si wa ni muku'urnuRelp ni pjp igbeyawo na.

Nigbati eye igbeyawo na ti nku l i pjp medoguo ni pkp iyawo na ti oniura ti o si ti npa ile mp ati papa ti gbogbo awpn enia ti pgbeni Brlogun fi i ie pe lati, ilu okere ti rde si ilu Okeya nigbati eye igbeyawo na ku pjp meta ati awpn egbe kan lati ilu Eko eyiti pkp iyawo n a je p k a n ninu pmp egbe Awpn egbe na si yan enia pataki meta ninu awpn pmp egbe na lati Ip se asoju wpn nibi eye igbeyawo ua ninu awpn enia na ni pgbe­

ni R.A Dumoye ogbeni Sa- idu Giwa Bale ati '« ckubu Mu tairu

Qpplppo awpn enia jan- kan jaokan lo wa sibi igbe­

yawo na lati llprin, Offa, OroEsie Uke-cdo ati pe awpn enia ti wa lati Igbaja lo si pp j.s nibi eye igbeya­

wo na.

Ni o w trp kutu ni Isaiah Qdedina pelu awpn pre re ti de lati Higher Tescher Traning College Igbajo Bakana Da ni Memudu Balogun ti de lati Jos.

L?hia igbati nwpn se iyawo na tan Ipna ti esin Islam ni cie Aladun wa

$plp ni owo Irple. Elcre pjp oa ni '-ROCK. MAM- BO ORCHESTRA” ti ow«

lati Qffa

Ni nkan bi agogo my fa ni ere oa bet? Laisi idu

ro nwpn yan arakunrin la - ti ilc i« e giga Igbaja gegp- bi alaga pjp na, nwpn si fi Eilioa Ayp, pmp Okeya ti o wa latiKABBA se ispgbe re, Lehin eyi ni alaga sp pro isiti ati didun re. Nigba­

ti a pari oyi ni alaga ojp na ba §i ijo. Ki Oluwa se iyawo ni abiyamp. Amin.

BERE EGBOG1 Aworan egbeyi fihan gb n gba ibiti jed'jpdi re ba wa ara re si nyp p lenu nigba gbogbo lire ni a n n e

“omusu tib i iho idi en a ibiti a m i be §e igbyns?

Arun jedijedi je pkau ninu amodi ti o burn ni piG ki fun pu jn rm ti o si |agbara pupp la i pe iwosan r p patapata

Opplppp egbogi ni nwpn nta kakiri ode nisisivi ti nwpn tna a polowo w p n un iwosan re ?agbpn boy.i la le ri mewa nin ■ awpn ogun m o le §e iwosan aru

YK 1BAWQ BE WO

Ohun ti o dara pupp ni ki enia mp ohun ti yio sele fun li pjp kan, Ditori, pni aigbpn pa lo pp, eni iku pa ko to nkan bi enia ba mp iwa oi bihu, odaju pe ko ni ko aba- mp, Afi pgbpn plpgbpn se pgbpn lo nje plpgbpn, Etna ka irawp nyin, ki e ie mp iru i» a ti o ye ki e hu.

AQUARIUS Jan 2 2 -Feb 2 0 :- Ire yio je tire loni Ipna gbogbo, la oju re silp loot ki o a legba ara re ile kuro ninu ewu ijamba

PISCES Feb- 21 Mar 20 -ohun ti o dara ni wipa ki o wa prp kan Ip, eniti o ti de pdp re ti pe k i o ma wa lp, yio fun p ni prp iakaye aijedede pkan r? le fa amodi wa fun o citorina ki o tpju o rare.

ARIES Mar 2t-A pnl 20- Ero ti iwe ni Ipkan loni ko ni ba ti el°mira mu ma$e agidi taku wipe e o tire tabi auiyan tire to daraiu.

TA U RUS-A pril 21 May 20 0 an ninu ohun ti o da o lamu ni o le yanju kedere sugbpn aora nipa ohun ti o fi pkan ra Awpn pre ti nfe si yio ma Ie p tpkantekan.

GEM INI (May 21-June 21) La oju re silp fun aye rere kan ti yio si si*? fun o se bi okunrin ki o si fi ban wipe iwp le se is? na, Ayp ati idunu yio kun inu pkan re ni ale oni.

CANCfcR (June 22 July 22) Amodi ara kan le sele si p loni, nitorina nse ni ki o tpju ara re ki pjp oni ba ie milijo fun p

LEO (July 24-Aug 22) §pra nipa erokero pkan re, iru eyiti o ma nsaba ro ninu okao, $e pelepele ki o ma ba fi se jamba fun ara re, Ogbeni on re ni iwp yio ma fi eru ika pale-

VIRGO (Aug 23 Sept 23) Ire m gbogbo pjp oni yio je fun p, mase lo egbogi kan lo i jeki eleda re $'?e fun p

bi are ba n u P loni r$e ni ki o $e pelepele LIBRA(S pt22- ct23)Ogbpn ori re yio peye pkan re yio si bale pelu ire loni. Sugbpn ohun kan ti oti gbero lati se ni iwp yio run yi pada sora nitor abamp.

SC0RPlO(Oci24 Nov22)Mase sba impran t o lewu kpk *, ki os: fjora loni bio ba fe rinrir n aj.', nitori ewu jamba mbe fun o loni,

S O G lf f a R!US(Nov23-Dec21)Bi o ba lo ja fara luni 'amba afia sele si o sugbpn irole ym san die ui“ s?k- iyesi aw< n iwa ti o nhun ki a si mp mpe prpkprp ti o nse CAPRICORNlDec22 J.m21)Yio d»ra fun p bi o ba le sonu lori irohiu kan ti iwp yio pbp loni |gba rere yio de fuo p ara ie yio si ya iwp yio si ri ere nla je loni’

yi daradara, Awpn el°miran lero wipe boya bi wpn ba Ip si ile iwosan lati lp ke eyiti obu nyp jade la t omusu ku nipa be awpn o bp lpwo re patapata.

$ugb n awa ko ro be rara lehin pdun die iypnu re yio si tun here bakana Oris'risi Jedijedi ni o wa, Ekini ti o here nipa aiko ma se igbpse dede tabilojojum p telomiran nipa tjako ni (jukanna pupp ojojump fabi gigun k'eke olegere (Basikulu) pupp elomiran pwe eran Suga oniruru ohun adidun pupQ, pupoju nigba kugba Jedijedi di orisirisi ni o wa, ewo ni tire? Bi o nyp jade ninu omusu tabi ti o ba nmu eje wa lehin igbonse tabi ti o ba nyp ti c ba se igbpnse tan ni tabi ti nrin p ninu omusu m cyikeyi ti o ba ie here egbogi CYCLOVEN ti awpn Oyinbu Jamani ses? wa idi re k'O si daowo tisi i me a daju wipe iwp yio bp lpwp Jedijedi p ata­

pata alafia lo de o ekeji re ko si ninu gbogbo egbogi atata eigboro Naijiria bore ni :

“ NIGERIAN M ED ICEN E STORED lin u b u Square Lago 4, Adedun Chemist 14, Workeman Street, Yah a

mKDK

E g b ? Ik i mIo A i y e Eyi ni lati kede fun gbogbo pmp Egbe Jmple Aiye Okunrin ati Obinriri wipe C a l e n d e r ti pdun 1965, eyi ti o ie ti egbe yio jade laipe yi.

Ohun pa »ki ti o se idaduro fun un ni aworan gbogbo gboo (Qmp Egbe) ti yio han n'nu Calender na. ninu ,p. de ti o ip ja ni l y e fpto ti wa let' ya gbogbo wa, suebon tpylopo ti ko wa ni pjp na ko je ki a le ya fpto na.

Nitori idi eyi ti o ba di pjv Sunday ni 23/8/64 a o ya fpto nr lagbara Oluwa ni nkan hi agi go meta psan ii a o ya . Qmp e be ti ko ba wa tabiti o ba pe lehin, kn ni han ninu aworan na a ko si ni ya foto na ri emeii- Nin ri idi eyi ki <• tele de ipade ni ogogo meti (ni 16, Baitiighose St Lagos.) nito- ripe awpn atunse die wa k' » to ya foto.

“ UAFARA LEWU O”

R ' I I MAN DUil/OYE Alaga Egbe Implg Aiye.

(5)

F R T f tW A UGUST 21, 1964 IROHIN IM QLg OJU EWE K A R U N (S')

BEKE EGBOGI

Aya Di Olopa no lie

Lati Owg H A D JI Y, A. D1SU Asif? pupg ni fun obinrin rcre lati 1q fg gkunrin ja n - duku, gkg opurg ati gkgonisgndisgndi; Ori buburu si ni o jg fun obinrin na. Bi gkunrin ire ba si Ig fg obinrin buburu, asifg ni o je fun gkunrin na.

B ik an a ni, ori buburu si ni o nje f u n u n . Oluwa rcre, a fi gla He be e, a fi Akehinde An.<b M uiiam- med, ki tkg ati gla ma a b i a titi I ilat, be B, ma*

$e jgki a si gkg ni, ma si

$e jeki a si aya m o. Amin.

Oko buburu a ma si aya ire lgna. Aya buburu a s i ma a si vkg ire lgna, fun apery, baba dudu omiran kan tube !ssik< kan. Oni- sgndisgndi cnia ni, onijibiti m, opurg pupg ni. Eniti o ba si purg mg, Qlgrur. ni Oba alaabo ti o le koo yg Afinju atgrgjg si ni. Baba

“ rigirag si ni o je, Baba na si fg aya doogo adelebg kan ti o $e enia ti o si fe ran lati maa sg otitg, o si feran lati maa h u iwa ire pelu.

Nwgn bi aya re ni idi baba ati i y a dada. Iran Oba ati ojoye kan ni awgn obi re na. §ugbgn oni idi igi kan ti o nda ileru n i gkg na. O kuroro si m o je

A. m a buram uram u b i kininun lori irg. Bi o ba si pe iyawo re lati jeri eke, bi iygn ko ba si se bee, yio beresi kar.ra, mg. Nigbati obinrin na ko si fe ki maa ko ak o sa, os i beresi jeri eke lati le tg g lgrun. Karii- kafg, obinrin na si di opu ro ati eke. O si di glgpa- nu ile, lati 1 e tg g k g rg lgrun.

Akiyesi

Si Gbogbo Enyir, Onkawe Irohin Jmple ni Ahenkuta ati agbegbe rg Ti o ba fe r.i Irohin lm glc ti o nj de ni Ojojumo Ig ra Igwg Asoju wa Omidan Owi k o y a .

O w o Bookshop S hrpon Ago - Oko R >ad

ABEOKUTA Ti Enikgni ni Irohin luiglg. kgbg mrji pere.

44v t:n M !Z Y X ,?

Ojulowo egbogi atam atase }i o daju fun iparun awgn

“ A R ON ” buruku gbogbo lara enia, papa tab* ni pataki fun ARON laiaolatan tabi argn kinisa tioma mu idiwg wa fun ggbagbeje obinrin lati loyun tabi ti o ma nba oyun jg lara Obinrin.

Besi ni egbogi y idara fun gbogbo gniti aran agbedu Igba-aya, gua gfun, sisg le- hin bi ake tabi aran oju p;lu Meji irufe egbogi urgn yi kosi r i gbogbo ilg Nai- geria jakejo i$e re si daju

AKIYESI PATAKI

Ri daju wipe oti re eekgno gwg ati esg re daradara ki oto lo egbogi aaan yi gggebi awon Jaman iti o$e ti juwe lilo rgo F un aabalagba n i- kan ni owa fun. Bere orisi- risi egbogi argn fun gmgde pelu wgn nbe fun tita ni

§gbu awgn:- W atedoo Medicine Store;

8, Palmchurch Stree Lagos P O Box 333 Phone; 22878 N aje ria (Oja Ita Faji) A DEDU N CHEM ISTS.

4, W orkem an Street Y abaJ,Phone 44166 I$g Olodumare Dispensary Okebgla Ibadan.

OLUSHI SOCIALISTS

P R E S E N T S

FIRST ANNIVERSARY DANCE

at Foresters Centen«ry Hall

22, OduDlami Street Lagos

ON F R ID A Y , 21st AUGUST, 1964, AT 6 p, m. till dawn MUSIC B Y

N e w T im e E n terp rises B ashy & H is Young’ S ta rs

O r c h e str a

Ladies and Gents, dont be told of what happen ?t Foresters on that 21st August 1964, bow Bashy 1 wi'l give you n uny latest hits at d h w New Time will give you many hits o f Roy Chicago, Eddie 0<onta, I. K. Dairo & Broadway Dance Band Arom Ghana Bashy is asuring you to bri> g .dong your Terntoeene or M entholatum to rub your body after closing.

COME TH ER E IN TIM E TO AVOID RU SH IN G

Bar Bar Inexhaustible

T ick ets 3 s F lat

Tickets obtainable at 16, B mgbose Street Lagos Irohin Imole Office) and at 3, Olushi Street Lagos O tg ki gkunrin rere fg

obinrin ire, ki obinrin ire si fe gkunrin ire Ki gmg obinrin ti obi rg jg oni mi- mg fe gmg gkunrin ti o bi re je onimimg K i gmg gkunrin Dokita Elaias fg gmg obin in Dokita Coker Ape.-rc ni eleyi o Ika ti o ba wg imu ni a gbgdg kiwg iho imu

m

0

m

' % _ ... j & f c - Aihaji Y, A, bisu Okg ire ati aya irs yio so es j ire Okg buburu ati Bya buburu y>n s0 es0 buburu bakanoa.

v

(6)

m n l F ORE *IV K , T E M OhUU BO LAWA M„ 77*. FRIDAY, AUGUST 21 1964 (2D)

Oloye Rcnson kllQ Fan AwQn Olfilis !w c Irohin

EKO Alakosi eto 1 robin fuu upapg Ijgba il<? Naijiria ati l#ba k$ta Olorl egbe AlaKulcp Oloye T. O. g Henson ki!p fun nwpn Oiotil Iwe Irohin lort Qrp Olotu*' ti mypn fi ma a niplu aw^n eoia.

ki awpn olotu iwe irohin fi ra* kp/n aw.

pn enia hi ko s$ pe ki nwpu fi ma tp awpn enia soju pna fo tp ati cyi to ye ati pe li nwvn £a ri nkan ti ko tpna lati

fiye a^baiyp

Ni ikehin prp r? Oloye Benson kesi igbitno awon egbe onirohin Uti ri pe nw pi lo ipo won rere lati ri pe nwgo ko fi o^O ninu awpn iwe irohin ma

plu enia ati p e Vi awpn v‘g b f onirohin wa t e t e r if i iwa a ^ o u c |t/n /«e irohin lati tete le, dekun iwa oa.

Oloye Benson sprg le pro Olotu ti iwe Irohin kan ti a npe ni Daily Tele­

graph** eyiti O/oyc Beason so pe n«en sp ninu prp asprpm.igbesi eyiti o sp p* » ko j$ ohun to tpn* lati ma kplu enia lori prp inn pro na.

O loye Benson sp pe li j? pe avpo Olotu iwe Irohin tete dopin prp Olotu wpn eyiti nwpn fi okplu enia pe ?rp Asprpmagbcsi .ki yio da a Ju re lati ma sp prp Olotu ninu pro Asprprnagbcsi Oloye Benson sp pc prp olotu ko m“

ly a a fin A w olow o Sty P e

Akintola Lo Ba Ise Ilpsiwaju Awolowo Je Ni iwo Orun

IJ E R O - E K 1 T 1 N i ojo Ru ti ise pjp kpkandinlogun o?u yi ni Oloye iyaafin H. 1. D. Awolpwp sp nibi ipade kan ti o ba awpn enia ilu Ijero Ekiti larin eto irin ajo re si ekun Ekiti pe awpn ise ti o le mu ilpsiwaju h in le Iwo Orun Naijiria lase co ti Oloye Obafemi Awolpwp wa ge- g?bi Alakoso Ijoba ipinle na pe lehin ti Oloye Awolpwp fi aye na sile fun Oloye S. L. Akintpla gegebi Alakoso ipinl? na lo ba ipinle na je.

N igbati Iyaafin Awo- lowp sp eyi fun awpn enia ilu Ijero Ekiti ni nwpn ba fa igbe ta pe, Awo! Awol!

Awo!!! lyaafin Oloye Awo­

lpwp si tun fi ye awpn enia na p c n i g b a t i Oloye S. L. Akintpla gba ipo gegebi Alakoso ipinle Iwo Orun Naijiria ni eto aje, alafia ilpsiwaju ati ile- ra ipinle na parun patapa- ta lati odun I960

Oloye iya a fin Awolpwp fi ye awpn enia na pe ohun to le mu ki Ijpba rere wp ipinle na ni pe ki awpn enia ipinle na je ki oloye Akintpla ati awpn elegbe re kuna laseko idi- bo to nbo yi ati pe nkan to le gba ipinle Iwo Orun sile Ipwo airi je ati airi mu niyen.

Lehin ti Oloye iyaafin Awo

lpwp ka awon ise rere tiO lo ye Awolpwp se si ipinle na laseko tire. Iya afin Awo- lp se si ipinle 11a lasiko tire, iya afin Awo pwp sp pe egbe Afenifere nikan lo le gbe ogo ipinle na yp Nigbati iyaafih Oloye Awolpwp tun n;i ye ttwon enia Ijero Ekiti lori g;gebi nwpn sc da egbe Demo N.

N. D P. sile iyaafin Oloye H. I. D. Awolpwp sp pc egbe ti nwpn ft iwa odale da sile lati le h ba emi isp- kan ati ilpsiwaju aw pnpm o ile Yoruba je ni.

Oloye iyaafin Awolpwp un fi ye awpn enia ilu n ap e ki nwpn fi tokantokan fara pmo egbe Afenifere le gba gbogbo awpn nkan to ti s,egbe paSa.

Gloye iyaahn Awolpwp tun se apejiwepro ti iyaafin

E adereraA kintpla sp lori owo ti o so pe awpn ;ghe Afenifere '1 painp si ile ifo- opam p kan ni ile Geesi iya afin Awolpwp so pe iro parapata ni prp ti iyaa in A kintpla sp ati pe pro iko- mo ni prp re p o a p a ta ati lati .i ba egbe Afenifere je.

Nigbati Oloye iya afin Awolpwp de Ikoro Ekiti ni nwpn n oye da a lola gegebi „Eye Abiye” ti ilu Ikoro Eked. Eniti o ft iya afin Awolpwp joye na ni Iya afin Tinuade A i n a

p 1 an ninu awpn O l o y e O binrin ni ilu na nwpn si ti fun iya afin Awplpwp ni ilek? iyun fin ti amin oye ti o j? na.

Ni Ado - Ekiti ni irohin ti de p w p wa pe i y a afin Oloye Faderera Akin­

tpla ati awpn pl?gb? r?

pe awpn O binrin plpja si here si sp okuta lu wpn nigbati nwpn de ilu Ado- Ekiti. Awpn O binrin na ti mura pelu okuta ati ada lati g b o g u n ti iya afin A kintpla ati awpn enia rp.

LATI O JU EWE KINI Otobo yio wa gegebi olori pgbe M. D. F (Mid West Front).

Irohin na tun fi ye wa label? pe egbe Olomi N. P.

C. lodi si eto Ijpba apapo fun awpn omo egbe Oseiu lake jado ile Naijiria lai ko si alatako kankan ni­

nu Ijpba ile Naijiria ati pe awpn omo egbe N. P.

C. sp pe pe yio je ohun yio mu r gbc wpn kuna

ori eto wpn ti nwpn tp se sile. Awpn omp egba N. D C. so ninu ipade ni pe nwpn ni lati ma asan owo ooya fun ilu to je pe awpn ti nri en t mpto wa jade gpgebi nkan to jepe o ba eto lo.

Irohin fi ye wa lati pwp Oniwe Irohin ni Ka- duna pe ko ti si Iron in kan to je pe awpn egbe na si ti gbee jade lori eto

udehun ti awpn pmp egbe na se nibi ipad wn na o to nlo

D okita Obi L«> Ba Egbv> P. G.

Se Ipade

Olori egbe Dynamic Party ati Olukp ni ile ekp gigati Univfasiti Ibadan tele Dokita Chike Obi n irohin tun fi ye wa pe o Ip si K aduna ipinle Ariwa ile N aijiria lati lp ba wpn egbe Olomi N. P. C. ati awpn alabajepp wpn se ipade nibi li awpn Olori egbe na ti nse ipade lati pjp Aku ti ise pjokejidinlogun osu yi ni il O lori egbe Olomi Alhaji Ahmadu Bello Sardauna ilu Sokoto.

Irohin fi ye wa pe Doki­

ta Obi si nip lati lp se eto gegebi egbe re yio so papp mp egb; Olomi laseko idi bo si ile igbimp asofin ti apapp Ijpba ile Naijiria.

Irohin na tun fi ye wa pe nwon ti nreti Dokita Obi ni K aduna nigbati ipade na ti be re.

Ni ojo kok a n d i n l o - gbo o:ju tolp ni Dokita Obi so ninu pro re ni Eko pe ajumpsepo egbe on a t i egbe Afenifere ti ba je lo­

ri pe awpn egbe Afenifere se adehun lati papp m p egbe Alakuko.

Dokita Chike Obi t u n sc alaye ninu prp re lasi­

ko na pe on to mu on sp pe egbe on ko ni ba

egbe Qlppe se pp ni pe awpn Afenifere kuna la ti sp fun egbe on ki nwpn to dapp mp egb? A laku-- kp ( N O N Cj.

Ninu ipade ti D o k i t a Obi y i o $e ni a w p n eto lori ajump^epp egbe re pelu N P C si je ohun to wa ni asiri ati pe awpn egbe na co ti sp nkankan si ode lori ipade na.

Gegebi irohin to de pwp wa pe aw pn ?gb? na pin ara wpn si pna m trin lati lp jinroro lori ajurno?- epp egbe wpn ati pe awpn egbe na to pin ara wpn si pna merin yio jijp papp lati le jinroro lori eto adehun ti nwpn se ninu awpn ipade ti nwpn pin ara wpn si.

Printed and Published by M odupe Prin ing Press 16, Bamgbose Street Lagos Phone 21985 Editor: TUNJT ADEOSUN 4.), Campbell Street Laffost ? ’ /&/64

Referencias

Documento similar

bpna lun ni awpn a ia ilu ologbc na nwa nki praploku na pplu, ilc ko gba awpn enia tobpti nwpn tun fi ntpro awpn ile ti o sun m p tosi ilc wpn pplu.. Orisirisi awpn