• No se han encontrado resultados

Irohin Imọlẹ

N/A
N/A
Protected

Academic year: 2023

Share "Irohin Imọlẹ"

Copied!
4
0
0

Texto completo

(1)

E MA KA IROHIN IMOLE

K1 E SI MA POLO- WO Q J\ YIN SINU RE. O kun fun iro- hin aladun, o si nkp enia ni ekp dada. O nfun enia ni oye.

imnaciRiiatamaaiasKaa

AKIYESI

li ma ka iwo Itohin tragic, nigtugbogbo niloripc iwn aladun nuia kan yio betf nifliijjn? la ip f yi. Blcini ni ilan Kogbon ninu «vi, oriro omo a b f Kjwp iya re (apaki- oi) ilan igb-si aiye awon ayaba ali awpn plMbyn aiye ( apakeji) ilan igbesi aiye

WEDNESDAY 8, JANUARY - JANUARY. 14, 195g KQBQ KAN

E ko Nomba Nitori Arun So p o n a

A run Sopona je eyiti o niberu gidigidi kakiri agbaiye. Paapa, lati daruko re jeeru jeje larin iran yoruba. Iberu yi !o jeki awon yoruba soo di Orisaakunlebo, ka­

kiri ile Naijiria ni a ngbe mo arun yi, oruko ototo ni a si

Hausa npe ni Adana, A- won lbo npee ni Kitipn, sugbon oruko merin ni a- wcm Yoruba fi npee (1) Ol- ode (2) Ilegbona, (3) Qba, awpn oruko m?t?la nwpnyi j? eyiti a nfi tpwp-tpwp pc sugbon (4) sopona. nibikibi ti a ba li pe oruko yi, afara ko si, Hsu ni gbogbo awon enia to wa nib? yio tuka yanga l?s? kanna, ni toripc nwpn ro o si ipc ti afojudi Olori awpnOnisegun He­

ra (Medical of Health) ti sc ikede ni tori eyi wipe, (onuaaBiaiaumittcKiininnmnniai

fi npe.

ki olukuhiku enia jpwp ara r? lati kp nomba fun (Va­

ccination] ati awon ara ile r?-

Ko nse wipe arun na ti kuku b?r6. sugbon ako nfi oju ogun wa efon, bi arun na ba til? wo ilu yio ba wa ni mimura sil? de, ati pe lododun ni a ma ko nomba fun gbogo enia bayi ni ibe- r? odun, nitori na ki ?ni- kan mase taku wipe sebi mo ti ko nomba kan lesi, ni torina nko tun ni ko lp- dun ni mo eyi ko buru.

SHOYINKA TUN GBE DE

I we Adura fun Arisiki lati II? Miiirat 3/6d I we Adura Akansc 3/6d

Iwe liana Esin Ojis? nla Muhammad 7/6d Kurani Esumeta ti a tumo si Yoruba IO/6d Odu merindirilogun 10/6d

Iwe Aniyan ati Nofila Oru Osu Aw? 5/6d lwe Egbogi Ajebidsn 20/-

Itan Aladun 3/- Gbedegbeyp Hausa 3/- Ajiran Ilu Oku 3/-

kumo ala kikun ati Odu Ifa !2/6d lwe Owe Yoruba 3/6d

Psalmu ls?gun Ai? ati aiye l7/6d p?lu Turari Ipf?

Turari Itaja 10/6d Turari Eyonu Aje 10/6d

Ab?la Adura (Dragon Candle) fun Adura tete Da- mi lohun 15/-6d Fi owo rans? si :-

J O. SHOYINKA c/o Post Office Ebute Metta Tab:

8, Ojo Road (Oduabor?) Mushin,

Ko nomba fun gbogbo awon ebir?, ati omp titun ti o ba ti to omo osu meta Bi enia kan ba ti ko no­

mba l?kan, osi tun di ?hin odun m?ta ki o to ko omi- ran. Eniti o ba sakiyeai ?- nikan ti arun yi wa lara r?, ki ? tete so fun awon wole- wole.

Mahtmidu Dantata pe awon onigbese re lejo

Kano

A

gbp irobin lari ilu Kano wipe Alhadji Mahmudu omo Alasan Da-

uta'.a ologbe. ?niti awon plppa baseejp iarapa owo ayederu ti o se, ti nwon si kamo Ipwp, eyiti nwon ti torir? gbeju spwqn fun, wi­

pe, o kowe si Alikali, wipe awon enia ti o j? on ni gbese po ati pe, nwon le titori pgba ?won ti on wa ki won salo tabi ki nwon so pe nwon ko je on lowo.

Ogidinleje owo ti Alhaji na p?jo le iori to oke kan poun, Awon Minister meji je on ni £40 ati £50.

Okunrin kan ni kano ya

£750 ara Babure kan ya

£50, ara Jegge £40, ara An- duruman £1.100, Albadji Sore kan ya £8,350 Saro keji ya £700 ati 0P0 enia ti ko si aye lati daruko won

Awon Olopa beresi gbogun ti awon Omo ti o ti Sonu

NJE OMO RE WA NINU WON?

/-vlopa bpres gbogun nla ti awon omo dot* spou '-'a ti awon agbalagba alairikansekan, ni ilu Eko.

Nwon si mu to adpta awon ompde ati to okun agba­

lagba lii apa ibi sobu itaja. Ninu mqto awon plppa kan, awon pmpdc b?re si sokun ni orisirtsi ede li wpn nse ala- ye, tabi ti nwpn ns? pro ?o? jade. Nwon ko won lo si ile ibi ti anpe ni Lagos Centra! Police Station ni ita Tinubu ni ibiti Dwpn ti fi ika t? iwe.

Ki nwpn to bprf igbogun na, alagba alabojuto ti a- wpn olopu, Mr. P. D. Milne spfun oniwe irohio kan wipe ibi is? ohun nf? Ip la ti b?r? igbapp li gbogbo enia eyiti yio leju Iori a- wqn pmpde-kunrin ti nwpn nrin kakiri igboro ilu Eko ti nwpn nse bi ?ni wipe awpn alabojuto k?k? olo- gere aiinipto awon enia ti nwpn lp ra nkan niuu sobu Iori wipe nwpn yio fun wpn ni torp. (3d)

O wipe igbogun ti na

bpre nitori iwa kuwa ti aw"

on omo b?r?si hu si awpn oni k?ke ologere ati awpn oni mpto nitori awpn kp lati fuo nwpn ni ohun u nwpn nf?.

Qpplppp ni awpn onik?- ke ologero ni nwpn ma itba k?k? nwpn ni jijo, tabi ki nwpn tu agogo wpn kuro g?g? bi iya nitori nwon ko fun wpn ui iye owo ti nwpn gbpdp fun 3d, nibiti awpn onimpto ma ba rapto nwpn ni bibaj? tabi ki nwpn ti ji nkan lo ninu r?.

(2)

WEDNESDAY JANUARY ft iKOKlN iM.Oi OJU EWE KliJI

I M O L E

S S

ESIN PRO AV A: m m & E: OKt .Vli' i M •' A V e o n O R U L H O M S 4 OFl/Cf.

16, B im eh n se Sivvjci, I «:•;> . Telephone : a ! O S S London OHict—

Sunday Ayorindi :- 5, Hrvumnv, Sl<■it !..-n.l n FUN OWO "IROHIN IMOU;." QD.UN K AK EKO—SILE MRRIN KQBQ MERiN t < . llu -liran ni Naijria. ati Okc-otunSUe nu-fa Kpbvh

mefa 6/6d).

10 HUN SI 0 R0 ADE­

WARA BALOGUN

Olot-n.

v J.j\vp ;gba mi laye lad datum si pro pgbcm Adewara

|. U.i! ni* jade nino iwe Irohin trap!? oloyin mpmp I yV pjv k?dngbaa oau to fcoja.

Ak.,k« -i -si <?gb?ni t :A«R-':iia ipe. aivpa

vnikojiisai

ODUN Ml RAN

DE Tut

rjilliiii

iron pt>top '

*;-fco.!tyv'Hh

>^abats.t'r j i i pc p*r>a n o fi nfun

alii .#?#«!?

jlti&u-

A

wa oniwe irohin Imply ki yi:> X'p-'ippo pdun. W Oluiya ko se oduh iw iar-o fim wa. Awa g?gebi orukp w;t, a k- !•> !i diuh; i fun fun yin, bena n i’a ko ni. ri tim" ki | t fun yin,

Ki a io tp siwaju nihi! prp wa. a m jlu wa yi po wpn ktt ise, Oiv.ua fm n luku won. ki Oiuwa si tdh ma jliii won ni imp ku.:i imp wpn.

Bakanna a kesi gbogbo enyir, (i p ma unm <• i i mu larin ilu, li f m usp wire yi? ilu kn kan yin Ha ! Arakunrin ati Arabinnn, . .. o r u c I. . . .

1

? nfi ye olukuluku wipe pm-iy... 1 CDikpkan w.i. n o . . ' .. c>.. ry ya'.p, boya ti iwo ba so ero tire ii gboguc aiye b.> ...

j? imnlowp furl drill- eiie wa, joggpit t?i bo -q sita I.n si cniti o le mo obun ti o w.i 'V ■. u.

onikun enp ika, toto o bi owe.

Gbogbo wa lo te eli Bi prp Okiui ap.f-p k; N.;:i- jiria Alhadji Tafaw-. Halowa jv.gbati o nlci'wa kti -w,:

pdun titun ti a -y-r h'.-.r vi. o sp mini .iro ... .... A yi wipe aye wa run olukuluku lati gbe i" du . nipa kikp edun okan r? siftu iwe l/Shin t: .i ,jjacl.-.

Pupp ninu wa ni ko in? oiitin ti ,.v i: iw; vr.

bin jf. >i" si je ohun ayp fun «i

Naijiria, ppolppo wado nfi iwo Jrobin da agurk. a fe t yc yin wipe iwe Irohin jp ofettn .pataki, ti ko ha si iwe Irohin a ko le ri Imp!? hi iabesi .dv - wa iv.c Irohin kan, ainiye enia to nka, tu. a . d o

hm ti o si njade. ko ui eyi ti Ijobr. ki nfi oju ri.

Nitorma ni o fi jp wipe t i « ba ri ..hun ii Ijpba : apa ko ba s= dada, n (e kp sim. iwe Irohin, ;ba - ■ ni ede Oyinbo labi ti Yoruba. i i Oaju.iuin ri iyatp mnu ohun u o f? ki Ijoha

Nitorina pdun utun • nf a tun wo \i. a i s-iv.

■ominira ti a U -ope: ni pdun .inula.' ti dinku ni jSisiyi. ise gidi lo. si mbf oiwaju wa. -Jt- i - ? 0 si ni is? se, O si tp o si ye ki a.lyri: iao :K:- H pdun yi. ki a ma sppe asii.o si wa fut ...

asiko ko ma duro de ?mkeui. iv.cn ti *.i O.-,.

se la o sp nipa tire.

tu

bere i n rsv ati litjlai o.i ‘kwpn Raba-B tbs v'u ti jupa nlJrun pap.?,

! by a iv'hiUi iw? Aden am de ile aiye i.ip m Islam Uc- Eku Oro o', kio la>e mi.

wi Alufa tion<’ imip wipe ti wpn b« r.ke utoba ni awpn flq ilo riarukp ki ise »se, kh'A ki nmp, ati wipe fumi hit, bby.'i Jyr» tio <le lie aiye si.ni ow.< yp kia make utuba m-M awon llu ti p darokp ni, sugl'pn awpn oafcaJasiie tbnpa ni owe wi­

pe "Ao lesp wipe isbadigba

sia:

DIRECT YOUR PRINTING .SOBo, 1(

MODUPE PRINTING PRESS

16, Bamgbo-c Street.

la g O s . r h .-.V

?.oi to ba nfe irpsi- i r ;

' 1 stam Qlprun tit lati n sits . ni.

Two' Ogopni Adewara to m pgl pn to si oi iakaye 1c T i (p i 's

Ord i dnn L tobip

<>.pe Ijomu si 9tun -.tints?' kao abp Jlu- s ? . katf, nfc b- lakaye ju aivprj.Babu Ipmp.lp uiycn, tali

•o irt? iyc ibuso Qtun n ncu

C o * l;.,rau l ati ti Uu- dun n is.bi nw-.io ki kirun

■pnpp.

• ftug ypn-ctni. mp ■ daiuda-

;iu pe ok. ise pm? bibitkii .Oro r ra, -gbaro (iyp oko) m dw sc ni Ekim Oro.

'Osi tun, wowtt, mi-., sidigidi pe ki o wadi ni pdo cnili i.dfeji' V.vsi tie re tabi irm ti

<ni i-t. gbe ifepdpp,- ‘ • i la gbogbo .bi istiv- da'; i Tsu OfO ti sa tele ri wa ti Wpihaiv fl we pp fua hyi. lati ftiaiy kirun.

ini (jt m Ctt>; liun Jim**

-ati Ot u.'i, rikim ti ki iSv »- . m lim . kvip m«o

■lai’t o n kU na Ip k, Ambn

a',! na gari ni Iw: uj

>16it fi v«J IV'V Odr;f:i fiakigm

torn? na. nje ni igbati oba Oioro wa ni agbertm awpn fjoya wa nip si lb? Ippon tin prun, tabi wpn ki ilp?

Agb,run sini yi to ibusp meta abp si Qtun—Oro, ki ni won ko fi wa sope oj n ca piipo ki awpn tia yan

;oba ti awpn? Tabi bi ko faasi is?fc tio sete, wpn ko wa ni mat? titi di isinyi ni

■'Sugbon orii ti ko ba fi orp ip agba wo, kio to ma sp- rp. tfu ne jade lenu, omugp enia ni oyp kia kakun, owa nfi ye wii pc, Ebute-Mc-tta si Eko nkp, "Alefi efi we tida" bi (male ti pp ninu llu meji tio darukp yi, beni owa Wa ni Ijontu ati ni Iludun bi? ’foripe okoro pro Aiun$e ti owi wo rara ti off fo lp gbc fun oni Iwe Irohin,

Etui ni Y, Ade Buraimob

Qinp Qtun Oro Ninu Esin Adinni OLOTU,

Jpwp gba mi taiye lati fesi si prp Adewara Balo- gtin eyi ti o jade ninu iwe yin oloyin mpmp tise 15

/ nr-,

7

.

Modnpg pupo lowp Ade- aara tori alaye li ose ati nipa iberc ti obore Ipwp ini. Etui Alufa Durosinmi ki ise pmo ilu Oro, jugbon mo m? ilu Oro dada ati a- wpn pkn ilu Oro na, ni- gbati orp mi kan yio se iyawo moloto pse meji nib?

nipa ijorau ati iludun towi gbogbo re ni momp dada.

On pataki ti mo f? ki Mr. Adewara mp nipe pba kan lopa awpn ilu Oro na Pp,- an pe on ti Qlpruo sp mnu Alnkurani nipe ki a to Irri ilu ti wpn ni lati ma ki Uiuba iptpto, onilati te ibusp m?rin [4 miles] o- kere gbaa ni on ti owa ninu kuram iya-n t*, ki owa lpwo awpn ilu yi wo dada,—

Oshogboyilprin, Abpokuta Kano, ati bub? ti o jppe won gim ni ibusp merin tabi jub? Ip oha kan na ni wpn ti riki irun Jiraoh ati iruft pdun lies a, kosi tun Wadi w o dada m Mecca pna Kan Hi wpn ti ki iruo Utuba

(Wo oju ewe k?ta)

(3)

OMO IFE EKO SF ODUN

i i i | ,

E D D I

Trohio koto afojuba ni ere ajodun Qdun Eddi ti

*apapp gbogbo egb? 91119 Jfe. Eko .se ni irole ojo Abameta ti ise 0.19 kpkandinlogun osu December 1957 Ki o to to nkao bi agogo mprin irole, ni ese gbo- gbo prop lle-Iff Eko, Ebute-Met'a, Shoniblu. Osbodi, Idi-Oro. Musiiin a’.i Agege ti pe so.?p si "jude Oloye Dcnloye, ni 66. Kad.ira Street. Ebute-M?t|i.

WEDNESDAY JANUARY a 1938_____________ IROHIN 1MQLE

Ere ajodun yi here p?lu orin alc-jl? lati pwp alagba Limpta Gboreti, emu o j? Alakoso ati Amereya, pelu awpn SantmJri Qdp- mobirin, Qmp Ile-lle, lehin cyi ni lyj-nfin, Ogundiniu (Jya-fgbc pja Ararpmi) di- de. o f i oro iwuri ki gfo- gbo 01119 If*- to peju sinii apejo na wipe, nwyn ku ewu Qdun, ninu pro re, 0 se alaye gegebi o tisc je wi­

pe, lie.lie ni ipilf^e fl? Yo- ruba, o si pan oro r? lori wipe, inu on yio dun pupp ti pmp Ile-If? Eko, ba nba irepp yi Ip b?, ati wipe, ki nwgn si tun fi ohun wpn se okan fun igbega ati ilp- siwaju ilf Odudua na.

Lehin cyi ni, Oloye De- nloye, Qba-Qfin ti Ile-If?

ati Alakoso aipyp Qdun na ki gbogbo pmp Ile-If? to peju pese sibi ajpyo odun yi ku ewu pdun, o si se a- laye is? nla ti Mpremi sc si Ile-Ife, eyi to mu tp-mp- de ta'gba pmp lie-If?. li nse odun Eddi yi fun Iranti MQREMi na jpdodun-

Oloye Denloye, fi han agbanjo pmp Ilc-Ift pjp na wipe, inu on dun pupp ni- tori wipe, pmp lle-lf?, wpn ti nse pdun Eddi I "eko yi, sugbpn ti odun yi dun ptlpp. O se adura fun 11?

ile ati If? idalf, o sc adura fun prai glgun Qba Aden,- mi, o pari prp re loti oria

Qba a terere K'aiye Kabiesi O! Odudua Orisa idalf If?

Odudua, QlofinO Lehinna ni jije ati ffiimu here si kplu ura wpn, ti omkalukii bpr? si jo ijo ajo- spdi, ti gbogbo re be re si dun yungba titi di nkan bi agogo mewa ale.

Di? ti a ri aye darukp ninu awpn agbalagba omp Ile-If? to peju sibi ajodun na niyi:- Oloye Qba-Qfin Oloye Klgraprp, Rufai Gi- wa Awoycjp. S, Banir?, Phillip Arawumi, Gaibrel Adewumi, S. Showals, A- basi lgedi, S. Akinfala, Q- mp-Qba Adetunji Shijuade ati ppplppo gbajump lp‘k- unrin atilobmnn.

Bi Oluwa ba da ?mi gbo­

gbo wa si, laipe yi ni ?nyin Onkawe yio ri iru is? ti Mpremi se si Ue-If? ka eyi to mu ki pmp Ile-lfe maa fi pdun Eddi se Iranti r?

lpdp dun.

Enyin Onkawe, ? foju spna 0.

AROFO A

noyinlohun

IKU To! Ton To!!!

lku pjfgb? onikp

A gba’pa lpwp Akeran A de k'agbpji s’ado mu A de k’awo dogberi lku so’le a I a d u n Di ibi awonu Enyin era Eko 9 ko gbo- hun mi na Emi Anpyinlohiln-bi-pmp- ge I m a r o Mo gbp'ku R a n d l e Mo tu puru sekuo lku ko m'olowo lku ko motosi

lku akodu ya mi I?nu lku fe?in site 0 m’plesin Ip lku kp popij?

1 wun fkii yi nf? saiye da O sebi 0 ye mi na lku tun fo fpr? o wo Ic to Silva Ip O gbc jagun Ip loriye Silva adu-m.i-dan ape pm?

Afiwa p?s?

Onile oke yi nwun Q.'oro O nwun pmp otosi Enyin ara Eko E ko nwoye na Ejiwunmi tun gba waya lku mu jagun lo Si Paradise oke Torapde tagba re nfekun pe ’daro r? o o dp efigba Nwapa tun y?ri bps?

O I?ru ail? Ip Jagun rphin eitu lku kp mo ajelu Ko mp onile Ko mp cni rowo j? kuta Ko mp ?ni nf?fp jori O ma pp k?

Iyi inp ti nwi la Uni Mo simi mo dehin prp lku m? re sa pa baba mi lku ko gb’etutu Emi ku ti spbo tan Awa yi ku a ku ewu A ku ajaiye Kolukuluku ?a ma palp- mp ?run

lku mbp Iona K’a ma ku ’ku ina K’a ma ku 'ku omi K’a ma li gbese sprun pmp K’a i ppninda

A. A. AKINSOLA SOKU IYA RE

I

rohin ko to afojuba ni ti isinku iya Qgbpni wa A. A. Akinspla ti o ngbe 34, Qlpnpde Street, Yaba Estate se ni agbo-ile ?lf- gba ada ni Abpokuta, ?se awpn 6nia jankanjankan iati Eko ati pna jinjin pe sibp. Nse nt Gin npe Beer ransf, Ogurp ati Stout ko tile ribi duro si, amutakiti ni awpn alaba??ye pjp na nmu.

Odindi malu bpsa ni Qgl>?ni yi pa. Die ti aye wa fun wa lati darukp si- nu iwe yi ni awpn Qgbeui

OJU EWE KETA J. O. Fplarin, Idowu, J. S.

Blaize, Makanjupla, Soyo- ye, Jaiyepla ati Olumtde

Madam Akispla Laisi. Iya 0 1 o g b e yi j?

fgbpn fun iya Qgbpni wa J- O. Shovinka. Iya wa Atunwa prun rere o I

Afose Isedale Yoruba

A T I PS H L M U A1EBIOA N IWE YI WULO NI ONA PUPO I Ofo atsia (un Arisiti 2. Ofy aiata fun Madarikan.

3. O f, a [a ir luri (t»ja 4. Ofo li ki jrki ope ran enia 5- Psalmu Aj,bidan fun f yonu

6

. Psalmu tun OrireAje.

7. Psalmu fun ,ju tita

»• Psalmu Ajfbidan fun Mada- riluo

*). i’salm Ajebidan fun Idabobo l,w , Ajakalc arun.

irohin ko to afojuba ti o ba ni iwe yi lowo, o ju

Wura ati Fadaka lo.

EYO KAN 2/6 DOS INI 20/- Fi owo ran§? si POPULAR BOOKSHOP

c/o Post Office. Ebute- Mctta.

IDAHUN SI QRQ ADE- WARA BALOGUN

O b?r, lojii ewe Keji bi on ti mowi yi koba da p loju, ki o lp wadi wo ni pdo awpn toni mimp ti won ba sunmp ? dada.

Nipa ti ilu Eko ti o wi ati Ebutc Metta ti o se apejuwe wpn, o yatp pu- po si ti ilu Oro, agidi ni awpn ara Eko nlo, ki ise mimp ni,

Emi ni ALUPHA DUROSINMi

(4)

JANUARY 8 - JANUARY 14, U58 IROH1N IMQLh OJU EWE KhRlN (4).

AYUNORUNBO ATI PANPALASO 16

M

o ti ge ileri pc:lagbara Odua, ngo kp itan yi fun nvin rii kikmvninu psp yi, Oduiriarc k'o se odun yi ni odun rere fn o wa Asp o

to gun If si ibjti a n!f? Esu term musen, oni c ma knlp Esu bore Ipwp wpo o ni nj?

Avuorunbo Mn Ogiriwo Wple Is? Eti Nigbali won wo ibiti a- wpn Maleka ti n?e cli,- eriu ya.Ogiriwo to be g?p, ti itp fi nja li pnu rpmtoripe.cti miran fe bi eti erin. bniiran ri konko.omiransi na san- sansan bi eti eboro, ni ku- kuru wpn tie gbogbo ibiti awpn MaleKa ti ns'cbrisirisi pya ara, Ayunprunbp ni kekere io ri y?n, o siku ilu kan ti ac rekoja si, nib? ni awpn Maleka t i nt o awpn fya ara wpnvi pp, ko si pna lati gba wp ilu yi afi ibo Jltf, pkftu Ogiriwo nsn kiki-ki, o r,ro ninu ara rp

K

nje rise kp ni Ayunpnm- f f Ip ti on si pgbun ainireti ?

Ni kukuru Ayuuprunbp fi opa pwp rp lule kiki, ilekun aja He na si hoo, isejuaya wpn ti wple, pni- kan ko rap enikeji mp nib?

oiukuluku risise lo kita—

lokunrin ati lobinrin ni a- won Maleka nmp won jp, omiran kttru, omiran ri gb- pita. fatari omiran rii jan- konjsnkan, etc omiran dabi ti rakunroi, ni kukuru ori- sirisi ni swon Maleka nJa won—Ogiriwo worari tit oju rengbpn perepere A yunprunbp wa pc Ogiriwo o rii nisisiyi ni a w to nip siwaju Eleda prun ati aiye, tribe ni awpn ti a m p jp yi yio ti gba cemi (emi) nibe na si ni wonyio ti yau ohun ti wpn yio se bile aiye wpn iwp papa yio jiarada nibe lati gba Ue aiye Ip—Ojo meje gbako ni a 6 gba ni- i wo papa yio si tun. ipin re yan ppiu, NgO ma pada lo nisisiyi ti o ba di pjp marun loni ngo pada wa ba p Ogiriwo joko lpnu- pna. p pwoye.

Awpn Qre Ogiriwo. fgle E$u Gfgpbi m<i ti sp tele ri, Esu ti tan a won or? Ogiriwo jp, o s i ti gba iwe eri won-

\Vpn ko mp Lsoro kan rara nsc ni won njp, ti wpn 11- mu, ti wpn si nfi igbadun se.ayp yala larin awpn 9- btririn ti o ti inu obiniin wa

Won rilo rprere, sugbpn Esu. ko so ibiti o nko wpn Ip, nigbati ose ni wpubere lpwp r? |<e—rijp wo ni ao

pnyin ba mp eniti emi i?e bi? Wpn ni rara 0, o ni e farabalf, e. o mp mp mi ni­

sisiyi, lei a ni esu poora mp won loju, yiyp ti yio yo si won p rck'oja firi ni. o wp asp alarabafa, pupa ati du- du, pkan ninu wpn ni njp e ti pkunrin to wp asp du- du kpja ni? ekeji dahun pc lotilp pkunrin lo kpja su- gbgri asp pupa ni o wp Esu da ede- aiyede sarin wpn, ija de, wpn beresi lu ara wpn, wpn ffre lu ara wpn pa ki esu to wa yp si won o si la wpn, ni ija A K I.Y E S 1:- Lose to nbp;? 0 ma ka bi Esu ti se ba wpn spro, ati bi 0 ti se mu wpn wp ilu ti a npeni

“Ilu Awpn EEkp Olprun”

Itan na gun gan o, etete lp ra Irohin Imole nitoripc, Itan psp to nbp prebf ni, Olotu o ko ni lu Ofin ijpba o Asp.

O H IIN TI IRAWO YIN WI.

A r i « M a r c h I I d e A pril 10 Ti o ba If s* ihpvo kan ni ipari f i t j i . awpii d o If b?wo yio Irwo gb» o ju .bi o 'li ro If.

Sbra nipa w li o ba so nibf, niloripe aw?n rlon>ir«o ki i pe gba okan si ibiou, Taurus April I I de May 11

Nkan kekere kail le da ijfgbfn nla ni ibere fS? yi. Sugbpn ni igbali o ba awpn obun li o dijii yio yanju era won. iwo yio si ni asiko rere. Mura k i1 o wo ritan li o -b a jr dudu ni i>«c yi, niieripe o je awo oHre (too o- Gomini - May 23 d e June 21 Ohun rere wa luo awynli b light ninu oko nti awpn u o rije if si arin ilu. maje jjki tnjn pa 0 ti nipa ero re. awfn olo-

Isilolo yio j? ohun pataki oi Uo li o ba fe to oi ipari 911;.

Ohun- li yio jy fdun pauki fun 9 nibi awfn floiuiran li nhuwa ls*3i iwf : papa )io wiun,e. ' Leo:- July 23 de August 22

N«mba kcje yip lun wa si P<t» Ip nips? yi. Ko si nkan kan li o lo se nipa Vf. spra ni­

pa awoii onun ti yio ni ibfrv psi; yi.ti- 0 dabi enipc nfra- ha kejo Je oiorire fun p.

Virgo August 23 de Sopt. 22:

Osf anifcanse.ni eyi j5 iun sripri ti ko. ili pe ogbpo pdun.

li 0 l>a Ic sa agbara dip. yio

j j cro rere rati ma se is? lie ktn If, jiltoripe pse ti o mb<?

dabi eyhi yio le dic- Llbra 5ept. 23 de O ct. 22:

Mura lati fl bi o ti ri gan pamp fun nnikan ti o seje. de su- gbpn mise fi nkan pa mo titi.ki o si >»a ma se igbeiaga si pni- keni. Nkan pupq wa lati ni lari Pdf awon prf-

Scorpion O ct 23 d e Nov. 21 Osp yi yio je os? fdun fnn 0, papa ni arin rp. Sugbpn ko yp li o .di oju rp niloripe 6 nilali.tuii ibajp flPmiran }«. Mura girl ni kiakia.

Sagittarius:- Nov. 22 d e Dec. 20 t i t lie kan lasan yio gba asiko PUPP ninu awpn isesi to ni pse yi.

Ti o k o b a spm iwp yio fun ara rp niinawo itan, ati ibrrp ise ile titun kan.

Capricon:- Dee. 23 d e Jan 20:

Fun iwp papa o jefJ?; Up ile sije, ijo kan so-50, it a )l se 14?

kan ti o ti nfoakpjusi re, jp ki eyi gba a kuro ninu ijpgbpn kan larin ile.

Acqarius-: Jan. 21 d e Feb 19:

Iwp le f? ?c bi eyiii o ko si ni ile fun alcjo kan ti o ko f{ ri, su­

gbpn bi iwa plan na ba ban si ila iwp nllali dahun iberc nipa ilpra Pisces Feb 20 de March 20:

Awpn isp ile wa fun 9 lati se atunpe rp.” Ero ti 0 ngba lati fi wpn silp' fun plomiran yio mu wabalawa, o si da|n'pc ipari psq yio; baje nipa stye b?

ESIN NI EYITABI ESIN?

Lati pwp, Afplabi Qlabimtaa.

Emi Innriu pmo onigbagbg oke Aro,

Emi Shehu-Jpji omp Amu- le-gboroima,

Emi pmpe-egun afi akara dara 1’pjp pdun, Emi pmp Abfnilori fi eyi to kujirini.

Emi Atanda eki pmp oni- gbajump;

A $oro pe sidi prp aimpdi, A fi gbogbo ara wadi ohun gbogbo dajudaju.

Ibu baba ini Adio pki, pkp Adekunle,

Iba baba lo tori ofin loto kg Imanu ni kewu, Iba agba to tori otitp kpmp niwe,

Iba baba mi Adio to so Kikplomp.

Enyin onkawc Imp!?, mo tunde mo pegedo, Mo pada bp mo fi gborp jeka,

Mo wadi wadi nko ri idi okun.

Mo mu, mu nko ri idi o$a Mo wadi bi pna psin ijo onigbagbp kan se yatp si- kcji nko ri,

Mo bore, bi pna ?sin jjp Imale kan so yato sikcji nkomp

Bp bibeli iwc mimp kan?o le lo wa, onigbagbp.

Bf kurani roimp kan If wri, fnyin imale.

Igbagbo nrojp bi ?sin wofl.

ko ba nrpliin nil? wg. mvpn ; ko mesi,

Esi re ko nira tili; pada kawc wo.

Nitori bi ijpba kan ba yapa si ra rp, fifp ni 0 nfp.

Omgbagbo fi etp silp, o npa lapalapa,

Kaka ki nwpn ronu bi esin yio se ma Ip dede, Kaka ki nwpn pana agbere larin ijp,

Kaka ki nwpn pana ij?ku- j? nile oga ogo, Ero ‘ogun’, ija igboro m nwpn ngba,

Onigbagbp ft iwo sila, 0 nps imale nija, Onigbagbp birao o sp ni

•Ypypnatu"

Ypyp ni eyi tabi pyp, psin ni byi tabi ?sin.

Bpni Qdumare ni “QIprun Owu ni Mi"

Bibeli ni pro kan ninu on ko ni sai ¥?

Imale nba igbagbp jowu, igbagbp nbinu, Imale nba igbagbp se gbe- inti oju nranko.

Rnyin onkawc Imolp p ma ma si mi gbp, Nko sp pe psin hgbagbp ko dara,

Bpni nko sp pe ti Imale ko tpna,

Sugbpn pna psin aiye yi ni mo ro, ti dede rp su mi ; Ti eto esin Amadiya yatp si t’ Asarudini, Ti Serafu yatp si t'atpbprai.

Bp bibeli kan on kurarii kan lo wa,

Aguda iypn tilp ngbe ere sile psin

O lun nka ofin keji lpsp- psp;

Esin ni eyi tabi psin, ? fesi fun mi.

Bibeli ni iwp ko gbpdp ya erekere fun ara rp, Tabi oke ni dede ere nwon- yi ti njabp ni ? Kini iyatp larin aguda ati onibeji?

Esin ni eyi tabi psin, mo kpli p la eyi ye mi.

Eto onjo alp Oluwa t’afe- bomi yatp si t’aguda.

Bp niranti pnikan ni dede wa se oje onjp alp Oluwa, Elo itehomi ti Semesi yatp si t'atebpmi

B? onigbagbp ni dede wa.

Eto ikirun ti Amadiya yatp si t’Alukurani. ki lo se f Tabi kurani t ’amadiya yatp ni, p wi fun mi.

Bp mo wo egun l'Eko mo wo 1’Abpokutn, eto psin ko yatp.

Mo wo gtlpdp ni ilu Aro, mo re Aiyetoro, eto ko ma yatp.

(k o iti pari) T Tm7

■ A ('•po bnutine Press, 1^. Barngbo-cSi. l ap' s Pborr- TiWT- cmj, 4 l iidun Street Eat Ebine-Menii

Referencias

Documento similar

wolewole o si mu, Nigbati o mu ti wpn kp akple ti o sp bi awpn igi bp wa ni N igeria.' Mo ki gbogbo agbagba O| 0 yui, ba ft mulp si kotu wpn tab wpoyi se wulo to ni ode oih'Tim Lphiona