IR O H IN IMOLE
1 M O IE O RE A1YE, T E til C E C C B O l A W A NO 88) WEDNESDAY DECEMBER 1 0 .1 9 6 4 (2 0
.%W 9 » Ara Ilu Ko Tun Gbod$ Ko Orin Awolowo Mo
SHACAM U:- t-Snu va gbogbo enia nigh- ti i-wgn gbe ile gbp irobin wipe ewpa A last Ijp ta Ibilg O ffir, itn k m p i . g te g tr Sbagi m u t f t O f in wipe. eoikem ko tun gb^dQ ii erg redio labi gartniyfonu kprin Ok ye Q baftmi Aw. U w pm v. bi okiwa- re ko ba ft wq gau.
ofin ti Igbimp ra ti sc yi, ti gwp ba tp Ninu ipade ti awpn Ighimp na sje ni olitware, onitpbun yio Ip fippnu n m p dp- opin psp ti o kpia yi, awpn ?c ni ofin gbpn (£25) tanran si kout tabi kl o ip si wipe, ti pnikan ko tun ni ape ninu gbo- pwpn osu mpt.. laifarabara.
ube awpn olugbe enia ti nwpn pgt-e iru Ni afikun, ljpba Uilp na ti tun s e e ilu na ati sgbegbe rg ti nwpn tun gbpdp ni ofin pe, pnikpni ko tu n gbcdp kprin kprin rpkpdu Awolpwp mp lati pjp " . Ip pgb? opelu kankan Di alp mp. eyi bprp Bi pnikan ba si tun kprin ra /phin lati agogo mpwa alp t It di owurp pjp iteji.
A WON ENIA DIBO L’ONI
EK O t— Ubogbo enia !o ya pnu silp ti nwon fprp nto le pade nu> nigbati irobin kan won kt> ni asale ana oju Ise- gun ti ise ojo kpkaudinlogbon 0511 > i wipe gbogbo awon enia orile cde Naijiria yio dibo ni ownro yi ti ise ogbonjo osu kcjila odun yi.
NAIJIRSA YIO
Dokita Nnamdi Azikiwe
Aw <)ii Q lo p a 111 d p i I^Biia
^'ieisa He U a b a la w o !
POTA:- Ort) di bo lo o ya fun mi k uro Iona nigbati irobin kan yika gbogbo ilu wipe awpn olt pa ri eyin 11 ju enia meji niuu lie Babalawo kan, Dusso H arry ti o ngbe ilu Port H areourt ni pjy Eti ti i$e pjp kpdp- gbpn osu yi.
Gpgebi awpn enia na tise fi pkan wvn si tele ri. ni wipe a»Qn ko ni dibo na mp ni owurp yi, gegebi awpn egbe o$elu kan tise n§p kaktri tele wipe ki Ijp- ba y? pjp idibo na si pjp iwaju.
Awpn enia na sp wipe m ad tru wa yika awpn adu gbo kan. paapa nibiti awpn pmp egbe oselu kan ti wp-
le faiko si alatako.
N itori idt eyi n i awpn pmp pgbe na se sate Ip kesi Qipla Nnamdi Azikiwe pe, ki o lo aye rp lati ri i wipe, nwpn ye pjp tbo na siwaju.
EDEA IY ED E Sugbpn r i Ijeta pjp Aje W o OJU EWE K pFA
Irohin awpn plppa Pota fi ye wa w i p e, nigbati awpn gbp irohin w i p e Bab6lawo n a ogre awpn nkan ti o lod* si of n simt ile rp ni awpn ba Ip lati tu ile Babalawo na, nigbati awpn si de i.iu tie te, ni t.wpn ba r i oju meji ati pran enia nmu ile re.
E; eks§e ni r v»pn ti mu Bab lawo i a Ip si lie ejp I. ti Ip so ti en re riiw»ju t dajp ati tt.. h o t. ri eran ati t ju enia me; ti awpn ri ninu ile rp.
Nig ati nwyti mu aba- WO O JU EWE K £ F A
Alhaji Abubakar Tafawa Balewa
WEDNESDAY DECEMBER 30, T964 IROHIN IMQLE OJP EWB KEJI g
SIRO ISE IRIJU RE
• * • •QDUN 1964 NKQJA LO
Enyin enia wa gbogbo kakiri igun me.-prin agbaiye a f? ran nyin leti pe Qdun 1964 nrekpja Iq si Opio. le hin Qla ti ise Omnia jp’Bp,^ <i Ise pjp kokanlelpgbpn o?u yi. ao 51 ma a kl ara ku ewu Qdun tituo Ki Qlp run jpki a ie pari Qdun na layp ati alafia
O hunpataki ti a fif pe akivesi gbogbo envin Onkowe wa si ni lati bojuwo ?hin Sati siro iwa wa lati i b e r f Qdun nr, ti o fi nip si Opin yi, ere ni a je ni tabi ad a
nu ? E jpki a bojuwo phin ki a si ronu wa wo.
Nigbati pdun ba nip si opin bayi, awpu onipowo a ma a vara kankan giro gbogbo pja wpn lati mp iye ere ti awpn ie lati iherp pdun na titi de opin re pja ti nwpn ba ri pe yio di eti si wpn Iprun ninu sppu, nw'pn a tele lu u ni gbanjo.
§ugbpn ohunti awa oniwe ‘‘IR O H IN iM O Lfi” nran nyin leti nihio lati fi mp bi a jere ni tabi adanu ki ise lori i$e owo wa bikose lori iwa.
Qua ti a le fi mp pe a jere niyi: Lati igbati pdun ly64 ti bere, elo ni owo tabi ohun ini ti a ti fi ta awpn alagbe ipre, enia melo ni a $e iranlpwp fun lati ma a ri onje o jp ie, enia melo ni a ti fi iwa rere wa yi ni pkan pada kuro ninu ibi enia melo nia ti sp ore fun ti ko ni ireti a ti gba nkankan pada lpwp wpn ?
Ti aba le ri ppplppp juwe, ni awpn ti a ti se fun, ki a mp daju pe, ppplppp ni ere ti ajp ni pdun ni, nitoripe k o s i ere kan ti enia le je laiye ju ki ppplppp awpn ti a t i s e inu rere fun ma a sure fun wa Ip.
Sugbon eniti owa idi pkan re wo daada, ti o si rii wipe, gbogbo irinsi on lati there oduo na ti ofi nip si opin yiko san ju ti alp ni lowo gba lp, ki oluware mp dajudaju p e, adanu ni gbogbo laala on lati iber? pdun na titi d e opin nitor pe He ti aba fi itp mp iri ni yio wo o, prp ti aba si fi eru kojp ko le pe titi.
Ki a wa tun ronu wo wayi, ki a wo awpn ti ajijp bp- re Odun na, gugbpn oisisiyi nw'pn ti sun ni iboji, laini ireti, nra wpn si pada si erupe, emi awpn ti jere pada tp Qlprun, Ip emi awpn ti o padanu Ip sinn Okunkuu biribi ri, nibiti pkun ati ipa ehinkeke gbe wa. Ki Olprun m"$e wa ni pni Qrun apadi lehin iku O,
Ki awa paapa wa ranti pe, w akatikan mbp, ni arin pjp kan, larin pse kan, ninu o§u kan, ninu Odun k a n ti ao di ,‘Oku” tabi “Ologbev Bi a ko tile t. mo akoko ati igba na, o ye ki a mura siip ni gbogbo pjp pe, “a ti wa” "Gbogbo igba e stand bai’
Eda ti oba sppe on ti to tan on ti mp tsn, on ko tun fe impran enikan mp, ki oma daju pe oferefe ni o n w a , ohun ti iru eni bee gbojule ni pdun ni, ole di omulpmofo ni pla, eyi ni otnu awpn agbalagba fi ma pa owe p e’ Bi oni yio ti $e ri, pla ki irl bee ni o ngmu Babalawo ft da ifa pro prun.
Fitorina eniti oba ti ri ppplppp ayp, inu didun ati ala
lia ninu pdun yi, ki oma$e lero wipe numose on ni, ko si eniti oebon afi Qlprun pba ni kansoso ti cti ri iwaji ii o ti 11 ehin ti osi mp aye ti yio to olukuluku wa si ninu pdun ti mbp yi.
WO OJU EWE KARUN
Lati O
wqS. O. JAIYE
Qrp mi oni je prp nipalQrp lori i?p iriju wa larin ilp wa yi, Hrin ile iva larin ilu wa, larin idile wa, larin prp si prp, larin ojulump si ojulump. Yio jp ohun to dara pupp ti gbogbo wa ba le fi ?mi to ghoro gba. tm i ko fp ki enika.i ka prp na bi pnipe on ni mo mba wi. Bi prp na ba j? bi pro ti o bp si ta nyin lara bi asp ala. Njp fi Pmi Qlprun gba ro ki p tun pna nym $e. Nitori boya enyin ki yio duro pp lori ilp alalye mp.
I$p iriju berp lati igbati aiye ti pe ti Qlprun tl da awpn obi wa simi pgba igbadun ati ltura Qgba ti ko si ahalu tabi ibpru ninu rp fun aini. Olpruo sp fnn w.'.i i$p ti nwpn yio ma se ti nwpn ko gbpdp rp ala ti Olprun paslle fun wpn kpja. Bi pjp ti yi lu pjp ti p d u n n p a d e pdun lpna ti gbogbo nkan ndan. Awpn obi wa ninu Ogba Idpra gbagbe ara won I$e iriju ti a fi le wpn lpwp di ohun aitik ita fun nipa ghigbi impran rere tabi impran ibi ti a fi dabu pna wpn. §ugbpn lupp a pe wpn ninu pgba idpra ki wpn wa giro ige iriju wpn.
Sugbon wpn kuna. A si le le wpn jade kuro ninu pgba idpra yi.
Sibp aiye ko d u r o j p aiye nmokun ninu ppp ni—
waju Olprun a ran onige Olprun ti nge N oah si wpn ronu piivada ninu iwa i b i wpn. Sugbpn wpn kp p n a yi. Laipc aran ikun omi s i wpn prp Q Iprun wipe a fi ikun omi run aiye A fi enia mpjo ni pla ninu aiy. igba na, Aiye tun bere si dagba siwaju idera tun ba w p n . Laipp ogbogi pdp ni idide pniti a npe ni Isumrodi tun gbe ilu nla kan dide ti o si I kp ile nla kan sibp ti a npe
| ni ile Isp Babeli, 6 mu r a lati kp ile yi fun iditp niwa ju Qlprun §ugbpn mp i r o ati ete rp nitori na o n a ede awpn enia ru nigbati wpn kp isp ti Qlprun fi 1 e wpn lpwp fun i§iro rere.
Lehin isubu yi tw puiran kan bi Nahoh Tera A brah
am u dide lasiko Abrahamu imo Qlprun ber? si gfcile ni pna to tp Qlprun papa ntp awpn enia wpnyi bayi I o yan Jacobu pmo Isaac ni ayanfe gugbpn iriju'ti a file Jakpbu lpwp ku fun ptan ail irpju ni gbogbc pna r e pa.aki larin on ati egbpn rp Isau. >ge iriju wpn ko ge ni atepe rare, Lori eyi ni yan Mi ses 1 .ti ko awpn pnm Jacobu ni Egypt lp si il? Kaanan Bayi Moses lati ko awpn enia wpnyi nip ni
arin inira pupp sugbon Qlp run j? itura fun wpn. Fun nkan bi ogi.ji pdun awpn enia wpnyi orin kiri ni aga le aginju F i gbogbo p n a wpu Qlprun nge Qpagun wpn §ugbon sibp ewpnpmp Israel mu Mose dpse n ito - rina Qlprun ri pe igp iriju ti a fi le Mose lowp kuna.
Bayi n| on papa ko 1 e d e ilp yi.
[ Qgbpni S. O. Jaiye Lphin tk o k o yi a ri awon ouidajp ati awpn ooinrin ti o nge ampna ayanfe Qlprun. B tkanna awpn pba ati awpn woli tun nfi pna han awpn enia wpn yi. §ugbpo sibp wpn kunu uinu is§ iriju ti a pe v/Qn
SI lati m p Qlprun kan goso bi Oluwa wpn gugbpn nwpn yapa nigba pupp ninu isp irju wpn. $ugbpn titi di igba hibi Jesu aiye wa ni iboriga ati aimp ohun kan Bayi ni ojo ore pfa de ba wa. Eyi ti a wa ninu re lom yi. D po tj a ba ro- WO O JU EWE K A R U N
WEDNESDAY DECEMBER 30 1964 IROHHS IMQLg OJ U BWE RETA U)
WE SI^OLOfU
EQBOGI AWQN aRA ILU FA R A N SETESSYDIIK
Fun Qmg — Qwg Ati Q mgde Gbogbo
Benson Ni A O Dibo Fun
A se awa Qing Yoruba ki i$e gmo ale, omg Qkg ni gbo gb o wa oya mi lgnu lati le ri gbogbo awgn enin ti nwgn wa sibi ipade idibo ti a ge ni Yaba nt gjg Aiku ti ise ogunjp o$u yi.
O hunti o dun mg mi ju - lg ni ipinnu ti awgn enia se pe gbgnin-gbgnin ni awgn gmg Y oruba duro ti Oloye Benson. Awgn ko si ni ii Oloye na silg.
Bi iya b a jg gnikan g jgki a mg daju wipe, gbogbo wa ni iya nje.
Oloye T . O . S. Benson E m ase jgki iya ki o jg wa, Bi Oloye Benson ba wgle aye yio wa fun awgn gmg Y oruba lati wa ni ipo atata lgnu isg
Oloye Benson nsa gbo
gbo agbara re lati fi awgn gmg wa si gnu i§g ko si glo miran ti ole §e eleyi fun wa Benson ni a o dibo fun.
Erai ni Oyedeji Adedoyin S U R U -L E R t.
A Nfe Irohin Imo- lp Ni Ede
Olotu, inu awa gmg ile gkg ti o wa ni ilu Ede yio dun bi g ba le $e iranlgwg yi fun wa ggggbi a o se ma ri iwe nyin oloyin mgmg ka ggggbi nwgn se ma nri iwe na ka ni ilu Ibadan eyi to fi jg pe a wa gmg ile gko to wa ni ilu Edg ko mo pe iwe Irohin kan njade lede Y oruba ni ojojump ni llg N»ijiria.
Inu wa yio dun si Olotu ati Alakoso ile i§g iwe Iro hin Iniplg ba le lo Ipo wgu rere lati ie jgki a ma ri i«e na ni ilu Edg ati agbegbe rg Iwe Irohin na si kun fun ggbon ati oye eyi to jg pe awgn gmg lie gkg yio si ma gbadun ati pe yio si ma fun wa ni oye si ati pglu jtan ti a nri ka lati gwg
Qgber/i S hoyinia eyi ti o kun fun grg origirigi a o si ma reti nyin o, O I o t u
Emi ni Adepla §olaja ED E.
Mo Ki I b a k a Ati A j c g b o r o
Dagba
Olotu
Inu mi yio dun bi e ba le gba mi ni aye dig niou iwe- yin oloyin nigmp lati k i a wgn gjpgbpn meji yi ninu awgn ti o nkg grg iwuri si- nu iwe Irohin im glg pe k i won ku gdun emi wgn yio se gpglgpg rg ( Amin)
Asi ma ni ireti pe ao tun m a ri awgn grg ti ofaggbpn ati oye wa lati gdg wgn ni nu gdun ti atna bg si y> ati pe ki n wgn si jg ki gbg awgn irohin ati nkan origirisi ti nwgn ba pade lasiko gdun Iceresimesi yi «ti gdun titun ti a ma bg si yi.
Adura mi si awgn gjggbgn meji yi ni pe ki Olu-.va ninu anu re ki o si fi ma sg ki o si ma da abo bo wgn lcri ofin ti o a lori awgn on i we ireliie ninu gdun yi A m i n O lotu mo dupg fun aye ti e gba mi.
Enn ni .fide Bisoye Abgokuta.
E Dibo Fun Benson
Nba $<?pc bi Olotu Iwe Irohin Imply ba le g/;a mi laye ninu iwe re oloyinmpmp lati kesi gbogbo awQn QniQ Yoruba, ti nwpn wa ni Abule Ijesha, Abule pja ati Surulere pe ki gbogbo wpn dibo fun Oloye Benson, ki aye ti Oloye na Vfa ninu tie Igbiwp Asofin Ijpba Naijlria ma a bp mo wa lpwp o jp ohun iyaleou lati ri ka ninu Iwe Irohin Imple ti o jade ni pjo pti ti ise ojo kejidinlogun osu yi wipe awon omo lbo ti mby ni Eko ko'Ao ote se Igbimo Arau- sese egbe Alakuko lati yan pnil/
ki ise omo Yoruba si aye Benson I>a nla ni a won c:nia na f$ fi j<? a’ io Yoruba kosi si ohun t/ a Ip se lati kp ijiya yi biko ye wipe ki gbogbo wil dibo, kj a gharuku li Oloye BeiiSOn lyhin ki a dibo fui1 mi ki o S! wplc.
Bii Oloye Byi.sodko ba wolt*
iliju n)a iri yio i.\ ki ise fun Bpn- son nikan bi ko se fun gbogbo awa pmp Yo»uba t'o mbp nile ati phin odi ki O.prun ma j ? k i yni iwaju ki o </i ero yhin Aye Oloj*e Benson ko gbpdp Pare ninu ii- Igbitng Asofin.
I;. dibo I tin lieuson QIaditncji -llugbc Abule — Ijpsl^a
Tessydre jg ojulowo egbogi haunhaun ti meji irufg bg kesi kakiri igboro ilu Nigeria fuD itpju gmg gwg tabi gragde lati le jg ki wgn ma hu E H IN enu wgn pgiu irgrun laisi wahala rara tabi aikole sun yala losan iwe sun awgn iya wgn gbogbo Qgoruo orisirisi egbogi bayi ni wgn npolowo siuu grg gbohungbohun ati sinu iwe kika lojojump sugbgn kosi eyi ta le fl we egbogi Tessd re rara o. Qlggbpn di ori gja mu pupg ninu awgn ara ilu Saro ati awgn ara ilu Agqnyin (CH AN A ) mg egbog yi dajudaju on na ni wgn si nig fun awgn grog ti wgn ba gesg bi titi fi di nkgn bi omg gdun wawa gbako. Kosi wahala tabi iygnu inu rirun gka ori inu iwg aiperi osiinu fgkun fgkun ewo, kokoro ara lapalapa ara gbigbona igbg gigu, gburu tabi aikolokun ninu ara sisu, Inu kunkun iro a ftfefg ati origirisi awgn amodi tabi aisan ti o ma nyg awgn g mg gwg lgnu nirba Ehin H IH U ’’ gbogbo. Tessy dre a ara mu ki ehiu gnu rg gmg rg lagbara gidigidl ati
san a wgn pglu.
Awgn gmg ti wgn nlo egbogi yi ki saba ge am a rara niwgn igba ti wgn ba ti ngbgsg dede, ti otutu ko si le ri aye lati duro ni igbaya wgn ti wgn jguo d ata
ara ti nwgn si nsun gbadun pglu Bere Egbogi Ni $gbu Awgn:—
W aterloo Medicine Stores,
8, Balm Church Street, (Oja Ita Faj!
Lagos, Nigeria.
A D ED U N CHBM IST I 4 Wakeman Street Y aba
Ip olow o hjit Ity Ko Ti tfege
Nitoripe
O KO TI PO L O W O Q JA RE SINU
I R O H I N I M Q L E
T ’O D U N K A FU N GBOGBO YORUBA KYWE IPOLOWO QJA R £ SI
A DVERT1SM ENT MANAGER i l l O U I N I M V L E 16, Bamgbose Street Phone 21985
aw -"si-' . a*.
WEDNESDAY DECEMBER 30, <964 IROH1N IMQLg______ OJD EWE RgRIS (rf)
Imoran Fun A won Obinnn
Lati 0<vp Iyaafin C. O. Olabimtsn, Yaba Envin ara mi e je ki a m a a gba’ra wa ni iyanju ni ede wa ni ?kppkan ninu “ IROH1N 1MOLE” Nito- ripe yio pe Anfani pupp bi ati ni oju ewe fun awpn obinrin ninu ppplppp Iwe Irohin ti Oyinbo. Qpplppp enia ni komp bi a t i se ntpju pmp. nitoriaa ki a b?r?
ti wa ni asiko yi ki a ma jafara rara nitori jjafara lewu o.
Ni oni yi emi yio sp die ti mo mp mpa bi a ti le pe itpju awpn pmp wa ni apa kini eyi ni ao pe ni wiwp awpn pmpde. Mo f?
ki a ranti pe awpn pmpde paapa awpn pmp-pwp fe itpju awpn obi lopplppp Emi ko le s?p? ma sp fun wa pe pelu ayp ati if? ni ki a ma se gbogbo nkan ti a ba nse fun wpn.
O dara ki a mp fi omi lilo, p?Iu awpn nkan oyin- bo orisirisi gegebi Detol to nle kokoro Ip, tabi agbo ti o da saka w? awpn pmp wa ni arp, Nko risi pe ki a tun ma w? ikoko ni ale paapa ni ssikn pye tabi ' tu
tu Anwe fun awpn pmpde yi nitoripe omi ntun ara se ni, ki ise pe idpti wa ni ara wpn sugbpn ti pmp b an k a osu o le w? fun un ni arp, lpsan ati ni ale ti oruba mu
Nigbati aba fe wp funun ki gbogbo nkan ti a nlo bi towpli, kotnu, arosi, atike, p s e kankan, paanu fifp,
(Basia) kan ati eyi ti o pe tp mi si bi k«n, ati asp to ma wp wa ni oju kan ibi iwe. Gbogbo wa lamp bi a ti pe nwp. sugbpn ko dara ka ma ho pse si ori pmp n i ojojump nitori ki a ma b a we epo dada irun sonu tan, ki asi lun fi iye sipe pse ko pp pupp nigbati a ba o w ? oju fun un.
Bi pmp na basi kere, ale fi pse nikau fp oju fun u n ki im a lo kan-nkan rara.
Ti aba we fun un tan, ao fi towpli gbe ara r? ki a t o wa fi atike kokoro para fun un ni arp, ni psan ati ni ale ti ooru bamu ki alo aw p n bi Baby Royal Powder tab!
Johnson Baby Powder ki a to wp a spfun un. A w p n elomirao tpran lati ma a lo atike kokoro ni igbakugba ti wpn ba lo fun ara w p n, wpn ari pe o nta enia g a n an paapa ninu ooru. JEjpwp ti ko basi kokoro ni ara p- mp, ekan perc tito o.
Osun si tun je nkan ipara
tpdara, sugbpn a ni lati ya Bayi ni ngo duro loni iyo sptp fun app osun b?kp ku sun di pp? to mbp.
yio ba gbogbo app wpn jp.
G B oGB O ARA 1LU N K Q OR1N 1YIN AYQ
N1PA
DYNAMIREN"
TONICA L E -B I-A L E Egbogi Ip n ik i Jamanu titun ti gbogbo ara ilu Eko ati ja- kejado Naijiria mp daju fun Akp agbara ati Aje- bidan ip? rp lara Agbala- gba Q kunrin gbogbo.
Bi arp ara ba nmu p, nigbakugba fun wahaia la- la pipe ti o ko le jeun daradara, tabi ki o male sun dada pkun lpsan tabi awpn ipa n ara re gbogbo ko ba sipp daradara ti Eemi Breath) inu rp ko ba gunle daradara fun ipp tabi wa
haia pipe tabi fun awpn ailera g bogbo’ tabi ti pjp ori rp (age) ba ti kpjapgbpn pdun o si de adprin tabi jube lo. Mp daju pe "D Y - N A M IR EN ni egbogi ti o nfp lati sp’ara rp di ptun pa tapata ara rp a si jplp, eran era rp tio ti hunjp vio yi po padapatapata alafia ati gbaduo yio de si p Iy?n
be.
Bere egbogi na ni § p b u
N IGERIAN M ED IC EN E STORES 4, Tinubu Square Lagos ATI N I SOBU
O LO D U M A R E DISPENSARY O K E BQLA IBADAN
1TE IHW VO HE WO
AQUARIUS (Jan 20 - Feb 18) Awpn idiwp die yio wa fun p loni. Beni nwpo yio mu ibin ayp kan fun p wa lati okere.
PICES (Feb. 19-March 20) Oiufe re yio huwa ite—
lprun pelu re loni beni gbogbo ise rp ko ni mu iyonu kao wa fun p ti o ba fi otitp sise re.
ARIES (March 21 - Apr i! 19) Gbcgbo idawple rp ni yio ma a lo gegebi o ba ti se fe loni mape foiya orire wa fun p loni.
TAURUS (April 20 - N ay 20) Gfciyanju lati mu gbogbo nkan se loni. mase hu iwa agidi kan ki idiwp ojiji ma ba se de si p.
GEMINI: (May 21- June 21 Qjo oni dara fun p lati pe irirajo si ilu keji tabi iwaju. ohunkohun ti o ba si pe rere ni yio maa ja si fun p.
C A N C L R ;- (June 22- July 22) Ojp d ira fun p lati pada tabi abewo oiufe rp prp ti e ba sp loni yio ri b?
ti wi.
LEO (July 23- Aug 22) Mape ba pnikenijiyan loni ki o si pp are re gidigidi nitori pjp ijangbpn.
VIRGO (Aug. 23-Sept 22) Qjo oni dara fun o lati se ibpwo awpn pre tabi ebi re ti o ko ba le pe ibewo awpn enia re, mape Ip si ode kan nitori oro akowaba.
LIBRA (Sept 23-O ct 23) Q jo oni dara fun p lati pe ibewo awpn enia atata ti nwpn le se iranlpwp fun p mase tiju fi oke isoro re han wpn.
SCORPIO (Oct 24 Nov 22) Idiwo aii airjye wa fun p lot.i site mase fi ise inu ile re jafar.i. Aalp nip ori ara re aaO nip ori oloko.
SAG ITl ARCS (Nin 23 Dec 21) Orire wa fun p loni gbiyanju lati se gbogbo awpn ipe ti nb? fun o lati se ki o le ba ri iranlpwp Ipdp omp enia. Ijafara lewu o CAPRICORN (Dec 22 Jan 19) Oku isoro li o wa fun p yio di pet?)? loni ti o ba it gbiyanju lati sun mp oluf? r? ma jina si ara oyin ajcji pwp kan ko gbe eru d’ori.
Gbanjo ! Gbanjo ! !
F o N Q DUN KERESIM ESI A ni lati fi kede fun awpn onibara wa pe Qja gba njo wa b?r? lati oni ip titi di 30/11/64. Tete ra tire ki o to kase nil?
APEJUWE ILE ITA IWE WA Wp Bppsi Mushin, spka'p ni A tev.plara B u s S tr p Bere ladipo Street, ti o ba rin titi Ladipp, bere ILE IW E O D U • ABORli. Ti o ba de ibe tan, wa be re Nomba 5, Alaba Stree M ushin, ile ipe w» dojukpta O D U S S U R F ”
AWON WA
Olubori Egbogi Ajebidan 40s di 30s Iwe Egbogi A je- bidan 25s di 22s Iwe Egbcgi Awogba Aruu 20s di 17s Iwe liana Ifa purin tit? ati etu pipe 20s di 17 Iwe Afop?
Isedal? Y oruba ati Psalmu Ajebidan 3/6 di 2s 6d T u ra i Is?gun Aje 10s 6d di 8s Turari Itaja 10s di 6d 8s Turari Ala rere 10s 6d di 8s lye owo Turari pangolo niti oke yi Turari ti o wa ninu paketi j? 2s 6d pere (we Itum p Ala Joseph Alala 5s Iwe Aniyan eto Irun o ti di 2s 6d Akpnni lesin pataki Islam 2s gd T a ilo r’s M easurement book di Is 6d
Tenants Agreement Forms 10/6d di 5/ Gold Smi/b Form.s Certficate of Apprenticeship (metnj 17/6 di 10/6d
OJA TITUN TI A SESE RI GBA Abflu minip fun adura tete Idaloju (orpiripi aw pu fuu Turari.
abela mimp fuu itaja (K.owo wple pelu Turari 20 /- - •> Isegun a e pelu Turari 20/- Lpfinda tabi O roro ipara f\.n itaja, Ipegun Aj? ati arisikl 30/- tgo kan
Fi owo r ns? tabi ki o wa r a n i pdp:—
J. O. Shoyinka 5. Alaba Street
M USHIN,
lMQLg OJ'J EWE KA RUN (5) WEDNESDAY DECEMBER 30, 1W IROH1N
Qro Isiti Si Awon Olori lie Wa ( Apa
Lati Owo Hori Moses, Ikeja
Ejowp enyin olori wa, enia le. sa ti ako ba mu ibpn lpwp, ibpn k o .le pani, ti enia ko ba, wa mpto ko le pa enia, enia logun, ogun i’enia enia vti orisa, orisa ni enia Q lprun l’enia e n i a ni Olprun, gbogbo wa ni a m p daju wipe ifi pwp sowppp pplu ohun gbogbo rii a ti le se ohun gbogbo o da mi loju pe ti enia ba fe $e ohun k ih u n ti ko ba sunmp ohun r.a ko ni se is? e ipwp pnyin alas? wa p ft pwp sowppp pmkan k jeki ile ko fe opin < hunkotiun ko si ni tori.
Ajpti ni orukp ti an p e aiye apa ko ni ku nyin o e se rere si dp Naijiria cmi llpri yio se rere si ile wa N aijiria ki ile Naijiria na se rere fur. emi na nitori pni to ba se rere si i l e Naijiria yio ri rere. E lo agbara nyin r.itori ninu prp ni enia ti mba Qlprun spro, ninu prp ni Qlprun tim b i enia sprp or 'n i ofm Qlprun si enia enyin Alas? ti p se ileri lati ko awpn euia nyin la okii'i pupa ja gpgpbi i§p Moses, Moses leri ni iwaju Qlprun Q lprun si wa pplu rp .M o so si wa pelu Qlprun nitori Moses se olutpju isp r e pplu otitp ki 5 e pelu owo tabi pelu mpto beni ki se pelu ile a ko si gbp pe poikan.
dibo fun Olprun tabi Mose
§e olukuluku nyin mp pe Baba wa M acaulay ni okp- kp here ise Q.ninira ti a gba yi o se i§e re pelu ot tp o si pari i$e rp o simi gpg?
bi Qlprun ti pari ise rp ti ko si atunse fun Qlprun mp ninu is? rp nitori ko si a$ise fun Qlprun ninu i$p re a$ise wa fun ema atunse si wa fun ema.
Ti a ba le tun ohunko- hun se laiye yi yio si dara fun awa enia ti a ba si ba aiye na jp a o si ba bi a ti se si lb .jp aiye o wa lpwo wa agba Om inira a si fi ns: pte si ara wa ko si eni ti o ni aiafia tabi ifi okan baalp a sp -pwpn di pwu ti a n * o bi cni wp a$p.
OLOYE S.L. AKINTQLA Olori $ g b p Demp
D 3 K IT A C H IK E O B I O lori Egb? D ynam ic 1 Tani pgba ewpn dara futl lati gbe ninu awa? A S(?, Ofin wa di pajawiri. Emi i o ti ri ka ninu Bibeli tabi kurani pe Q lprun se ofin pajawiri kan fun a w p n enia re ri. Beni enyin O n i- m a leati Onigbagbp pp ni nu awpn Oselu O lprun sp pe ki a ma bi si’ ki a m i re si i, ki a si ma pp ne ile. §ugbpn a ko mu s$a Qlprun na se mp ti ara wa ni a nse.
A gba Ominira tan ppm de ko mp ara rp ni pmpde agba ko mp ara re ni agba mp nitori owo gbogbo wa nyp kump si ara wa.
A ko tun raati pjp ibi wa ni pjp ire wa enyin ala- S?, Nje o ha y ek i a gba ominira ninu ile wa ki a ma to eto ile wa ise bi? Eyi si fa aisi isimi wa fun p m p de ati agba ni il? wa. Beni ko si isimi fun Q lola ati Ts luka.
Enyin Awo irawo Aladu- ra Unimple Onigbagbp, Onijcgun pflu B ibalaw oe jpki a wo iru nkan to n$-.dp si ile wa yi wo ki e jeki a gbe oye wo ko si eniti o feran ara ninu awa enia ile Naijiriria a si tun fi ibo di- di di ara wa lpkat. a npa ara wa nigbati Olprun ko
Keta)
ba wa. Nigbati awa enia pa pa ara wa tan kini omi- nira yio duro fun? tabi ere wo lo wa ninu ominira wa?
Enyin alas? wa abp nyin ke ba wa moju si iru isple wpnyi ni il? Naijiria A ,k d Baba wa >o si npa lo’we pe A ki ni pgber.i Ajp nile ki a sp pe a ko ri enidele ale Ale ti ko ba toju eni le a ki mp okunkun re rin Nigbati Qlprun da aiye Mose okan popo ni Qlprun fi se ajiwaju awon om olreai ‘ lose se is?
rc p ; l j uiui p .lu otitp pplu ife pplu ise Olpr u n s i w a pelu re.
Enyin Olori wa e jeki ani sum , ifarada ati pgbpn ki a le mu ero pkan wa s? kini agbara ibo didi niwajunyin enyin ni e ni agbara 1 o r i jbo ki ibo loni agbara tori wa e jpki a ro gege bi ile wa yio sp dara pelu ifi pkan bs/e.
DOK.1TA O KPA RA Olori Egbp rtlakukp Awpn oyinbo Jsi t fi i|?
wa sile fun wa kini o tunkn Sebi awa (a osq peiw pn oyi nbo nr? wa je? Nwpn le ma re wa je sngbpn o si pe eni kan np.i ara wpn Lsiko ti awpn oyu bo, a sp pe a bp loko eru a tun bo s pwp aisi mi. Enyin alis? wa p lp ro wo k i e ipki amp ohun ti a o se o di p *p nyin o.
L A TI O JU EW E K EJl nn ki a si wo ehio ki a le Se a tnn pna awa ko se bp rare- Nise ni a r un nmokun ninu psp wa ti awa ko rooupiwad . csp wa gbogbo Iwq arakprin ati arabinrin ko ha yp ki enyin siro is?
iruju nyin.
Boy a p ki yo se isp iriju pe mp. Iwp ti o nhu iwa ibi ' inu gbogbo pna re nj?
ko ha y? ki o siro ise iriju re boya laipp yi a o pe p lp si ilu aiyeraiye. two oselu ejonigboro ti ko s> iwa ododo kan lpwp re nje siro is? iriju re boya lo le yi ni a o yp p. Boya 11a igpimp ti o fi nsogo looi, twp yo tun vt'p ile na mp titi aiyera
ve. . . . ,L. .
Iwp ti o j? pga ni ibi isp o jp pga ni ibi is? kan ti kosi ohun ti o mo ju iriba gbigba lo nigbati o jewipe pwp awpn alaini lo ten gba Nje firo isp iriju re,G bogbo pnyin ti a fi sipo itpju ilu nje kini ise rp? $ e iwp yo ta orile ede wa vi fun alaini awpn eni trele Jowp siro Iwp re siro orp re boya ohun re jeje tabi file ini a ki yio gbp wpn mp. Nitori gbogbo enyin eni ibi p ye ara nyin wo funiy ipada s pna rere. Qjp anu ti ipt sumple
Ki Oluwa jp ki a le ro m oinu awpn ikilp wpnyi §irt ise iriju re ara Odigba o.
ODUN 1964 NKOJA
Lati Qju t w . Keji
Ni ipari pro iya ju wa fun ipari pdun 19 4 , e jpki a j^nti awpn a$ayan prp wpnyi lati inu Iwe Mimp Qlprun
^ o le je Ogun ispra fun wa de inu pdun titun.
Bavi ni Oluwa wi, ki pjpgbpn ki o mase sogo ninu ara r.-, beni ki ala gba ra ki o mase $ogo ninu agbara re, su - gbpn ki enikem ti yio ba ma a sogo, ki o $e e ninu eyi pe, O n ni oye. On si ni imp mi, pe Emi ni Oluwa ti nse anu ati idajp ati ododo nl aiye. Ere kiii fun enia, bi o le jere gbogbo aiye, ti o si sp emi ara rp nu.
Ki odun na to kpja lp e jpki a b? Q crun ki o ran wa lpwp ki a tub? ina a pp si ninu is? rere ki a le ma a ri iypnu Qlprun gba ni gbogbo igba, ki o si pplu wa wp inu pdun titun 1965 ti mbp yi Amin.
IR O H IN IMOLE
IU O L E ORE A Y IE , TLN 1 GBOGBO LA H A NO 883 WEDNESDAY DECEMBER 30, 1964 (2D)
Awpn Kan Wo Kotu Ijoba Ibil?
Gbogbo ll« lo kunw so ti p$p ko si g b tro nigbsti amen O k pa mo Qltunrin torn wa si kotu Ijtb a Ibilc TJmoituru - Etchc, jlu kan ti ko iirra p ip e si Port K aicourt fun psun pe, o huw a ti o le da i ukcm do site larin ilu, ni ojo Aje tt igc ojo kejjdin- o gbpn o$u yi.
mu gbogbo a wen adajo si pate pe ki N/gbati awon p lo p a rojo tan, ni mepn Ip fi wpn panto si itimp/e.
pkunrin na ba rojp, Nigbati adajo gbp Nigbati awon Qlopa ti awpn Q kunrn pjo totun tosi tan o bl p kunrin na lere na mole tan, n1 awon kan ba de nigbati p c “ O gba wipe o jfbl tabi o ko gba awon Q :opa t i lo nwpn si wo lie
pe o jfb l” itiroole na pale ni gbogbo awon enia
Okunrin na gba wipe on k o jfb l, in - na ba salo b em utam u.
gbpn nibiti nwpn gbe nsoro Ipwp uinn Awon Qlppa ti rw a awon enla na k o t u .n l awon mptala kan ba nkprtn kak 'ri nisisiyi, sugbon rw on k o ti rl ninu pgba kotu kl a ol awoo p lo p a ba wwn mu
LA TI O JU EWE KINI ti iye pjo Kejidinlpgbpn osu yi ni Qlpla zikiwe ransp pe Tafawa Balewa ti awpn mejeji si jijpjiroro lori yiye pjp ibo na si pjp iwaju
Nibiti nwpn gbe ta nsprp na, jpkptp gbe pmo le a wpn mejeji lowp n w pn si ja
»uka lori prp na.
Leypkps? r-iQlpla Azikiwe ba runs? si gbogbo awpn Gomina ati Alakosi Ijpba Ipinlc.
Nigbati o di ni psan ana Gomina Ipinlp Ila Oron ati Alakoso Ijpba Iwp Orun G omina Ipinlp ati Alakoso
Ijpba ipinlp A gbedem eji ni nwpn wa si lp a d e na.
Oniwe Iroltin wa Ejong- bodo ti o lp si ibi ipade na ni He Qlpla Azikiwe fi y e wa wipe Oloye S. L. Akin- tpla Alhaji Ahmadu Bello Qlpla Q dfleypFodahunsiat Olpla Ibrahim Kasihim ko wa si ibi ipade yi.
Awpn ti o wa here ipade ni agogo mejila aabp nwpn si p ari rp nl agogo m arunirplp ku ogun ispju (4 40 p. m .)
Lehin ipade Da eyiti nwor. ye fun wakati mprin lie i$p M inisita Alam ojuto eto irohin fu n A p ap a|Ijp b a
sp fun aw p t oniwe Irohin wipe “ Gbogbo awon etna orile ede Naijiria yio dibo ni owurp o h (oni) gpcpbi Ijoba t| sp eto tplp Inti pbin wa”
$ iwaju eyi ni A Ihajl Abu baka r fafawa Balewa ti ba gbogbo oga agba nwpn
§uja ye ipado ninu ile rp ni onikan Eko.
“ D A R U D A PQ ‘ Ninu ip nip na nwpn sp- rp lori bi ibo ti wpn enia Naijiria yio di loni yio ti ye fpypmulp ti ko si ni si ija m adaru ati dartidwpp ti gbogbo enia yio si dibo aa
make it a successful SEASON
with MERCEDES-BENZ
TRUCKS
{ LAGOS, APAPA & E B U T E -M E T T A , IB A D A N , I K A D U N A , KANO . JOS, ENUGU, O N ITS H A . I , PORT-HARCOURT & ABA.
wporp.
Ikede Iran latiile isp awpn Alabojuto eto ibo fi ijp wa ni alp ana wipe ni deede agogo mejji owurp yi ibo na vio si pari ni deede agogo mpfa irplp.
G bogbo aw en enia ti
• wpn ba ngbe Ebute Mptta Y aba Surulere Shomolu ati M ushin ti nwpn ba nsi- sp ni Eko Iti gbogbo wpn duro dibo ni owurp yi ki nwpn to wa si ibi ijp wpn.
Gbogbo awpn oyiyp ni Noba yio fun ni aye lati lp dibo oi owurp yi.
x, v, gb° " ‘P® 0D,<? *Bbe N .N.A . Adprin (70) ati pmp gbp UPG A mpdogun
( I S ) ni nwpn ti wple laiko
ni alatako.
Agborp awpn akpwe eto idibo sp fun oniwe Irohin wa Ejoneboro nigbati nwpn nfi pro jonitoro pro niwaju Ile Qlpla Azikiwe lann wipe gbogbo ile bi metale'ogun ti awon kan wolulp PEko ni Ijet« ni Ijpba yio tun kp omiran k i awpn enia le ri ibi dibo ni owurp yi Awa Oniwe I r h r n Imp- Ip kesi gbogbo pnyin enia pe ki p tete lp dibo ni owurp yi
Bi ay p risiib o na ba ti pip. e o ma a gbp ninu fwe irohin wa lati pla lp.
A wqh Qlopa Ri Ori E n i a Ni Re
Babalawo !
LATI OJU EWE K IN I lawo na de Iwaju adajp ni an», Babalawo na ni on ko jebi eyu > t i awpn pi pa fi sun on. Adajp ti yp gbi- gbp pjp na si pjp kprin osu oyu kini odun ti mbo vi, lori iduro adpta penun (£50) ati onigbpwp iyckanna. Bi nwpn ba ti pati pjp na si, po tun ma a gbp.
Printed A nd Putilished by M o d u p e P rin tin g Press/ 16. Bamgboye Street Lagcs Phone 21985 Editor; TU N JI A DEOSU N 45. Campbell Street Lagos (30/12/64)