IROHIN IMOLE
1 M OLE ORE A YIE, Ti.N l GBOGBO LA 11 A
NO 884 THURSDAY DECEMBER 31 1964 (2D
Awon Qmo Egbe UPGA Meje Wa Ni Itimoie
IBADAN:— Ni i l« g u ti ?e i...Ur.d ■ Ivfbv o ju y . . i Ad y> 4e tjo ibi ij mvpn tise rj w n £ 'ia mi Qgbe ■Th( mi
t S'waju mcjc ti nwpu mu lori n pc nw ohun io Icwu Ipwp Si yj . Etr n o§u 10 rut Awpn citiq pgbp ilpsiwaju ilp N aijii/a meje ti n*Qn li ysun na kan ni Musa O b‘§?s m Ra*mi Aka* de Ov'oade Egbe - leke La midi Obi§?san Jimp Obj§$san ati Adisa Ob'S?san. Nin« psun ti Agbpjvro t un ilc pjp na fi kan awpn pm p pgbp UPGA na ni/?e ni pjo kpkanlclogun osu yi pc «H’Qn lg kolu Minista Alamojuto
is Cu m. s sun awpn in, vghp n 1 ja ija igLort/cyi to 19 pe o le fa 9 y«-
eto iclm fin I/cba ipmlp Iwo Orun ni u dug t o 11« Ba/p, Olugtoc’c, lbadun.
Lih.i. tyi in A g t i c rc fui awon <mo pgbv UFGA na Alhuji Busari Obi§psan .vo fun A da jo na lati je ti 1 won gbn idu- ro awon < n o vgtp m . Jvuglpn Adajo ile ?jo na taku lati g ta id u row pney i ti o ti .vp j c kir.won Io li won mole titi di ojokyrin o$u to m b o yi.
«Ajjn Ivo Imi E»e«U.N Bilctly Kp Imi Aja”
EKO:— Or? di ki onile o gbele nigbati gbogbo awon ara Eko fariga ni kutukutu owuro ana ajo ojo'Rn ti ise ogbonjo osu yi ti gl»og! o awon e ia Naiiir a n lati dil>o ti gbogho won s1 dake sinu i c ti enikan ko jade sita lati Io dibo geffbi eto t o ti wa ml?
lati bi o$u kan $chin.
Siwaju eyi ni < gbe Afp- nifere ati Alakukp ti kesi gbogbo awpn pmo egbe wpn wipe, ki en keni ninu awpn pm p egbc na mase lpwp tnnu ibo Ap.pp ti nwpn f? di ni a a.
Awpn cm < gbe na so wipe “ Mad.uu" « a ii nu eto ti awpn enia kan se lati fi crukp awon As ju sile, ni gbogbo agbegbe na ni nwpn si gbe sp wipe awpn kan wple laiko si alatako
Sunbpn nigbati o di owurp ana, gbogbo awpu aia Eko, Qbalende, lkoyi, Falpmo. Yaba, Ebute Metta, Apapu, Surulere, Mush n, Shotnolu, Ik?ja ni nwpn ko iade lat• Ip dibo.
Onirohin wa Ejongboro ti o Ip kakiri gbogbo igbo- ro ilu Eko laoa fi ye wa w i
pe gbogbo awpn fcleran Ala te, oniwosiwosi, Alasp Ala- ta Elewepmp, ni akotan, gbogbo awon obinrin plpja ni Ebute-Ero Ereko Qbun- Eko lta Faji Jar kara, San- girpsi, Idera Kajvla ni gbo gbo wpn ko wu si pja lana.
Bakanna ni gbogbo awpn He i$e Ijpba die l’Eko ni nwpn ko si sis?.
Awon o§i$e Bppsi Muni- sipa kp ise cile gbogbo wpo ko 8'se Awpn 0$ sp ko tile ri mpto wp de ile i$? w p ii niana Takisi niawpn miran WO OJU EWE KEFA
THURSDAY DECEMBER 31,
Asiso Or? Ni Bamu-Bamu
Lati ()»<? IBAKA
Olo f i prp awpn pjpabpn pe yiyi ri aiye r.yi. Nitotp alyo nyi corun l a, o si tua nyi ara re ta geeebi ogo tabi okoto n a won pmvde : fi sire. $ugbyn yatp si yiyi mejeji t a f’en'u kan wpnyi a tun le sp pe aiye nyi nigbati igha ati a?a b» nyipada. Nigbati igba ati ihuwasi awa pmp enia ba ti vipada tan, o,«e tabi pip tt o tt je plpgbpn ti o si ti ba eti mu tple-tpl? ri a wa pad.i dt asipa tabi asisp ti ko ba igba mu tup. Qrp kan b « ti o ti wa pi,da di a$>sp prp ni prp orin ti awon ara ilu ma a nfi ilu kp bayi pe
■‘Bamubamu lavo. awa ko mp peebinppm p enikpkan, bamu-bamu layo.”
1964 IROHIN IMQIP- EWE KEJI W
Ni aiye atijp, nigbati imp tituu ti ode oni koi ti waiye rara ni ile Yoruba is? ogun jija, igara dida ati owo eru ni pmp akin nse j?un. ’ Nigbana nipa i?e awtn iwpfa ati ti a>vpn
?ru ni awpn ti a npe ni alagbam fi ndide ti nwpn si ndi olowo ati plpla. Ni akoko ti a nwi yi, a ma a ngbp iru o»e bayi: Eja ni eja nje sanra.
Ni akoko na, ?ni ti o ba gboju, on na ni ayo re nje Akoko na ni pmpde ko gbpdp nikan rtn, nitoripc baba oni-baba ti lugp siou lgbo lati gbe pmp-plpmp ta ra ooje fun awpn pmp
tire. Agbalagba paapa ko le rio I ii ia okun ipa k t- run nitoripe o le pade akp oknnrin ti o ngbe okunrin ta jpun. Ni ko- ko na ni awpn nkpni ile Yoruba a ma je oriki ba- wonyi: Aja’le onile bo tire lehin. A nle e bp lehin o n'e ara iwaju A’v p n prp hi Bamu-bamu l-yo yi ba ode igba i ,ms. Qro na fe
re jp orp ti Kami sp lehin ti o ti la abaro re Abeli pa ta , ti o si da Oiprun lo- hun pe: Emi ha nse olu- toju arakunrin mi bi ? Ako ko ti a nwi yije asiko imp- t ara eni-nikao. Ni asiko na paid a ba bi si ile pla a
tubp ma Ipla si i ni. pni ti a ba s' bi ile talaka nse ni yio tubp ma giranan si i ni nu iwa osi. Laiye pjpun, atapatadiiie enta ko pp bt ti ode oni.
L’ode oni aiye ti yipada Aiye tidi aiye ekp Qtp aiye iwosan pfe ati aiye awpn e tapatadide enia Aiye tidi pe ki pmp a$egit» k‘o ma ba pmp olowo figa gbaga ni awpn ile ekp g'g< Aiye tidi ajumnsepp ati akojppp pwp lafi nsp aiya Aiye tidi aju- mpda ajp owe ori ninu eyiti olowo yio da gegebi o ti lowo to ti talaka yio slk iwpn ti agbara re ba gbe kun u Lati ara ajumpjpda
L’ayo
owo ori yi ma ti n$c inawo ekp pfp ati iwosan pfe fun mp talaka Lar.t re na ni a tl nte riti plpda li a$e "mi erp ti asi tan ina iletirikl si titi fun anfani pmp olowo ati pmo talaka
Enyin pkawe mi pwpn ? ko wa ri i pe, 1‘ode oni asi§o orp m bi -a ba sp pe
•Bamu-bamu l‘ayo, awa ko mp p ebi np'pmp pni- kpokan’’? L'ode oui oni- kalukti ti di olutpju ara
kunrin re.
Nje ki yio je ohun iyale- oti fun ppolppp ninu awpn pdp wa loni lati gbp pe ni igba lailai “ Bi o ti wu ni I'anse Imale eni’' ni orp larin o?i$e ati pni ti o gba a $‘i$p je? Bo ti wu ki o yanilenu to, sibesibe otitp ni pe ara ti o ba wu o,.t-
$e ni o ma nfi o§ise a be re da nigba atijp. lyc owo ti o ba wu u ni o nsan fu.i u Igbati o ba te oni$e lprun ri o$i?e le kuro nf ibi-ije.
L'prp kan, bi eru ni cst$?
ma n?e fun ooije re. L'o
de oni nkp o? Gbogbo nkan ti yip.da, Omse ko tun le san iye owo ti o wu u fun osi§e re. Bi o ba da l‘asa awon egbe osi- t>e a ka a 1‘owo ko. Oni§?
kan ko tun le 1 > o§t§e r?
ni ilo eru mp Bi o r>a dan a wo ljpba ile wa yio sp fun u pe uki $e be
Aye ti o?i$e wa si onis?
re niiba atijp fe alaye di?
ki o le ye awpn pmp ode o ni Nigba at jp kosi Ope pni kan ag'a §ise aseghowo io- sosu lab? ekeji nipe kl tala ka kio yawo lpwp olowo ki talaka na kio sidi Iwpfa la- h? olowo ua 1st, a§egan ati a lopm niti Iwofa tabi arin- gba vi titi on yio fi san owo pada fun olowo re Nisbati awpn pmp olowo re bn nsi mi ninu aba tab) ahere lo ko Iwpla gbpdp wa ninu or n nibiti ogbe sis? nigbui a*pn ba pada lati oko stle ti awon pmp olrvvo re nfi fjayiyan bi Iwpfa ba le ri ep" li je tsu ki o dup. lpwp ori
Bayi ni aiye ti ri nigba atijp. 1.asiko na ni orin Bamu-b mu layo dun led.
Ko beti mu mp lode oni.
Aiye ti yi kuro nibi iru prp bayij o si ti yi sibi F?ran pmomkeji re bi ara rp,
Bi pjp tt ngun ori pjp, ti o§u si ngun ori osu ni iyi—
pada yi i tubp ma pp si i WO OJU EWE KARUN
• Full fropicalisation and underbody protection plates
* Strong and comfortable suspension.
* Outstanding road holding.
* Modem workshops and spare p a rts s to re s, manned by Factory Trained Staff.
* HIGH RESALE VALUE.
DON 'T F O R G E T TH A T YO U CAM
ALSO TR A D E IK YOUR OCD
M ER CED ES-BEN Z 0 8 . RENAULT C A & t
M l R tff K » - • » 3® -4
LEVENT1S MOTORS LTD.
l a g o s, a p a p a, & e b iii h t t a, i b a d a.n k a d l n a. k a n o JOS, ENU Gl), O M TSIIA , PORT H A R C O L R T & ABA.
THURSDAY DECEMBER 31 1964 IROHIN IMQLR OJP BWE KETA (cl
Shoyinka Nki Yin O
OLOTU:-— Dakun gba mi ni aye ninu iwc rg arim&lelo ari yo KQiQ racji ninu tgrp latl ki awon onkawe Irohin Imolg pc nwon kuy d u n , nwon si ku iyedun.
Oluwa ko $e Qdnn yi ni od un rere fnu wa o Amin.
Mo si tun ki Olotu p a a p a ati awon abasi§epo rg pc woo ku ewu Odun yi o. Edum arc jg ki a ?e opo Qdun I’aiye o
Ileri mi ni qrfun yi lsgbara Olornn ati Olotu ni pe, g o ma ka itan. Itumo ala, Ituwo Ami Ara ati Owe Ijinlg mi bi ti atg- lu'nwa, nitori idi eyi, mo kesi awgn onkawe wa pe ki nwon ma a ra Irohin Imolc deetfe Ki awon nkan anfani na ma ba ta won o
Emi ni J ,0 . Shoyinka Onitan Ajiran
Eku ldele O Sho
yinka
Olotu:- Inu mi yio dun bi e ba ie gba mi ni aye ranpe die ninu Iwe nyin a kprno lede ki Qgbpni J, O.
Shoyinka onita Ajinran ilu awon oku pe ki o ku ilede ati a§$hiune ti pgbp rp olo- gbe Jacob Shoyiuka to ?alg- isi laipe yi mo si bapgbeni wa J. 6. Shoyinka ati awpn ebi re kpdun pupo lori iku ti egbe rp otun rp na ku ati pe ki Oluwa si gbe si apa otun re ki o si tpju awpu pmp ti o bi site.
Awa onkawe Irohin Imp- le ni ilu Ib»dan si ba oni- we wa ogbeni J. O. §hoyi- nka kedun pupp paapa julp awa ti o tigbe ni lopole
Yeosa ni ilu Ibadan.
A si ni lero pe iehin ti cyp oku ti ologbe §hoyin- ka na a lero pe omtan wa pgbpni Shoyinka vio si ma fun wa niitan oloyinmprap nvran gegebi ti atehio wa ati pe o pe pjp dig ti a t n ri itan rp ka, Olotu ru o dup? fun aye ti e gba mi ajinde y io ma j? 9
Emi ni Ygkini Adeyemi Ibadan.
Itan Shoyinka N k y?
Olotu:- Inu mi yio dun bi ? ba
\e gba mi nl aye ran/?g n/nu Iwe nyin ti 01a bi akaia gbigbona ku lati b<?re ogbgni wa onjgeg* ku bi ojo ti o tun j? onitan Ajinrao ilu awon oku ogbgni J. O. ^hoy/oka lori pe o ti pg dig ti a ti ri i/an rg ka ninu iwe nyin Irohin Imolg ati pe elepl ya awn onkawe Irohin Imolg Ignu lati ri pe a ko ri awon itan ka eyi to j? pe 0 yato si itan Ainjiran ilu okui
Oloto inu awa onkawe nyiu yio dun bi e ba le j? ki a tete tun ri itan m irin ka lati owo ogbgni J. O
§hoyinka ati pe awa ui nreti itan re bayi. EleyJ jg ohun ti ko dun mo wa ninu pupo. Mo tun kl nyin olotu pg ki g ku a bo binojo nyin ati pe mo dupg lowo Adcle nyin 1 a pglu fun iwe Irohi.i Imolg ti a cri ka nigbati g k0 si ni ile.
Emi ni Adetgla Ilori Abgokuta.
b e r e lGBOGI p a t a k i y i t i NWON NPE NI:-
■Mpias D educing D ragees:,
Je ojulowo egbegi ti awpn Jamani §p$ s e iwadi rp fun awpn ti o ba sacra tabi ti o ba ‘TOBI, ju latima mu ki nwpn le fpn tabi ki won fpnku lai si wipe nwpn ma ka ewp onjp ti nwon yio maa jp rara, besi ni ko lewu ni bio lun ema yala pkunrin tabi Obinrin rara.
Ki enia §anra, gborio, tabi kio tobi puppju ki n$e ohun ti o dara o i lewu pplu ppplppp amodi ni o nko »ya lilu kiki tabi iija nigbattugta aikole mi ka nip daradara, ara wiwo tabi vviwuwo; Eemi mimi hp-hp ati orisin?i arood omiran pelu
§a dan I go re kan wo, Iwp na yio ri ayipada ati A la- a ti yio de si 9. Bere ni §pbu awpu Olori Elegbogi Jamani ni Igboro Ilu Eko.
WATERLOO STORES 8, Palm Church Street, Lagos ADEDUN CHtlMIST
4, Wakeman Street, Ynba
EGBOGI AWON aRA ILU FARANSE
TESSYDKK
Fun Qnip — Qwg Ati Qmpde Gbogbo
Tessydre jp ojulowo egbogi haunhauati meji irufe be kesi kakiri igboro ilu Nigeria fun itpju pmp pwp tabi pmpde lati le j? ki wpn ma hu EHIN ?nu W9D ppiu irprun laisi wahala rara tabi aikole sun yala losan iwe suu awpn iya wpn gbogbo Ogorun orisirisl egbogi bayi ni wpn npolowo sinu pro gbohungbohun ati sinu iwe kika lojojump sugbpn kosi eyi ta le fl we egbogi Tessd re rara o. Qlpgbpn j i orj gja mu pupp niou awpn ar?
ilu Sato ati awpn ara ilu Agpnyin (CHANA) mp egbog yi dajudaju on na ni won si nip fun awpn prop ti wpn ba sesp bi titi fi di nkpn bi ome pdun wawa gbako. Kosi wahala tabi iypnu inu rirun pka ori inu iwp aiperi osiinu fpkun fpkun ewo, kokoro ara lapalapa ara gbigbona igbp sisu, gburu tabi aik dokun ninu ara sisu, Inu kunkun iro afpfefp ati orijirisi awpn amodi tabi aisan ti o ma nyp awpn Q'mp pwp lenu nisba Ehin HIHU” gbogbo. Tessy dre a ara mu ki ehin enu re pmp rp lagbara gidigidl ati
san a wpn pplu.
Awpn pmp ti wpn nlo egbogi yi ki saba $e ama rara niwpo igba ti wpn ba ti ngbps? dede, ti otutu ko si le ri aye lati duro ni igbaya wpn ti wpn jpuo tiara
ara ti nwpn si nsun gbadun pplu Bere Egbogi Ni §pbu Awpn:—
Waterloo Medicine Stores,
8, Palm Church Street, (Oja Ita Faj!
Lagos. Nigeria.
A DED U N CHEMIST 14 Wakeman Street Yaba
lp o lo w o Oja R g Ko Ti Yege
Nitoripe
O KO Tl POLOWO QJA RE SINU
I R O H I N I M Q L E
T ’ODUNKA FUN GBOGBO YOKUBA
K.QWE IPOLOWO QJA Rp SI ADVERT 1SMENT MANAGER
11U»UI^T 1MVLE
16, Bamgbose Street Phone 21985
THURSDAY DECEMBER 31, <964 1ROHIN IMQfeg Qj q EWE KgRIH (4\
YK IK A WO H E WO
AGUARIUS (Jan 22 - Feb 20) Ire wa fun p loci, ki o si gbajumo lyp rp, ki o Ip ye abpwo awpn ti o nifp re ki o si fi orp wa prp Ipnu wpn, awpo pbi re ati awpn ere re yio ma niff re siwaju.
PISCES (Feb 21 - Mar 20) Maye j p k i irpwpsi pkan mu p loni, ododo ni ohun ti o ntp mp, pugbpn koiti si aye lati si paya nkan na.
ARIES (Mar 21 - April 20) Arp wa lara re mase fi ara silp puppju lyp y ° gbe 9 1? e< irinajo kan, ire si mbe pelu rp loni.
TAURUS (April 21 - May 20) Ki o se irohln aladun kan ti o dara nipa i§e fi o jp eyi o dura fun p.
GfcMINi (May 21 - June 21) Iyp aje rpgba yi p ka ohun ti o si fp bprp ti o jp ti ara re, yio ba ode pade lwp yio gba alejo lati okere, prp i§p kan yio si sylp CANCER (June 22 - July 22) Se jejf, ki o si he
re dipdip tio ba ti mp O le da are bo p, tot.p ti o fi ledija larin iwp ati prp rp kan, igbadun ati a y p y io vvp ile rp loni.
; LEO (July 23-Aug 22) Ijade rp loni yio dafa ni wiwo mtori ire mtp ninu ip Bio ba si lp ra pja loni iwp yio ti ere je pupo ninu rp §ugbpn maps hawp fun pnikan
ViRGO (Aug 23-Sept 23) Mase ba pnikeni gbolonun asp loni mayi ye gbagbe awpn t| iwp pplu rp jp pregbiyan u die tio ba ye yio mu ere Dials w'a
LIBRA (Sept 24 - Oct 23 ) Ori re yio ma gbona la^oko, ohun ti o dara ni wipe ki o mase ba e n i k a o gbonu ninu awpn to sunmp p, eto ti o si fe fi to is?
rp yio ypri si rere.
SCORPIO (Cct 24 - Nov 22) Niti isp yise, o mp daradara, yugbpn o kanoa bie. Tpju ise rp na, jeki iwp pelu prp rp jijp kpsp Ip si ode toni, si awpn oni ba
ba re.
SAGITTARIUS (Not 23 - D ec 21) £lpda rp yio dabo bo p loni, larin iwp ati prp rp, ki o si ma si ye tun da ija silp, foju silp si ise te ki o si ri pe gbogbo re nip leto - leto.
CAPRICORN (Dec 22 - Jan 21) Ri gbangba wipe awpn isp tl o ye ku yanri si rere ki o to wa dawple i s p niirao mase ba alidugbo re ja yugbpn ki o ma fi.ifp ba wpn gbe.
Gbeje Ki O Niyi
Lati Emmanuel oloto-llu Omupo
Gbe je ki o niyi pre mi 5 ri aiye nye loni:
Kio dakun ki o se ara rp je je.
E ni igba si odun fun yen- yen.
Kio jare ki r> fi ara rs siwpn lie aiye ki ise awe ilp ilu Bara.
Qrun nikan ni arpmpbp Qmo ti a bi loni ti o si di Ajike.
B’o se were ad’pni iku npa Ii;nsini opp enia atata Ti aiye nyp ti eda si nfp B’pp? titi nwpn a d’pni iku mu ]o.
Ko si s’ohun ti nwa ti ki nkan Paye.
A fipla Olprun ti oto wa jp Bi un’irinwo eru loni ti oko gbe je.
Bi o si ni Gbingbin-Dikin
orp ti o ko ye pple, B’ oye were nvon a salp bi eiye.
Bi o ni wpn ma yeiGbera- ga Gbe jp ki oni 'iy pre mi Igba agbeje ki ifp kiakia, Awo ogbejp ki ifaja bpry- bprp
§ugbpn ero io fi waduwa- du K o aiye ma ya ti ko gbeje
B’ope tlti a d’pni aiye ntp kiri.
Y p y cl’pou aiye ypyp l’pnu enia:
f ni t’ o nppn p loni ti o yp titi
B‘ o se were a bu p Ida b’eni layin.
Se pgbpgbp iyawo mbp wa d’otuba - ntp,
Gbe jp ki on iyi p r e m aiye n’ipa. aiye nipon.
GBOGBO ARA ILU NKQ ORIN 1YIN AYQ
b i p a
“DYNAMIREN”
t o n i cA LE-BI-ALE Egbogi Vpniki Jamanu titun ti gbogbo ara ilu Eko ati Ja- kejado Naijiria mp daju fan Akp agbara ati Ajp- bidan iyp rp lara Agbala- gba Qkunrin gbogbo.
Bi arp ara ba ninu p, nigbakugba fun wahala la- la yiye ti o ko le jpun daradara, tabi ki o male sun dada pkun lpsan tabi awpn iya n ara rp gbogbo ko ba yiyp daradara ti Eemi Breath) inu rp koba gunlp daradara fun iyp tabi wa
hala yiye tabi fun awpn ailera gbogbo’ tabi ti pjp ori rp (age) ba ti koja pgbpn pduD o si de adprin tabi jube \o. Mp daju pe “D Y - N AM IRBN ni egb ogi ti o nfp Ian sp’ara rp di ptun pa tapata ara rp a si jplp, pran 8ra rp tio ti hunjp yio yi po padu patapata alafia ati gbadun yio de si p Iypn
be.
Bere egbogi na ni $pbu
NIGERIAN MED1CENE STORES 4, Tinubu Square Lagos ATI NI $QBU
OLODUMARE DISPENSARY OKE BQslA IBADAm
Gbanjo ! Gbanjo ! !
Fv N QDUN KERESIMESI A ni lati fi kede fun awpn onibara wa pe Qja g b a rtjo wa bprp lati oni ip titi di 30/11/64. Tete ra tirg ki o to kas? nil?
APEJUWE ILE IT A 1WE WA Wp Bppsi Mushin, spkalp ni Atewplara Bus Stop Bere ladipo Street, ti o ba rin titi Ladipp, bere ILE IWE ODU - ABORR. Ti o ba de ibe tan, wa be re Noinba 5, Alabu Stree Mushin, ile iyp wa dojukpta
ODUS SURF”
AWQN WA
Olubori Egbogi Ajpbidan 40s di 30s Iwe Egbogi Ajp- bidan 25s di 22s Iwe Egbogi Awogba Aruu 20s di 17s Iwe liana Ifa purin dtp ati etu yise 20s di 17 Iwe Afoyp Isedalp Yoruba ati Psalmu Ajpbidan 3/6 di 2s 6d Tura i Ispgun Aje 10s 6d di 8s Turari Itaja 10s di 6d 8s Turari Ala rere 1 Os 6d di 8s lye owo Turari pangolo niti oke yr Turari ti o wa ninu paketi jp 2s 6d pere Iwe Itump Ala Joseph Alala 5s Iwe Aniyan eto Irun o ti di 2s 6d Akpnni lpsin pataki Islam 2s 6d Tailor’s Measurement book dl is 6d
Tenants Agreement Forms 10/6d dl 5/ Gold Smith Forin.s Certficate of Apprenticeship (mpta] 17/6 di 10/6d
QJA TITUN TI A §ESE RI GBA Abfla mimp fun adura tete Idaloju (oryiriyi awpu fuu Turari.
abela mimp fuu itaja (Kowo wole pplu Turari 20/-
„ i, Isogun a e pplu Turari 20 /- Lpfinda tabi Ororo ipara fun itaja, Iypgun Ajp ati arisikl 30/- Igo kan
Fi owo ranyp tabi ki o wa ra ni pdo:—
J. O. Shoyinka 5. Alaba Street
MUSHIN.
THTTRSDAY DECEMBER 31, 1964 IROH1N JMQLB OJO EWE RA RUN (5)
AyO ayoporo ni Akere yo nijosi ti o fi Se Ni Itan
Lati Qw q p § 0 ,
Nigba atijp Oba ilu kao wa ti nwpn i pe ni Ooijin, o ni okiki, » li pla, o si ni dukia lppplppp ko si ogun ti yio lo ti ko ni SPgun ilu na, nitoripe, o ni awpn enia pu- pp Iphin rp. Ilu I$in je ilu nla, o si ni pja nla, ojoju- mp ni awpn alejo nwp inn rp.
Ni pjo kan irohin ka"n wipe Qba Oni§in wp aja.
Awpn agbagba ilu Isin pi- ara wpn jp lati da Ifa wo, tani ki tiwpn fi rppo Oba to ku, Nwpndifa lp, nwpn difa bp, Ifa sp wipe Akere ni ki wpn fi jpba na.
Qmpba kan wa ti o je wipe on ni Abikehin fun Qba Onisin Akere si nl orukp rp nje. H a ! si se gbogbo en ii wipe, Akere ti o je pmp kekere, alagba- ra ati janduku enii ri ki nwpn wa fi je oye oba.
Gbogbo awpn agbagba pa- nupp wipe ayafi bi nwpn ba tun ifa na da,
Nwon ranse lp pe Adifa Koro, Awo Ipptrin ki o wa tun Ifa na da fun wpn Wayi ! ti nwpn tun da ifa, Aketc ni Ifa tun mu, su- gbpn awpn Ijoye ilu ko fe ki Akere jt> Oba le wpn lo - ri, nitori n w p n m p iru itu meje ti Akere n$e lann ilu.
Awon agbagba ilu ko gba ohun ti ifa wi, nwpn se eti gbpnran si pbp, nwpn
sc arpngbp si e§u, nwpn ni bi iwa eni ba baje, owo ara eni li a fi ntun iwa eni ?e, ni gbati Ifa ti mu Akere, ni o ti lo gba ilu gang an spbin ti njo ti o si korin bayi wi-
pe;-
Akere yio j’Onisin Asere yio j’Onisin O b?rp si jo kakiri ilu i'in bio ba io die asi fo si ke lai nigba bib’er? si fo n.iyi wo iwaju re bio lito fyip beni o §ubu sinu koto osi fi itan se
Awpn gbogl o Ijoye ran 5? lope Araba It.t layi owo gbulu gbnlu ku kio wa ye Ifa tire wo fun wpn B i o ti o gbe Ifa t re janle o si yan elomiran ni Oba Onisin bat/i ni akere i ayp ayepprp gba oye Oba kuro Ion ..ra tp ni
tori a ko gbpdp fi’ alabuku ara je oye Qba akere tise ni tan ko le jpba ni Aksre ba kps? sinu igbo loba di kpn kp ti nwpn pe ai Akere
Eyi na li o di owe ti wpn npa wipe ayp ni Akere yp ti o sp ni itan
E t i i l Q C i l
BERE EG BOG f Aworan egb? yi fihan gba dggg gba ibiti jedijpdi rp wa ni ara rp ti nypp Ipnu nigba gbogbo. Ibp ni a n p e ni
“omusu isb i ibo idi enii ibiti a raa ngba ?e igbpnsa Arun Jpdijedi j? pkan ninu amodi ti o buru ni pataki fun' pkunrin tl o si soro pupp lati p e iwosan r p patapata.
Opolopp egbogi ni o wa ti nta kakiri ode nisisiyi an nwpn tna a npoiowo nw un iwosan re sugbpn Inv fa ie i ri me va ninu awpn ogun ti o le se iwosan aru yi laradara, Awpn elomiran gbe Ip si He iwosan lati lp
nmosu kn nip„ he awpn o bp Ipwo rp patpiata Sugb u awa ko ro bp rara lehin pdun dip iypnu re yio si tun bet? bakana Orisirisi Jedijedi ni o wt Ekini ti o b?re nipa aiko ma se igbpse dede tabilojojuma elomiran uipa ijoko ni ojokanna pup? ojojump abi gigun kpke ologere (Bssikulu) pupp elomiran ewp eran §uga nniruru ohun adidun pupp, puppju nigbu kugba Jedijpdi orisirisi ni o wa, ewo ni tire? Bi o nyp sode ninuoi.u$u tebi ti oba nmu eje walphln >gbpnse tabi ti o ba nyp ti o ba se igbpns? tan nl tab! ti nrin p ninu omusu ni eyikeyi ti o ba ic bere egbogi CYCLOVEN ati awpn Oyinbo Jamani $?5? wa idi re k o si daowp kuaju wipe iwp yio bp lpwp jedijpdi pata
pata alafia yio tie bap ekeji re ko si ninu gbogbo awpu n ia tan igooro Naijiria bem ni :
NIGERIAN MEDICINB STORES 4 1 inubu Square Lagos WATER-LOO MEDICINE STORES
8, Palmchurch Street, Lagos i Phone 228/8 Nigeria, (Oja ItaFaj
CYCLOVEN
ero w ip e boya fi wpn re eyiti > bi ri"p jade
Ogun Belubelu Tabi Lere
QNA QFUN — QNA QRUN ' E»su nlanla pi lati fi abe si pfua lati ge Belubelu o ti fi iku pa ppplppp enia nipa bayi ati ' an Ogun Aje- bidan ti ati fi w o Ogunlpgp enia sann i pj .ikan na.
Ko Si Tun Se Oluwnrp M p Lailai, p B £R E LQDQ
Ogbeni Aro - Lambo
43, Koseh Street, Lagos.
A DAYS REMEDY FOR THb C U R E OF
TANS1LITIES
WITHOUT OPERATION
P r ic e I2s 6 d E Ndiiro Fiiia ?
Bi o ba ni asp fun flip «ti lilp bi ( wollen) asp oke, Tapeta Saprti ati orisirisi asp ti o ba ni fun fifp atili/p ni i pju kan
TETE QBE WA SI ODQ
JOYCE L UNDRETTE SEVtCE
34, Ojo — Oniyun Street, Apapa Road Ebute Mi-t’a Kia ni ao ba o fp ti o si ri gba ni ese kanna.
A ,e wa gba ni iie re. k> a si ko pada fun ti a ha fp tan kp nomba tie re ranse si wa.
Dan wa wo lpkansoso ki o si ri bi is? wa ti dara to wo p p tlu ni t si ngba
LATI OJU EWE K.EJI
orile aiye. Bi tyipadu wpn atijp yio ma di kasi, ti yi ba si ti npo si i bp na nwpn yio si ma a jasi asi- ni awpn asa ati awpn owe sp prp.
BERE EGBOGI PATAKI YI TI NWON NPE N I:-
“ A p ia s IS cd iiciu g llr a g e e s :9
Je ojulowo egbegi li avpn Jamani s?5 s e iwadi rp fun awpn ti o ba sacra tabi ti o ba ‘TOBI, ju latima mu ki nwpn le fpn tabi ki wpn fpnku lai s> wipe nwpn ma ka ewp onje ti nwpn yio maa jt rara, best tii ko lewu ni bio I un enia yala pkunrin tabi Obinrin rara.
iG enia $anra, gborin, tabi kio tobi puppju ki nse ohun ti o dara o G lewu pplu ppplppp amodi ni o nko Aya I ilu kiki tabi jija nigbakugba aikole mi kanlp daradara, ara wiwo tabi wiwuwo; Eemi mimi hp-hp ati orisirisi amod omiran pelu
Sa dan igo re kan wo, Iwp na yio ri ayipada ati A la- a ti yio de si o . Bere ni Spbu awpu Olori Eiegbogi Jamani ni Igboro Ilu Eko
WATERLOO STOKES 8, Palm Church Street, Lagos ADEDUN CHEMIST
4, Wakeman Street, Yt;ba
KiKIIE ^ 2
Kurani Ogbpn Esu ti a se Larubawa ati itump ri sitiu Y oruta 25/- Postage l /6d, Iwe Aduru patnk de Aris ki ati is;gun lori ^ hun gbogbo lati ile Mi ra I/O Iwe Atump Ala ati Adura Ala ibanujp a ti nta ni 4 /- o ti din si 2/6d Afpmp isin Moham
med 1/— lodp:—
Tete ra tire
ES KOGBOGUN SERVICE
8 ldumagbo Avenue, L agos Nigeria (Leti Q ji J a i u r i I’ i t u
IROHIN
IMOLE
IM O L E O RE A IT E . TEN1 G BO CBO L A W A NO 884 THURSDAY DECEMBER 31. 1964 (20^
Ogbologbo Olosa Kan Lo Gb?’Wa Odun Kan
EKO:— Ni yjo A ie ti i}e vio tcjidi. !yg Eko til ki ogbologl o Qlysa kan Ycsufu I kara Ip jura fun csun ole jija yi /i awpn Gfgebl cstin li nwon fi kan Qlcsa na ni awyn Qlppa fi yc Adajp pc Qkun- rm na si jf Ogbologbo Qlpsa alt pe o li d ip g a n ln u Ole jija eyi ti awpn Qlppa tun $e alaye pc awpn pro ti Q kya ra jt gbe pc ipc oworp je ponun mptala sile mptnla (£13: 13/-) dgbejpro fun tic cjp na fi ye Adajp pc Qlpsa na lo ji pru na gbe ni adugbo kan ti a npe ni Jone
bpn o$u yi ni AdQjQ i/e cjp kckere I/u egb« Iq fi ?wqoQ Jun kanpf/ui?? alasc-
Qi^pa fi kan Qkunrin odar*n ne.
Street ni Ebute M ^tta ninu osu keje Qdun yl.
Ninu idajp A d a j o na ni o tisc alaye pe gbogbo oro ti Agbcjoro fun He na so lo j? otito ati pe edaran na wa si iwaju on lati wa pa iro. Ooi ki Qlo§a na lo fi ewon odun kan lo juro lo- ri ?sun na ati pe o j$bi ^?sun na.
Edeaiyede Bpsile Larin Aw on
Akowe Alamojuto Eto Ibo
EKO:- Awpn enia fere ti pwp gun ara wpn torn nigbati nwon ber? si se ipade kan lati jiroro lori iyipada ati sisun pip idibo ti nwon fe se ni ana siwaiu nigbati awpn ema meji kan dide d> ro ninu ipade ti nwpn si ft aake kpri wi
pe, o ye ki nwon le ye pip idibo yi siwaju.
Ninu ipade na, Ogbe i David Akerzua, ti ise Aso- ju Ijpba lpinle Agbcdemeji ati Ogbem Anthony Ariia- golu, ti ise A§oiu Ijyba Ipiol? Ila t_>run Naijiria se alaye wipe, awpn ko fara mp p wipeki nwpn dibo na ni ana.
Awpn enia na $e alaye wipe, ni ppplppp ngbegbe ni awpn ti j»bp irohin wipe madaru wa tiinu eto ti awpn akpwe alum juto ibo nse.
NwpnjB"' sp siwaju si i pe, awytt Asoju miran ko ri iwe gna, ti o fi ye w pe, Eko ni nwpn ti wa gba t«e wipn beni awpn akpwe wa ninu i'.u na ti owpii sapa- mp nitoripe. nwpn (|o I'ara- mp egbe Oselu wpn.
Awpn enia na tun sp si
waju ninu ipade na w pe ni
gbati awpn gby irohin na pgbeoi Eyp Esua, ti is? Ala ga Jgbirnp Ibo funrare sare
$e ibewo yika orile ede v i on paapa si fi oju era re ri gbogbo prpoa.
Lehm ti o de lati ir najp rp p se ikede wipe nitootp ni ma daru wa ninu awpn egb?
o$eIu ti akosn Ijyba wa ly- wq wpn ko gba awyn omp pgbe Alatako laye rara.
Awpn enia na wa se alaye niau ipade na wipj ni tootp ni roadarn, ati aisedtede wa ninn eto idibo t: nwpn le §e o ye ki awpn tuo gboebo olntn li ko ba dara sc ki abo gb ■ re le o si gunlegelege-ki awpn enia to le ni anfani lati dibo Ipna ety Ipna wpprpwp.
Awpn enia na tun se ala
ye wipe ki if? jspkan ifpkan
bale ati irepp o le ba ws ba- rin’ghogb ' awpn enia N ai- j r a o ye ki Ijpba le y? ojp idibo yi siwaju.
Sugbnn nigbati awpn enia meieji na ti spry t a n t i nwpn si se alaye wpn gbo- gbp sile bayi tan awyn enia meji miran ninu wpn sp wi
pe, awyn lodi si aba tiawyn enia na da.
Enikan tun dide n i n u awpn enia na ti o sp wipe on faramp imorau ti awpn meji ti nwpn kp spry niaky ky wipe ki nwpn sun piu idibo yi si pjp iwaju nitori irepe rti ispkan on ajpscpp gbogbo enia orile-ede yi.
Enia meta lo faramp wipe ki nwpn ye pjp idibo yi si 1 pjp iwaju enia maji ko fara
mp impran na.
Ni ipari ipade na awon enia meta na sp w i p e,
“ Enia meta lo faramp wipe nwpn ko faramp lati dibo yi, lehiuti a ti rp gbogbo ui$e deede ti o wa nidi prp na wo daada, ti A I a g a Igbimp lp si irinajo yika Orile ede yi li on na si fi oju aiare ri gbogbo re.
“Lehinti a ro gbogbo nkan wpoyi ti a si my rrii titobi ise wa ninu prp ti o dele yi, a lero pe ki yio d^ra bi awpn eni i ba dibo yi, sugbpn ti e ko ba gba impran lori gbogbo alaye ti a ti se sde wpnyi.
‘Eyi ti o si da iva silp la- rin gi ogbo awa akpwe ala
mojuto eto ibo, a if lati fi ifepk.au wa kan gbogbo enia wipe, a binu ii aye i?e wa sile, a ko $e ise akpwe alamojuto ifio na mp’’
Oni ve Irohin wa Ejon-
gboro ti o Ip sibi ipade na se alaye pe Ogbeni F.yp Esua, Alaga gbimp na ko raye lati sprp lori prp na titi ile ft $u ni ana.
tOnirobm wa ni Ibioni fi ye wa pe gbogbo awpn akpwe Alamojuto eto Ibo yoku Ipinl? Agbedemeji nl L A II OJU EWE KINI wp, awpn ti ko si ri p w p Takisi wy Bpiekaja.
Gbogbo ilu Eko lo d a paroparo lana ti gbogbo ilu.
si da wai bi yni pe ko s' enia lario ilu mp.
Akbprpsp awyn akpwe e ;o idibo kan sp fnn On,we Irohin wa Ejotigboro ni Ikoyi lana wipe awpn ko ni
$ise lana.
;‘§e Qga Spja ati Qlppa ni Balewa ba spry, ko ba wa spry, ki Qga awpn §p- ja ati Qlppa.ma a lp $p He idibo, ?nitt nwpn ba ri ni be ti . wpn o sp?
Nigbati awpn enia na de ibi i$e Una nwpn so pe ki gbogbo wpn o ma a lp sile awyn yio maa kywe si wpn Ipjp aipe
Irohin fi ye wa wipe gbo gbo ile idibo ti nwpn ko si Eko ni awpn kan ti lp baj?
ti nwpn si wo luly ti ko wulo mp.
Bakanna ni Onirohin wa
nwpn ko sisy yika gbogbo Ipinlp na iar.a.
liakanna ?we ni gbogbo awp i akowe eto idibo ijika gbogbo lpinle Ila Jtun Nai jiria ko ?i$e awpn enia na paapa ko jade nile lati w a dibo.
ni gnugun fi ye wa ni ana wipe ppylppp awyn ilc idi
bo ni awpn krn Ip dana son ti gbogbo r? si jona
tan raurau!
Bi awpn eoia na tilp fe dibo ni ana, ko si ibiti nwpn yio ti dibo. Awpn akpwe ti yio gbe apoti idi
bo p si ibiti nwpn yio gbe dibp ko gbeapoti Ip, awpn ti yio Ip si lhkun ko lp.
Awpn pi plppa ati §pj i lo kakiri Qligbo igboro ilu Eko lanagbrgbyu ohun ija kan ko eel? li i iip fi su lana
Awpn osise pkp < jo irin Reluwe da is? sil? lana, gbogbo wpn lo lp si ibi is?, pugbpn nwpn ko fi pwp kan is? se.
A gbp wipe nwon dibo ni awpn agbegbe kan ni lpinle Iwo Orun ati Oke-Qya la- na atigbcn awpn enia ko ri iwe idibo lo nibo miran.
Bi abaypri eto ibo yi b a ti j? lo tun ma a gbp p.
BERE EGBOG1 OJU TI WON NPE NI:—
63 I U I I I W ( O J U BABA ARA )
Fun itpju “ OJU D D U N ” ni pataki bi oju enia ba nsu nigbakugba, ti o ba wa ipin jade ti o ba ppn bi e$e ina, ti o ba ngun ^nia bi ?nipe iyprisi wa n nu r?, tabi bi enia wa le riran dariidara to bi enia ba wa ni pna jinjin tabi lokere rere, §a dan egbogi awpn ara ilu Am?rika yi wo iwp na yio wa rohin r? titi gbogbo eoia. Bere r? ni ?ybu awpn:—
Waterloo Medicine Stores,
8, Palm Church Street, (Qja Ita Faji Lagos, Nigeria.
Pnmed A m i I'u fished by M 'dtip? Printing Press, 16. Bamgbosc Street Lagos Phone 211)85”
Editor. J UNJi ADEOSu n 45, Campbell Street Lagos (31/12/64^